Isa Dongoyaro
Ìrísí
Isa Dongoyaro je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà to je asoju ìjọba apapọ fun àgbègbè Babura / Garki ni ipinle Jigawa ni ile igbimo asofin agba kẹwàá. O ku ni Oṣu Karun ọjọ 10, Ọdun 2024 ni ọmọ ọdun 46. [1] [2] [3]