Idì
![]() |
Ojúewé yìí ti jẹ́ dídárúkọ fún ìparẹ́ kíákíá. The reason given is "No useful content". If you disagree with its speedy deletion, please explain why on its talk page. If this page obviously does not meet the criteria for speedy deletion, or you intend to fix it, please remove this notice, but do not remove this notice from a page that you have created yourself. Administrators, remember to check if anything links here and the page history (last edit) before deletion. |
Kini àwọn idí?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Idì (eagle), won le fo ninu orun. Won je ọdẹ dara. Àwon idi nigba gbogbo eranko won pamo ni iji lile, awon idì, won ma tesiwaju lati fo, ati fo ga. Inu won ko beru lati kankan! Àwon idì, je eranko dara gidigan, won je àwò igi ati won le je orisirisi àwò.
Áwon idì je ẹyẹ nla, won ni emu ti o tobi gan, won wa lati ebi ti "Accipitridae". Àwọn idì jo àwọn gúnugú nigba won fo ni orun ati ni ara pèlú..[1] Won ni ìyé ti o po lori ori re ati won ni ẹsẹ pèlú agbara pupo ati èkánná.
Àwọn idi le je láàyè fun asikò ti o ju o po ninu àwọn ẹyẹ. Won le je láàyè fun odun àádọrin (70).[2]
Kini iyara ti idi?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awon idi le fo pelu iyara ti igba kilomita ni wakati okan (200 km/w) o je kiakia gidigan, kiakia ju amotekun.[3]
Igbesi ayé titun ti idì!
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lati dàgbà si odun yii, odun aadorin, idi o nilo lati se ipinnu ti o soro gidigan. Nigba o ni odun ogoji, won ko le lo ekanna ti ode won lati gba ati gbe ohun odẹ ti o je ounje fun won. Enu re ti o gun ati ti o je mimú o ma di itẹ. O ma di darugbo ati o ma ni iye apá ti o ma di wuwo nitori pé ìyé re won ma di nipọn ati won ma nilo lati se iye apa re lati lemó si aya (aiya) re, ati o ma soro lati fo ni orun. Idi, o ni nkan ipinnu meji, lati fi ku tabi lati tesiwaju ninu irora ti yipada ti o ma duro fun ojo àádójo. Nitori náà, idí, o nilo lati fo si òkè ati jókòó ninu itẹ re. Nibẹ, idi o ma lu enu re lodi si apata lati enu re o ma yo kuró. Léyin náà, idì, o ma dúró, fun enu re, nitori pé, enu re o ma dàgbà, léyin náà o ma fà-yo ati fà-tu ekanna ti odẹ. Nigba àwọn ekanna ti odẹ re, won dagba, idi o ma fà-yo àwọn ìyé re ti o je darugbo. Nigba ti odun ọgbọn ti pari, idì o ma ni ìyè ati igbesi ayé ti o titun patapata! Idì yii o ma fo lẹẹkansi, o ma fo ni asikò keji ni orun dabi tele tele ati o ma je láàyè fun odun ọgbọn ti o poju! [2][4][5][6]
Orisirisi Idì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]idì apari, idì wura, idì dudu, idì ade, idi òkun, idì iru funfun
- ↑ https://www.britannica.com/animal/eagle-bird
- ↑ 2.0 2.1 https://www.suecoletta.com/secret-life-of-eagles/
- ↑ https://dinoanimals.com/animals/the-fastest-birds-in-the-world-top-10/
- ↑ https://archive.org/details/DictionaryOfTheYorubaLanguage/page/n59/mode/2up?view=theater
- ↑ https://languagedrops.com/word/en/english/yoruba/translate/chest/
- ↑ https://www.bible.com/search/bible?query=nitori%20naa