Jump to content

Iffat Miraj Awan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Iffat Miraj Awan
Member of the Provincial Assembly of the Punjab
In office
29 May 2013 – 31 May 2018
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí15 Oṣù Kẹ̀wá 1971 (1971-10-15) (ọmọ ọdún 54)
Jaranwala
Ọmọorílẹ̀-èdèPakistani
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPakistan Muslim League (N)

Iffat Miraj Awan (tí wọn bí ní ọjọ́ kẹdogun Oṣu Kẹwàá Ọdún 1971) jẹ́ olósèlú ará ìlú Pakistan kan tí o ti jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ti Apejọ Agbegbe ti Punjab, láti oṣù kàrún ọdún 2013 sí oṣù kàrún ọdún 2018.

Ìbẹ̀rẹ̀ Ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Iffat ní a bí ní ọjọ́ kẹdogun Oṣu Kẹwàá Ọdún 1971 ní Jaranwala . [1]

O parí ile-ẹkọ gíga ti Punjab ni ọdún 1995 o sì ní ìwé ẹ̀rí ìyẹ̀wù àkọ́kọ́ ti áatì.

Wọn dibò yán sí Apejọ Agbegbe ti Punjab gẹ́gẹ́bí olùdíje ti Ajumọṣe Musulumi Pakistan (N) (PML-N) láti agbègbè PP-53 (Faisalabad-III) ní idibo gbogbogbò Pakistani ọdún 2013 . [2] [3] [4] O rí àwọn ibo 44,754 o si ṣẹgun Malik Zafar Iqbal Khokhar, olùdíje ti Pakistan Tehreek-e-Insaf (PTI). [5]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]