Iris Apatow
Iris Apatow | |
---|---|
Apatow in 2018 | |
Ọjọ́ìbí | 12 Oṣù Kẹ̀wá 2002 |
Iṣẹ́ | Òṣèré |
Ìgbà iṣẹ́ | 2007–present |
Parent(s) | Leslie Mann Judd Apatow |
Àwọn olùbátan | Maude Apatow (sister) |
Iris Apatow ( /ˈæpətaʊ/; tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹwàá ọdún 2002 jẹ́ òṣèrébìrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ó di ìlú-mòọ́ká fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí èdá ìtàn "Arya" nínú eré onípele tí wọ́n ń ṣàfihàn rẹ̀.lórí ìkanì Netflix tí akòrí rẹ̀ ń jẹ́ Love, òun náà ló tún kópa ẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn "Charlotte" nínú eré Knocked Up ati This Is 40.
Ìgba èwe rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Apatow ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹwàá ọdún 2992,[1][2] Apatow tí ó jẹ́ ọmọ gbajú-gbajà òṣèré Judd Apatow, tí ìyá rẹ̀ Leslie Mann náà sì jẹ́ òṣèré pẹ̀lú. Ẹ̀gbọ́n rẹ̀ niMaude Apatow.[3] Her father's family is Jewish. Her maternal great-grandmother was of Finnish ancestry.[4]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó di ìlú-mòọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bí "Charlotte" nínú eré apanilẹ́rìín Knocked Up, eré tí babá rẹ̀ Judd Apatow darí rẹ̀.[5] Ó tún kópa nínú eré This Is 40. Lára àwọn eré onípele orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán tí ó ti kòpa bí "Arya" ni Love.[6][7]
Àwọn àsàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́lé | Ipa tí ó kó | Note |
---|---|---|---|
2007 | Knocked Up | Charlotte | |
2009 | Funny People | Ingrid | |
2012 | This Is 40 | Charlotte | |
2016–2018 | Love | Arya Hopkins | Recurring role |
2016 | Sausage Party | Berry Good Candies / Grape #3 / Coconut milk | Voice role |
Fọ́rán orin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Akọ́lé | Olórin | Ref. |
---|---|---|---|
2017 | "Sonora" | Spendtime Palace | [8] |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Apatow, Iris (October 12, 2018). "This is 16". Iris Apatow verified Instagram account. Retrieved January 7, 2019.
- ↑ Cardoza, Riley (August 2, 2019). "Leslie Mann’s Daughter Iris, 16, Claps Back After Mom Critiques Her Makeup on Instagram: 'A Text Would Have Been Nice'". Us Weekly. Archived from the original on November 2, 2019. https://web.archive.org/web/20191102223030/https://www.usmagazine.com/celebrity-moms/news/leslie-manns-daughter-iris-claps-back-after-mom-critiques-makeup/. Retrieved November 24, 2020. "Mann and Apatow, 51 ... welcomed Maude and Iris in 1997 and 2002, respectively."
- ↑ LaPorte, Nicole (2012-08-24). "She's 14, Going on 140 Characters". The New York Times. https://www.nytimes.com/2012/08/26/fashion/maude-apatow-is-growing-up-writing.html?pagewanted=all&_r=0. Retrieved 2019-02-07.
- ↑ "Cameron Diazin tähdittämässä komediassa aitoa suomalaista sisua – videohaastattelu". Yle Uutiset (in Èdè Finisi). Retrieved 2019-09-04.
- ↑ Zakarin, Jordan (2012-11-20). "Judd Apatow on Casting His Daughters and Their Dramatic Onscreen Arguments". The Hollywood Reporter. https://www.hollywoodreporter.com/live-feed/judd-apatow-casting-daughters-maude-393408.
- ↑ Narasaki, Rosie (2016-02-19). "Is Aria from 'Love' Based on a Real Person? Iris Apatow's Child Star Steals the Whole Show". Bustle. http://www.bustle.com/articles/142780-is-aria-from-love-based-on-a-real-person-iris-apatows-child-star-steals-the-whole.
- ↑ Fienberg, Daniel (2016-02-14). "'Love': TV Review". The Hollywood Reporter. https://www.hollywoodreporter.com/review/love-tv-review-864870.
- ↑ Eckardt, Stephanie (2017-07-18). "Stranger Things' Finn Wolfhard Directed a Music Video Starring Himself and Iris Apatow". W. https://www.wmagazine.com/story/finn-wolfhard-iris-apatow-music-video.
Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- CS1 Èdè Finisi-language sources (fi)
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókí tó jẹ́ àfikún PearBOT 5
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 2002
- 21st-century American actresses
- Actresses from California
- Actresses of Finnish descent
- American child actresses
- American film actresses
- American people of Finnish descent
- American people of Jewish descent
- American television actresses
- Film child actresses
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Place of birth missing (living people)
- Television child actresses