Jump to content

Internet

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Íńtánẹ́ẹ̀tì jẹ́ asopọ̀ bí ìtakùn àwọn ẹ̀rọ kọ̀m̀pútà káàkiri àgbáyé fún ìpàṣípààrọ̀ ìpolongo àti ìmọ̀. Ní èdè Gẹ̀ẹ́sì ó wá láti orúkọ inter - network, nítorí náà ní èdè Yorùbá à ń pè ní Íńtánẹ́ẹ̀tì.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]