Jump to content

Igho Otegheri

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Page Module:Infobox/styles.css has no content. 

Igho Otegheri
Ighoteguonor Otegheri of Wikki Tourists.jpg
Ighoteguonor Otegheri, 2010
Personal information
OrúkọIghoteguonor Otegheri
Ọjọ́ ìbí20 Oṣù Kọkànlá 1983 (1983-11-20) (ọmọ ọdún 42)
Ibi ọjọ́ibíCalabar, Nigeria
Ìga1.83 m (6 ft 0 in)
Playing positionStriker
Club information
Current clubHeartland F.C.
Number13
Senior career*
YearsTeamApps†(Gls)†
2003Wikki Tourists33(16)
2004–2006Enugu Rangers61(26)
2007Dolphins F.C.33(16)
2008–Heartland F.C.32(14)
National team
2002–2004Nigeria3(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Igho Otegheri (tí a bí ní ọjọ́ ogún oṣù kọkànlá ọdún 1983 ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà. Ó gbá bọ́ọ̀lù fún Heartland FC.

Otegheri bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú Wikki Tourists ní ọdún 2004 kí ó tó di pé ó lọ sí Enugu Rangers fún ọdún méjì. Lẹ́yìn náà ó fọwọ́ sí ìwé àdéhùn pẹ̀lú Dolphins F.C. ní ọdún 2007.[

Lẹ́yìn náà, Otegheri dara pọ̀ mọ́ Heartland F.C.,[1] níbi tí ó ti gbá bọ́ọ̀lù títí di ọjọ́ kejìlélógún oṣù kìíní ọdún 2009 nígbà tí ó kó lọ sí Beitar Jerusalem F.C.[2] pẹ̀lú ọmọ orílẹ̀-èdè rẹ̀ Anderson West.[3]Wọ́n tú u sílẹ̀ kúrò nínú àdéhùn rẹ̀ ní ọjọ́ kìíní oṣù kejì ọdún 2009, ó sì padà sí Heartland F.C.[4]

Otegheri jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Super Eagles,[5] àkọ́kọ́ rẹ̀ wáyé ní ọjọ́ kejì oṣù kejì ọdún 2003 nínú ìdíje kan tí wọ́n ṣe pẹ̀lú Costa Rica[6]

Ìgbésí ayé ara ẹni

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó fẹ́ agbábọ́ọ̀lù orí pápá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Blessing Okagbare, ní oṣù kẹsàn-án ọdún 2014.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Page Àdàkọ:Reflist/styles.css has no content.