Indira Gandhi
Ìrísí
Indira Priyadarshini Gandhi (Híndì: इंदिरा प्रियदर्शिनी गांधी Indirā Priyadarśinī Gāndhī listen (ìrànwọ́·ìkéde); 19 November 1917 – 31 October 1984) je oloselu ara India to je ipo bi Alakoso Agba ile India fun igba meta lera won (1966–77) ati igba ekerin (1980–84).
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |