Jump to content

Isinku

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Isinku je eto ti ebi ati ara oku maa n se lati sin oku si inu ile pelu awon ohun eso ti o feran. Won le gbe oku yii sinu posi ki won to gbe wo ile.[1]

  1. Howarth, G.; Leaman, O. (2003). Encyclopedia of Death and Dying. Routledge Modern and Contemporary Dramatists. Taylor & Francis. p. 66. ISBN 978-1-136-91360-0. https://books.google.com.ng/books?id=5GK2AgAAQBAJ&pg=PA66. Retrieved 2024-12-11.