Jump to content

Ime Akpan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ime Akpan
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí27 April 1972

Ime Akpan Ig-Ime Akpan.ogg listen (Tí wón bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹrin ọdún 1972) jẹ́ eléré ìdárayá orí pápá ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ẹni tí ó kópa nínú ìdíje alásùré fòsá ti 100 mítà fún àwọn obìnrin nígbà tí ó sì fi ń sáré Ó jẹ́ asáré orí páápá Olympic lẹ́ẹ̀kan ni Ọdún (1996), ó sì gba ẹ̀bùn wúrà ní 1991 All-Africa Games ní Cairo, Egypt .

Akpan jẹ́ ọ̀kan lára àwọn asáré orí pápá Asúre fòsá fún ẹgbẹ́ Arizona State Sun Devils, ó sì gba ipò kejì nínú ìdíje 100 mítà níbi ìdíje NCAA Division I Outdoor Track and Field Championships ti ọdún 1993. Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà fún ẹgbẹ́ eré ìdárayá Utah State Aggies, tí ó sì parí ní ipò kẹrin nínú ìdíje alásùré fòsá òní mítà 55 níbi ìdíje NCAA Division I Indoor Track and Field Championships ti ọdún 1990.

Àkọsílẹ̀ Eré ìdíje

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Sójú fún Nàìjíríà Nàìjíríà
1991 Universiade Sheffield, United Kingdom 8th 100 m hurdles 13.74
All-Africa Games Cairo, Egypt 1st 100 m hurdles 13.44
1992 African Championships Belle Vue Maurel, Mauritius 1st 100 m hurdles 13.14
World Cup Havana, Cuba 6th 100 m hurdles 13.57[1]
1993 Universiade Buffalo, United States – 100 m hurdles DQ
1995 Universiade Fukuoka, Japan 4th 100 m hurdles 13.11
All-Africa Games Harare, Zimbabwe 3rd 100 m hurdles 13.09
1996 Olympic Games Atlanta, United States 26th (q) 100 m hurdles 13.11
  1. ↑ Representing Africa