Jump to content

Jíìnsì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwọn jíìnsì méjì
Àwòrán aṣọ tí ó ti kóbó tàbí Sá

Jìínsì jẹ́ irú ẹ̀yà sòkòtò tí a fi aṣọ denim tàbí dungaree ṣe. Lọ́pọ̀ ìgbà, ọ̀rọ̀ náà "jínsì" tọ́ka sí irú ẹ̀yà ṣòkòtò kan pàtó, tí a ń pè ní "jínsì aláwọ̀ búlúù", pẹ̀lú àfikún àwọn àpò òní rivets tí Jacob W. Davis fi kún un ní ọdún 1871 [1] tí Davis àti Levi Strauss sì fún gba ìwé àṣẹ ìjònlónté lórí rẹ ni oṣù karùn-ún, ọdún 1873. Kí a tó fún wọn ní ìwé àṣẹ, ọ̀rọ̀ "jínsì aláwọ̀ búlúù" ti wà fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ aṣọ iṣẹ́ (pẹ̀lú sòkòtò, aṣọ ìbora, àti àwọn aṣọ iṣẹ́), tí a fi aṣọ denim aláwọ̀ búlúù wúwo ṣe.

Ní Ìpilẹ̀ṣẹ̀, a ṣe àwọn sókòtò wọ̀nyí gẹ́gẹ́ bí aṣọ fún àwọn òṣìṣẹ́ ọwọ́ bí àwọn awakùsà tí wọ́n si fi rivets kún etí enu àpò wọn ní àwọn agbègbè Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà kí ó bá fi lè ní agbára sí. Àwọn sókòtò onígun mẹ́rin òde òní wọ̀nyí ni Marlon Brando àti James Dean so di gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí aṣọ ìbílẹ̀ nínú àwọn fíìmù wọn ti ọdún 1950, pàápàá jùlọ The Wild One àti Rebel Without a Cause, [2] èyí tí ó mú kí aṣọ náà di àmì ìṣọ̀tẹ̀ láàárín àwọn ọ̀dọ́langba, pàápàá jùlọ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ oníṣọ̀nà greaser . Láti ọdún 1960 lọ, àwọn aṣọ jìínsì di ohun tó wọ́pọ̀ láàrín onírúurú àwọn ọ̀dọ́ àti àwọn ọ̀dọ́mọdé gbogbogbòò. Lóde òní, wọ́n jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà sòkòtò tó gbajúmọ̀ jùlọ ní àṣà àwọn èyàn ìwọ̀ oòrùn . Àwọn orúkọ ìtajà tí wọ́n ní ìtàn lẹ́yìn ní Levi's, Lee, àti Wrangler.

A traditional women's Genoese dress in "blue jeans" (1890s). Palazzo Spinola di Pellicceria, Genoa, Italy.

Àwọn aṣọ owú tí wọ́n rẹ ni aró Èlu Indigo dyed ní won ń tí n pèlò tí wọ́n ń sì ń tàá ní ilé India fún bí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọdún sẹ́yìn, kí ó tó di wípé ni ìrépé aṣọ owú Aláró èlu wá di mimo sì àgbáyé ní nkan bi, Ọ̀rùndún kejìdínlógún (18th century) gẹgẹbi ‘blue goods’ ni èdè Gèésì, tàbí ‘guinée’ ni èdè Faransé, tí ó sì jẹ́ ọ̀kan gbòógì lára àwọn nkan ọjà tí òun gba orí omi Indian, àti ara ǹkan títà nínú ọkọ̀ ojú omi tí òun kò àwọn ẹrú kọjá lórí omi Atlantic.[3][4] Òpò àwọn aṣọ olómi èlu (indigo) tí wọ́n n tá, ní o wa lati ibi oko ọ̀gbìn indigo ni India, kí ó tó di wípé ni wọn bèrè sí mi ṣe àtowodá àwò aró èlu ní orílẹ̀ èdè Germany ni Ọdún 1878.[5]

Àwọn ìwádìí ìjìnlè tí wọ́n ṣe lórí rírà àti títa Ìrépé Aṣọ Jìínsì òun ló fi hàn wípé ni agbègbè ìlú Genoa,ni ọrílé-èdè Italy, ní ǹkan bí ọ̀rúndún érìndínlógún (16th century) óun ni ó ti jeyo, tí Nîmes, ni ọrílé-èdè faransé sì tẹ́lẹ̀, ní ọ̀rúndún kẹtàdínlógún (17th century). Ìrépé Aṣọ jìínsì tí ìlú Genoa òun ni ó jẹ́ Ìrépé Aṣọ fustian tí wọ́n ṣe àpèjúwe bí "medium quality and of reasonable cost", aso tí ọwọ́ rẹ kò gúnpá tí ó sì nípon ni ìwọ̀nba Pẹ̀lú àfijo aṣọ Olówu corduroy lèyí ti o jẹ ki ìlú Genoa ni orúkọ ni Àgbáyé, gẹgẹbi ask na ṣe jẹ́ èyí tí wọ́n lè wò fi ṣe iṣẹ́ gbọgbọ. Ọmọ ogun orí omi Genoese navy pèsè aso òun na fún àwọn awakọ̀ ojú omi wọn, gẹgẹbi wọn ṣe nílò aso tí ó ṣe wọ bóyá ó tutù tàbí ó wà ní gbígbé. Gênes, orúkọ Genoa ni èdè Faransé, òun ni ó jẹ́ ipilese orúkọ jìínsì òun.jeans".[6] Ní Nîmes, àwọn ahunṣọ won gbìyànjú láti ṣe èèdà Ìrépé Aṣọ jìínsì na sugbon dípò kí wọ́n ṣe èèdà rẹ gélé bí ó ti ri, wọn ṣe àwárí Ìrépé aso òmíràn tí ó fi ara pé tí ó jẹ́ twill tí a mọ̀ sí 'denim' , "de Nîmes", ìtumò rẹ jẹ "láti Nîmes".[7][8] Aṣọ "denim" láti Nîmes's ṣe Súkúṣúkú, tí wọ́n sì káàkun aṣọ tí ó dára jùlọ tí wọ́n sì ń lọ fún ìpèsè àwọn aṣọ bí "Smock tàbí overalls".[9](p23) Ní ọdún 1576, ìdiwọ̀n aṣọ jìínsì Fustian "jean fustians" de si pápákò ojú ọmi Barnstaple Lori ọkọ̀ ojú omi kan láti from Bristol.[10]

Copper rivets for reinforcing pockets are a characteristic feature of blue jeans.

Ní bi àwọn ọ̀rúndún kẹtàdínlógún (17th century) , Ìrépé Aṣọ jìínsì tí di pàtàkì nínú aṣọ tí àwọn òṣìṣẹ́ àríwá ilé Italy ń wò. Èyí je àfihàn Ninu òpó àwọn àwòrán tí wọ́n yà ni àwọn ọ̀rúndún kẹtàdínlógún (17th century) tí wọ́n tọ́ka sí ayàwòrán kan tí ìnagije rẹ ni ayé òde òní ń sì ń jẹ Ògá Aṣọ jìínsì alaro búlù "the Master of the Blue Jeans" .[9](p10) Àwọn àwòrán mewa òun ni ó ṣe àfihàn àwọn àìní pẹ̀lú bi àwọn òṣìṣẹ́ ṣe wọ Ìrépé aṣọ tí ó dà bí "denim". Lai si tàbí ṣùgbọ́n, aṣọ òun ni yio je jìínsì ti orílẹ̀ èdè Genoese, tí ọwọ́ rẹ kò gúnpá púpò. Ìyàwórán Genre painting óun lọ di mímò ni àkókò igbẹyin ọ̀rúndún kẹrìndínlógún (16th century) , tí àwọn ènìyàn tí wọ́n ó ní ìbátan pẹ̀lú ọlá nínú àwọn àwòrán na si gbé wọn sì ìfègbé-kègbé pẹ̀lú àwọn àwòrán yókù tí àwọn na ṣe àfihàn irú àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ bé .[11]

Dungaree, tí ń ṣe irúfé aṣọ kan ní wón dárúkọ ni igba àkókò ọdun 1613,[12] pẹ̀lú bi wọn ṣe tokasi gẹ́gẹ́bi aso Calico ti ó yí Pẹ̀lú Súkúṣúkú lọ́wọ́ tí ó sì ń sábà má ń wá ní àwo búlù tàbí funfun tí ó ti sáwé tí àwọn òṣìṣẹ́ tí wọ́n ó rí ọwọ́ horí sábà má ń wo ni agbegbe Bombay, ni abúlé Dongri ní èèbá ilé odò kan ní ilè India. Aso yí ni wọn pé ní "dungri" ni èdè Hindi. Wọ́n kò Dungri lọ sí ilé England tí wọ́n ń sìn lò wọ́n láti pèsè àwon aso ìṣiṣẹ́ tí kò wón púpò bí àwọn àwòtélè (overalls) . Ní èdè Gèésì, wọn pé "dungri" ní "dungaree".[13] Àwọn oníṣẹ́ eto amáyéderùn oníṣẹ́ ogun ọri omi tí ilé US lọ àwọn aṣọ dungaree na gba ìgbà ògùn àgbáyé àkókó.[13] denim,òun ni ó gba ipò aṣọ dungaree, Ìrépé aso tí wọ́n so lórúko látàrí àwọn èyàn Nîmes, tí ó di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí Jacob W. Davis bèrè sí mi ṣe jáde.

Ìṣó-Pẹlẹbẹ (Rivets)

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Jacob Davis
Levi Strauss

Èdè àpèjúwe jeans jeyo ni ìgbà àkọ́kọ́ ní ọdún 1795, ní ìgbà tí òṣìṣẹ́ ilé ìfowopamó Swiss kan tí orúkọ rẹ ń jẹ Jean-Gabriel Eynard áti bùròdá rẹ Jacques Jo lo sí Genoa tí àwọn méjèèjì sì bẹ̀rẹ̀ si ni darí ìṣe òwò tí ó múyán. Ní ọdún 1800, àwọn ológun ilé Massena wo inú ìlú Genoa, tí wọ́n sì fi wọn lé ọwọ́ Jean-Gabriel láti ṣe ìtọ́jú ọjà fún wọn. Ní pàtó, aṣọ ẹgbẹ́ tí wọ́n dá látara aso búlù kan tí wọ́n ń pè ní "bleu de Genes" lèyí ti wọn padà yọ òun ti wọn pé ní "blue jeans" káríayé ní òní.[14]

Levi Strauss, gẹgẹbi ọ̀dọ́langba ọkùnrin ní ọdún 1851, ó kúrò ní Germany losi New York láti darapọ̀ mọ́ Ẹ̀gbọ́n rẹ ọkùnrin tí ó ń ṣe òwò ọjà títà. Ní ọdún 1853, ó kó lọ sí San Francisco láti lo ṣí ilé ìtajà tí ara rẹ. Jacob Davis jẹ́ aránso ti o sábà má ń rà òpò aṣọ láti ilé ìtajà Levi Strauss & Co. wholesale house. Ní ọdún 1872, Davis kò ìwé sì Strauss pẹ̀lú ìbẹ̀rẹ̀ láti jẹ ki wọn jọ da ọkọ òwò papò láti gba iwe òntè lórí títa àwọn aṣọ rírán tí wọ́n fi irin èsó, àti ìdáàbòbò rivets rán.[15] Àwọn ìrìn ìdáàbòbò (copper rivets) òun ni ó jẹ́ láti dáàbò bo àwọn àpò ṣòkòtò àti àwọn ìpele tí ó lè tètè ya lára ewu, bí ìsàlẹ̀ ṣòkòtò, ẹnu àpò, abé ẹnu ìpèlé bótìnì. Strauss gba ìmọ̀ràn Davis's wọlé ,[16] lẹ́yìn na ni àwọn méjèèjì gba iwe òntè ilé US patent Pẹ̀lú nọ́mbà ìdánimọ̀ No. 139,121 fun mímú ìtẹ̀síwájú de ba ẹnu àpò ṣòkòtò "Improvement in Fastening Pocket-Openings" ni ọgúnjó oṣù kaarun ọdún 1873.[17]

The classic label for Levi 501 jeans

Davis àti Strauss ṣe ìdánwò ìwádìí ìjìnlè pẹ̀lú orisirisi aṣọ. Àwọn Ìgbìyànjú ìbẹ̀rẹ̀ ni ṣe pẹ̀lú àwo aṣọ Ẹpọ́nrusù (brown) cotton duck, aṣọ kan tó nípọn .[lower-alpha 1] Denim je aṣọ kan tí ó dára fún rírán àwọn aṣọ iṣẹ́, wọn bèrè sí ń lọ wọn láti ṣe àwọn ṣòkòtò onírin "riveted pants". Aṣọ denim ni àwọn Olùpèsè aṣọ tí ilé Amẹrikà pèsè. Gbajúmọ̀ ìtàn àtenudénu se àṣìṣe pẹ̀lú wipe ni lati ile Nîmes ni wọ́n ti ko wá . Ìtàn àtenudénu míràn tún so wipe ni Strauss ń kókó tá àwọn ṣòkòtò aláwò Ẹpọ́nrusù fún àwọn awakùsà, tí wọ́n padà kùún ni àwò aró búlù, tí wọ́n sì yípadà sì lílọ aṣọ denim, tí ó sì jẹ́ wí pé lẹ́yìn ìgbà tí Davis kò ìwé sì ni ó tó bẹ̀rẹ̀ sí ní fi irin ìdáàbòbò rivets kún .[15]

Ní ìbẹ̀rẹ̀ pèpè, àwọn ṣòkòtò jìínsì Strauss kan je aṣọ tí ónípon tí àwọn òṣìṣẹ́ ìle isé factory workers, awakùsà, àgbẹ̀, àti àwọn adaranjè ń wò káàkiri àwọn agbègbè apá ìwọ òòrùn Ariwa ilé Amẹrikà.[18][19] Ní àwọn àkókò yí , ṣòkòtò àwọn ọkùnrin òun ni ó ní ojú Sípù fly sì ọwọ́ iwájú, tí sòkòtò àwọn obìnrin sì ni ojú Sípù sì ègbẹ́ apá òsì. [20] ni ìgbà tí Levi Strauss & Co. gbá ìwé àṣẹ ṣòkòtò jìínsì ìgbàlódé tí wọ́n pèsè púpò re ni Ọdún 1873, àpò ṣòkòtò méjì ni ó wà ní owó iwájú pẹ̀lú àpò ìlèmóra ni apá ọ̀tún ni ọwọ́ èyìn tí wọ́n fi èso pẹlẹbẹ onírin bàbà (copper rivets) sí.[14] Àpò kékeré ònírin rífẹ́ẹ̀tì bàbà óun ni Levi Strauss kókó fi sì ṣòkòtò jìínsì wọn ní àwọn ìparí ọdún 1870s.[21]

Ìtẹ̀síwájú látìgbàdégbà ní àwọn ǹkan bi ọ̀rúndún ọgúnjó sẹ́yìn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní Odún 1901, Levi Strauss fi àpò apá òsì ni ọwọ́ èyìn sì ara ṣòkòtò òní bọ́tìnì ọwọ́ iwájú wọn tí 501 model.[22] Eleyi lọ je Ìpilẹ̀ṣẹ̀ ṣòkòtò òde òní yìí tí a mọ̀ tí òun má ń ní àpò méjì ńlá àti kékeré kan ni iwájú, pẹ̀lú méjì ńlá mi lẹ́yìn tí àpapọ̀ àpò sì jẹ́ márùn.

Dídì gbajúmọ̀ àwọn aṣọ "waist overalls", gẹ́gẹ́bí atúnṣe mòó si aṣọ jìínsì gbèrègèjigè sì ni àkókò ogun àgbáyé World War II.[23] ni ìgbà tí yíò fi di ọdún 1960s, àti sòkòtò ọkùnrin àti obìnrin ní o ti ni ojú ihò zipper ní owó iwájú. Àwọn àwòrán ìgbàanì fi hàn wípé ni kí o tó di wípé aṣọ jìínsì di aṣọ ológe, télèri, òun má ń fẹ́ ni gẹgẹbi aṣọ àwọ̀lékè bib overalls sugbon ti oun kí ṣe "bib". Ní títí òótọ́, títí di ọdún 1960, Levi Strauss gan fúnra lára rẹ ni òun pé àwọn aṣọ tí òun ṣe jáde gẹ́gẹ́bi "waist overalls" dípò "jeans".

Lẹ́yìn tí James Dean so aṣọ jìínsì di gbajúmọ̀ nínú eré ìtàgé Rebel Without a Cause, wiwo aṣọ jìínsì di òun àmì ìṣọ̀tẹ̀ àwọn ọ̀dọ́ ní àkókò ọdún 1950s.[24][25] ni nkan bí ọdún 1960s, wiwo aṣọ jìínsì di òun ìtẹ́wọ́gbà, ní ìgbà tí yíò fi ó di ọdún 1970, wiwo aṣọ jìínsì to di òun èṣó gbọgbọ ni ọrílé-èdè United States.[26] ni Japan ni Ọdún 1977, ọ̀jọ̀gbọ́n kan ní ilé ìwé Yunifásítì Osaka University Philip Karl Pehda ba omobìnrin opé ìwé na wí nípa wiwo ṣòkòtò jìínsì ni yàrá ìkéko. Lẹ́yìn na, àwọn ọmọ ilẹ̀ ìwé ṣe ìwòde ìfièrò-inú hàn, lèyí tí ó fà àríyànjiyàn ni orile Ede ni ọdun na.[27][28]

Àpẹ̀rẹ̀ àwọn ṣòkòtò denim ti wọn mọ̀ọ́mọ̀ ya bèrè sí mi di òun èso ní àwọn àkókò ọdún 1935 ninu awon apẹ̀rẹ̀ àfihàn Vogue's June issue.[29] Michael Belluomo, ẹni tí ó jẹ́ oluye ìròyìn wo fún Sportswear International Magazine, Oct/Nov 1987, p. 45, kò ní ọdún 1965, Limbo, Yàrá ìta aṣọ kan ní apá iyo-òòrùn ni àwọn abúlé New York, jẹ́ alágbàtà ṣòkòtò jìínsì àkókò tí ó mọ̀ọ́mọ̀ fò ṣòkòtò jìínsì tuntun lójúnà áti je ki o funfun lójú, èrò òun di di òun ìtẹ́wọ́gbà. Ó tẹ̀síwájú pẹ̀lú gbígba oníṣẹ́ ọnà ìwọ òòrùn"[Limbo] ṣíṣé láti mọ ran àwọn àjákù Ìrépé aṣọ mo ṣòkòtò jìínsì gborogidi tí òun sì ń tàwón ni $200." Ní àwọn ìbéèrè ọdún 1980s, ilé itaja ṣòkòtò denim ṣe àfihàn àwọn ṣòkòtò tuntun tí wọ́n ti ní ojú fífò stone-washing Ọ̀nà ara fífọ̀ òun ti GWG ṣe ìdásílẹ̀ rẹ, tí wọ́n tún mọ̀ sì "Great Western Garment Co." Donald Freeland ti Edmonton, Alberta, òun ni ó gbé àsíá ọ́nà ara tuntun òun dání,[30] lèyí tí ó rán ṣòkòtò denim lọ́wọ́ láti wo òpò àwọn ọjà mìíràn. Ìtẹ́wọ́gbà ṣòkòtò jìínsì òun ni ó tẹ̀síwájú gba àwọn ọdún 1980s wo 1990s. Ní Ìbẹ̀rẹ̀ pèpè gẹ́gẹ́bi ṣòkòtò isé, ṣòkòtò jìínsì di aso afé ni àárín àwọn ọ̀rúndún ọgúnjó. [31]

Ṣòkòtò jìínsì Levi' 501s óun ni won ṣe àfihàn wọn gbangba-gbanga nínú ìpele akọsílẹ̀ àwọn ṣòkòtò A Gentleman's Wardrobe: Classic Clothes and the Modern Man ni Ọdún 1987 láti ọwọ́ ọníròyìn ìwé aṣọ ilé British, Paul Keers.[32]

Àwọn ìdàgbàsókè ni àwọn nkan ọ̀rúndún kọkànlélógún

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2001, Olùranso Ara ilè Japanese kan Chuck Roaste gba iwe ìjònlóntè ilé United States láti pèsè aṣọ iṣẹ́ utility patent èyí tí ó ṣe wọ ni ọ̀tún àti òdì tí òun ti fi orí ro láti nkan bí ọdún 1998.[33] wọn pèsè ṣòkòtò na ni abé orúkọ ìdánimọ̀ aṣọ Chuck Roaste label, aṣọ sòkòtò na ni ó ṣe àfikún àwọn èròjà, bí àpò, ojúbo zíípù, àti àwọn nkan èso ara ṣòkòtò mìíràn tí ó jẹ́ ki ṣòkòtò na le ṣé wò lójú àti ní òdì-kejì.[33]

Ní ọdún 2007, Details Men's Style Manual yaa abala ojú ìwé kan fún ṣòkòtò jìínsì, pẹ̀lú ọ̀rọ̀ ìso pé, "Wàyí óò, ní ìgbà tí aṣọ sòkòtò jìínsì tí di ìtẹ́wọ́gbà gbogboogbò, kò sì òun ti burú nínú kí ó ní eya ṣòkòtò jìínsì méjì tàbí jùbélo". Tí O sì tún ṣe àpèjúwe ṣòkòtò Levi's 501s gẹ́gẹ́bi òun "Iyì láti ìgbà tí wọ́n ti ṣe àfihàn rẹ̀" àti gẹgẹbi "kòsémááni ṣòkòtò". Àkọsílẹ̀ ìlànà ṣòkòtò pé ẹ̀yà sòkòtò jìínsì èyí tí wọ́n rán gboro gẹgẹbi sòkòtò Iyì ìgbàlódé tí òun fúni ni ìrísí American Graffiti."[34]

Ìlànà Ìṣàmújáde

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Pípa-Aṣọ-Láró

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Chemical structure of indigo dye, the blue of blue jeans

Ní ìbẹ̀rẹ̀ pèpè, àwọn aṣọ jìínsì ni wọn má ń rẹ dye ni aró búlù pẹ̀lú lílọ Aró Ẹ̀lú ara ewé indigo dye. Ọ̀pọ̀ àwọn aṣọ denim ni ayé òde òní ni wọn ń fi àwọn Aró Ẹ̀lú àtawódá ṣe. Ọ̀kẹ́rẹ́ jùlọ, Ẹgbẹ̀rún Tọ́ọ̀nù Aró Ẹ̀lú ni won pèsè ni ọdọọdún fún rírẹ̀ aṣọ jìínsì, botilejepe ìwọ̀nba gíràmù ni won nílò láti rẹ aṣọ sòkòtò jìínsì kan.[35] Fún àwọn àwò aṣọ sòkòtò denim mìíràn, àwọn àwò aró mìíràn ni wọn nílò láti lò. Lọ́wọ́lọ́wọ́, àwọn aṣọ jìínsì ni wọn pèlò ni oríṣiríṣi àwò tí wọ́n bá fẹ́ pẹ̀lú òwú.

Fún àwọn òye àti ìmọ̀ nípa ríre aṣọ ni aró, ká síwájú sí ní ibí denim àti níbi abala àríwísí Aró Atọwọ́dá.

Sáájú-Ìmúsúnkì

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Crowd of people wearing a variety of jean styles, including carpenter jeans, bootcut jeans, drainpipe jeans and lowrise jeans (Rome, 2008)

Ní ọdún 1962, Levi Strauss ṣe àfihàn àwọn ṣòkòtò oní-Ìsúnkì (àwọn ṣòkòtò jìínsì Lee ati Wrangler tí wá ní oní-ìsúnkì tipé-tipé); àwọn eleyi ò súnkì lẹ́yìn rírà wọn, lèyí tí ó fún àwọn tí wọ́n bá ra ni àyè láti ra ṣòkòtò èyí tí ó jẹ́ dèdé wọn. Àwọn ṣòkòtò tí wọ́n ti súnkì tí pò lára àwọn ṣòkòtò jìínsì ni òde òní. [36] Àwọn ṣòkòtò jìínsì yí ni wọn mò ń gẹ́gẹ́bi àwọn ṣòkòtò jìínsì 505. Àwọn sòkòtò jìínsì 505s óun na fi ara jọ ṣòkòtò 501s Pẹ̀lú ìyàtọ̀ ojú ihò zíípù. Ilé iṣẹ́ Levi's Corporation tún ṣe àfikún àwọn ṣòkòtò slim boot-cut tí won ń pè ni 517 àti 527. Ìyàtò tí ń bẹ ní àárín àwọn méjèèjì ní pe 517s jòkọ́ ni orí ìgégérù ìdí ti 527s sì wà ní abé ilà-Ìbàdí. Lẹ́yìn ìgbà na, Levi's ṣe àfikún àwọn ṣòkòtò mìíràn òmíràn-rán bí ṣòkòtò èyí tí ó fè, èyí tí ó tóbi, èyí tí ó fún ní ẹnu ẹsẹ̀.

Àwọn aṣọ jìínsì tí wọ́n mú ìyípadà àrà dé bá lẹ́yìn rírán

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ronald Reagan wearing stonewash denim associated with Western clothing, 1970s

Ọ̀pọ̀ àwọn aṣọ jìínsì tí wọ́n wuyì lójú ni wọn mú àyípadà ọ̀tún dé bá lẹ́yìn tí wọ́n gé, tí wọ́n sì rán wọn. Púpò nínú àwọn èwù tí wọ́n fi asọ denim rán ni wọn fò lójúnà áti lè mú àdínku de ba ìsúnkì shrinkage aṣọ na. Àwọn aṣọ denim tí wọ́n bá fò dadada ma ń jó aso tí wọ́n ti ń lọ fún ìgbà pípẹ́. Látàrí bí ewa rẹ, wọn tún mọ̀ lọ àwọn kẹ́míkà láti lè mú kí aṣọ denim fi ojú sísá hàn pẹ̀lú àwọn ọ̀nà àtọwọ́dá orisirisi bí stone washing.

Lílọ àwọn kẹ́míkà "acid wash" láti fò aṣọ denim ni wọn ṣe pèlò fífi àwọn kẹ́míkà bí acryl resin, phenol, hypochlorite, potassium permanganate, caustic soda, acids áti beebelo bóo.[37]

Botilejepe Aṣọ jìínsì yíya tàbí yíya aṣọ lójúnà áti ṣe ní òsó ( distressing) mó ń wáyé bí aṣó bá ti gbó, ṣùgbọ́n ni ìgbà mìíràn, àwọn olùgbàtà aṣọ má ń yaá pẹ̀lú bi ó ṣe jẹ́ wí pé aso tí wọ́n bá yaa tàbí tí ó ní ojú gbígbó má ń tà kíá kíá. Bí àpẹẹrẹ, Pucci ta "embellished mid-rise boyfriend jeans" fún £600 (US$860).[38]

Ìyípadà aṣọ látàrí lílò

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bí ó bá pè, àwọn aṣọ denim yio bèrè sí ṣáá, lèyí tí àwọn kan ká kùn òun èsó lábé àwọn àpẹrẹ kòkan. Ní àwọn àkókò tí wọ́n wo, ojú sísá yio bèrè sí mi hàn lára àwọn aso na pápá jùlọ ní àwọn ibi tí ó bá ń rí lílọ ju. Ní ara ṣòkòtò jìínsì, àwọn apẹ̀rẹ̀ agbègbè be a má wá ní orí itan, ìgìtísè, àti àwọn agbègbè ẹyin orúnkún. Ara àwọn àmì apẹ̀rẹ̀ ìdámò ṣòkòtò jìínsì tí òun ti ṣáá ní wọ̀nyí:

  • Ìté Oyin (honeycombs) àwọn àpẹẹrẹ ojú ìlà sísá lẹ́yìn orókún
  • Àwòrán fífasẹ́yìn lórí Aṣọ Jìnnsì (whiskers) –Dídán lẹ́gbẹ̀ẹ́ ibi awẹ́ (crotch) tàbí itan aṣọ jìnnsì, tí ó sì máa ń jọ irun imú ológbò.
  • Àrà kíkárí aṣọ jìnnsì sí orí bàtà (stacks) – Bí aṣọ ṣe máa ń kárí sínú tí ó sì ń peléke sí orí bàtà rẹ[39]
  • Àrà Ìlà lórí Aṣọ Jìnnsì (train tracks) – Àwọn ìlà funfun meji tí ó máa ń farahàn lẹ́gbẹ̀ẹ́ itan aṣọ jìnnsì lẹ́yìn fífọ̀.[39]
Àwọn aso jìínsì tí wọ́n yaa lọ́nà òsó
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Punk rock spearheads the Ramones wearing distressed jeans.
Ripped jeans were worn by singer Leigh Jones in this promotional photo.

Àwọn aṣọ jìínsì denim tí wọ́n ya ni yíya òsó jẹyọ láti ara àṣà ìgbàlódé punk ní ọdún 1970s. Àmọ́, ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 1970s tí Iggy Pop láti The Stooges ṣe àfihàn èrò aṣọ yíya nípa òsó ni ori ìtàgé. Lẹ́yìn tí ẹgbé olórin punk The Ramones ṣe imujade aṣọ yíya ni ònà ọ̀tún pẹ̀lú àwọn aṣọ tí ó fún móni lára tí wọ́n so di aso ẹgbẹ́ uniform wọn. Eleyi gangan ni ó ṣe àfihàn aso jìínsì yíya gẹ́gẹ́bi aṣọ àwọn olórin Punk ìgbàlódé.[40][41] Botilejepe àwọn olórin punk kan so yíya òun ìwò di ifi èrò inú wọn hàn lórí Ìsèjoba alasuwada àti ojúkòkòrò àwọn olóko-òwò, ọ̀pọ̀ won ni wọn lọ gẹ́gẹ́bi nkan òsó àwọn tálákà àti gẹ́gẹ́bi ìtakò sì asa iwoso lèyí tí ó papò mo akomona àkọ́lé do-it-yourself tí àwọn èyàn punk tí wọ́n tako àwọn ìṣẹ́ kan. Gégébí èrò ayélujára "Please Kill Me website", o se ni àlàyé wípé ni wiwo aṣọ yíya ṣe àfihàn ẹni tí òun ti àwọn ènìyàn so kò ní nkan ṣe pẹ̀lú rẹ tí ó òun ti oun mú inú ara ẹni dún sì jẹ́ òun ti o ṣe pàtàkì jù sí irú àwọn ènìyàn be.”.[40]

Ní àwọn ọdún 1980s, àwọn ilé iṣẹ́ aṣọ ṣe ìyípadà gentrified èrò òun pẹ̀lú bi wọn ṣe ṣe àgbéjáde àwọn aṣọ tí ó ní Abẹ́rẹ́ Olórí nínú wọn, lèyí tí ó jẹ́ ki ìtumò àṣà tuntun punk di òtúbánté.[42][43]Aso Denim di òkan gbòógì nínú àwọn aso àfojúsí fún ìlòdì sì àwòn àṣà ìwoso ìgbàlódé pẹ̀lú bi ọkùnrin àti obìnrin ṣe bèrè sí ní wo aso èwù àti ṣòkòtò tí ó ní àwọn nkan òsó bí Pínnì Aláàbò, safety pins, Abẹ́rẹ́ Olórí, àti àwọn àtẹ̀jáde Ọ̀rọ̀-ìpinnu. Ìpilẹ̀ṣẹ̀ àṣà na ni ó tún di gbajúmọ̀ padà ní àwọn ọdún 1990s Pẹ̀lú bí aṣọ àṣà grunge fashion ṣe jẹyọ. Àwọn aṣọ grunge àwọn ọ̀dọ́ je aṣọ jìínsì tí ó tóbi tí wọ́n yà gẹ́gẹ́ bí àrà, èwù flannel tàbí Aṣọ ti wọ́n fi irun àgùntàn hun bí Pendletons tí wọ́n rán lórí aṣọ èwù. Ihà ìtàpá sí àṣà aṣọ wíwò òun ló sọ asa "casual chic" di gbajúmọ̀ títí wo àwọn ọdún 2000s.

Ipa lórí Àyíká àti fífi ìjé ọmọ ènìyàn Ẹ̀dá síwájú

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Eyo aṣọ jìínsì aláwò búlù kan yio lọ ìwọ̀n omi 3,479 litres (919 US gal) ni àkókò ayé rẹ. Eléyí pẹ̀lú àwọn omi tí wọ́n fi gbìn òwú, tí wọ́n fi ṣe aṣọ na àti gbogbo ìgbà tí ẹni tí ó rá yio fi fo aso na.[44] Ní àkókò tí wọ́n ń bá ṣe aso jìínsì, dédé iye omi tí wọ́n má ń lọ tí wọ́n ń bá ń lọ ẹ̀rọ Pullman ń má ń to àádọ́rùn omi lítà kan fún jìínsì kan àmọ́ tí wọ́n lè dínkù Étàdínlógbòn lítà nípa lílo àwọn ẹ̀rọ ìgbàlódé "frontloaders" .[45] Àwọn ọ̀nà ìgbàlódé ask fífọ̀ bí 'Droptima' Le mú àdínku dé bá dórí mítà omi mẹ́fà omi títún àti mítà omi mẹ́rìn omi àlòkù.[45][46][47][48]

Ìpèsè àwọn aṣọ jìínsì tí wọ́n dàbí pé wọ́n ti lọ wọn rí tẹ́lẹ̀ mo ń ní àwọn ìpalára fún àwọn àyíká wa, ìpalára òun ni ó ní ṣe pẹ̀lú ọ́nà tí wọ́n bá gba ṣe àwọn òun èlò tí wọ́n fi pèsè aṣọ na. Lilo Sandblasting áti sandpaper le fa àìsàn silicosis fún àwọn òṣìṣẹ́, ní Turkey, ó kéré jù lọ, àwọn òṣìṣẹ́ bí ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) òun ni wọn ti lùgbàdì àìsàn yí, tí mẹ́rìndínláàdọ́ta (46) sì ti pàṣè àìsàn na kú. Awon ile ise ìpèsè aṣọ jìínsì kan tí kéde ìfòfindè lílọ sandblasting.[49]

Ìtọ́jú àti Wíwò

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bótilèjépé òpò aṣọ jìínsì ni wọn ti súnkì láti ilé iṣẹ́, wọn si tún lè súnkì síwájú sí pẹ̀lú ìpàdánù àwò ara wọ látàrí fífọ̀. Ìpè iṣẹ́ aṣọ Levi Strauss gba ni ìmọ̀ràn láti mọ ṣe mọ fo aṣọ jìínsì ni òpò ìgbà. [50] Eléyi àti àwọn ìmọ̀ràn miran láti mọ ṣe mọ fo aṣọ jìínsì òun ni wón rí àtakò. Cory Warren, olóòtú ìròyìn ni LS&Co. Unzipped, ṣe ìtúpalẹ̀ àwọn àtakò won yí nínú àtẹ̀jáde èèsì rẹ kan:

ìmọ̀ràn tí àwa fún yín ní pe ki ẹ mọ fòó ni èkòkan, àmọ́ ni inú ara yín, ẹ mọ oun ti ó tó. Ọjọ́ tí òrùn bá mú, ẹ sisé ìdọ̀tí? Edákun ẹ fọ aso yín ó. Ọjọ́ tí òtútù mú, isé ọ́físì ni ẹ ṣe? Bóyá ẹ lè wọ ni èmejì kí ẹ tó kó wọn lọ sínú èrò ìfoso fún fífọ̀. Ní tèmi, bí mo bá wo aṣọ lọ sí ibise ni ọjọ Etì tí ojú ọjọ́ sì tutù, mo sábà má tun wò ní ọjọ́ àbáméta. Tí òjò àbáméta bá sì jẹ́ èyí tí mo lò ní inú ilé, mo tún lè wọ ni ọjọ Àìkú.

Fún àwọn ẹlòmíràn tí wọ́n ó nífé sì fifo aso jìínsì wọn ní gbogbo ìgbà, àwọn ìmọ̀ràn Ìtọ́kasí kan sọ pé kí wọ́n sọ sínú fíríjì láti dènà àwọn kòkòrò tí wọ́n fa òórùn. Ṣùgbọ́n , ìmọ̀ràn yí ni ìwádìí ìjìnlè tí fi idi rẹ múlè pé irọ́ ni.[51]

Àwọn ọ̀rọ̀ ìpèléjó

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Èsùn ìfipá báni lòpò ní Italy

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Ní Rome, Italy, ní ọdún 1992, wọ́n fi ẹ̀sùn ìfipá bánilòpò kan olùkọ́ni lókowà wá kan ọmọ ọdún aárùndínláàádọ́ta. Ni ìgbà tí ó gbé ọmọbìnrin ọmọ ọdún méjìdínlógún kan láti kọ́ ni ọkọ̀ wà ní ìgbà àkọ́kọ́ rẹ̀, wọn fi èsùn kàán wipe ní o fi ipá bá lòpò fún wákàtí mẹ́rìn gbáko, lẹ́yìn na ni ó sọ fún pé bí ó bá sọ fún ẹnikẹ́ni òun yio pa. Lẹ́yìn ìgbà na ni alẹ́, ọmọbìnrin na so fún àwọn òbí rẹ tí àwọn òbí rẹ sì gbà láti pèé ni ẹjọ́. Lẹ́yìn ìgbà tí adájọ́ tí dajo fífi ipá bánilòpò fun tán, ilé ejò gíga tí Supreme Court of Cassation ní Italy padà yí ìdájọ́ na padà ní ọdún 1998 pẹ̀lú àlàyé pé ọmọbìnrin na wo ṣòkòtò jìínsì tí ó fún Gádí-gádí. Wọn jiyàn pé,ọmọbìnrin na nílò láti rán lọ́wọ́ bo ṣòkòtò rẹ ni lèyí tí ó so di ìbálòpọ̀ àjọṣe consensual. Ile ejó so nínú ọ̀rọ̀ rẹ pé "ó jẹ́ òun mímò pé ó ṣòro láti bo ṣòkòtò jìínsì fífún bí kò bá sì ipa ẹni tí ó wọ níbè". [52]

Ìdájọ́ ilé ejò òun fà awuyewuye púpò larin awon ajàfétó ọmọbìnrin. Ojo kan lẹ́yìn ìdájọ́ tuntun òun, àwọn obìnrin ní ilé ìgbìmọ̀ ìjọba Italian Parliament tí Italy ṣe ìwóde Pẹ̀lú wíwo sòkòtò jìínsì pẹ̀lú Pátákó Ìfihàn tí wọ́n kó sì ni ara pé, " Jìínsì: Kí ṣe Ẹ̀rí Ìmúdájú nínú Òfin fun yíyóríbó nínú èsùn ìfipá bánilòpò"gẹgẹbi ifi àtìléyìn hàn. Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà Ilé California California Senate áti ilé -Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Olómìnira ti California Assembly na si fi owó tí lẹ́yìn. Patricia Giggans, ẹni tí ṣe olùdarí àgbà fún Commission on Assaults Against Women (now Peace Over Violence) ní Los Angeles sì so ọjọ́ denim Denim Day di ayẹyẹ olódodún. Títí di 2011 ó kéré jù lọ, àwọn ìpínlẹ̀ ogún ni ọrílé-èdè U.S. Ní wón ti ń ṣe ayẹyẹ ọjọ́ denim nínú oṣù kẹrin. Wiwo aṣọ jìínsì ni ọjọ na ti di àmì ìfi èrò inú hàn tako àwọn ìhà be sì esun ìfipá bánilòpò. Ní ọdún 2008 ilé ejò àgbà tí Supreme Court of Cassation da ìdájọ́ tuntun òun nu, fún ìdí èyí, kò sì òun ti je lílọ Sokoto denim lọ́ wọò gẹ́gẹ́bi Ẹ̀rí Ìmúdájú nínú ejó ìfipá báni lòpò.[53][52]

Èsùn Rokotov-Faibishenko

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 1957, ní àkókò ìgbà ayẹyẹ ọdún kẹfà àwọn ọ̀dọ́ àti akẹ́kọ 6th World Festival of Youth and Students tí ó wáyé ní Moscow, Soviet Union (Russia òde òní), àwọn ṣòkòtò jìínsì láti apá ìwò òòrùn ni wọn ṣe àfihàn wọn sì apá ọ̀dọ́ ilé Moscow tí ó sì dá akitiyan ńlá Kale lórí rírà rẹ tí wọ́n ṣe àpèjúwe rẹ gẹ́gẹ́bi "jeans fever" ni igba na lóùń. Àwọn ènìyàn nífẹ̀ẹ́ sí àwọn ṣòkòtò búlù apá ilé ìwọ òrùn ju aláwò aro dúdú tí wọ́n ń ṣe ní ilé wọn lọ. Nínú ìròrí àwọn adarí ilé Soviet, irú ìṣẹ̀lẹ̀ be ni ó tàbùkù ìje ara ile Soviet tí ó sì dabi ìjáwé olú borí ilé ìwọ òrùn lórí wọn. Ní ọdún 1961, àwọn onífàyàwó méjì kán, Y. T. Rokotov àti V. P. Faibishenko, ní owó bá fún ṣíṣe fàyàwó ọwọ́ ilé òkèrè láti òkè òkun àti àwọn ṣòkòtò jìínsì búlù àti àwọn ẹrù òfin mìíràn. Lábé Ìsèjoba Nikita Khrushchev, àwọn méjèèjì ní wón dájó ikú fún tí wọ́n sì pa wọ́n.

Àwọn òun tí ó gbòde

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọjà ni Àgbáyé fún Jìínsì

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ariwa ilé America kó ìdá 39% nípa jìínsì rírà ni Àgbáyé, lẹ́yìn na ni ó kan apá ìwò ọrùn ilé Europe pẹ̀lú rírà 20%, Japan àti Korea jẹ́ 10% tí gbọgbọ ẹka nínú ayé sì kó ìdá 31% tí ó kù. [54]

Àwọn oníbàrá aṣọ jìínsì ni Orílẹ̀ èdè United States na bíllíónù mẹ́rìnlá ọwọ́ Dollar (US$14 billion) lórí rírà jìínsì ni ọdun 2004 àti bíllíónù máárùndínlógbòn dollar (US$15 billion) ní ọdún 2005.[14] àwọn oníbàrá jìínsì ni ọrílé-èdè US ra bíllíónù mẹ́tàlá bélénjá méjọ dollar (US$13.8 billion) lórí aṣọ jìínsì ọkùnrin àti obìnrin ní ìparí oṣù kẹrin ọdún 2011, gẹgẹbi ìwádìí ọjà tí aájò NPD Group ṣe.[55]

Orílẹ̀ èdè Soviet Union

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní orílẹ̀ èdè Soviet Union, jìínsì je àmì ìgbẹ́ ayé àwọn ará ilé ìwò òrùn.[56] eré kìtà-kìtà láti ra aṣọ jìínsì tí wọ́n dàpé ni "jeans fever" ṣẹlẹ̀ ni ọrílé-èdè USSR ni Ọdún 1957 ni àkókò ayẹyẹ àwọn ọ̀dọ́ àti àwọn akẹ́kọ̀ọ́ World Festival of Youth and Students.[57] Gégébí àtẹ̀jáde àkọsílẹ̀ àwọn orúkọ aso ọdún 1961 ni Soviet, jìínsì ni wọn rí bí aṣọ àwọn òṣìṣẹ́ (рабочий костюм, rabochii kostyum).[58]

Ilé iṣẹ́ jìínsì Rokotov àti Fainberg ni won so lórúko olùgbèjà adájọ́ nínú ejò tí Rokotov–Faibishenko, Yan T. Rokotov àti Vladislav P. Faibishenko, tí wọ́n pa lábé èsùn ìṣe fàyàwó jìínsì [57]

Bótilèjépé wọn ò fi ìfòfindè aṣọ jìínsì pátápátá, ṣùgbọ́n ask jìínsì ni ó ṣòro rí ní orílẹ̀ èdè Soviet union látàrí bi àwọn ọ̀dọ́ ilé Soviet tí àwọn na fẹ̀ ṣe ìfarawé àwọn gbajúgbajà òṣèré orí ìtàgé ilé ìwò òòrùn ṣe rí wọn bí àmì ìtakò. Ijoba ilé Soviet union tako ìṣòwò ọjà aṣọ jìínsì nítorí bí yio se dabi ẹni wípé ìbẹ̀rẹ̀ fún aṣọ jìínsì ni ọjà 'market' ni ó mú wọn tẹríba, fún ètò orò Ajé capitalist.[59] Àwọn ènìyàn sá akitiyan àti ipá wọn láti rí aso ṣòkòtò jìínsì láti ìwò-òòrùn wo. Èyí sì ṣe okunfa ìdásílẹ̀ ọjà gbàrogùdù ' black markets' àti ìdásílẹ̀ àwọn àgbélèro ọjà 'bootlegging' sòkòtò jìíns lèyí tí ó padà nkan ńlá nínú ìwé ìtàn àṣà history of the Soviet Union.ilé Soviet union[60]

Ìyípadà Iṣẹ́-ọjà aṣọ ìdárayá ṣí aṣọ fásíònù nínú ètò ọrọ̀-ajé

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2014, àwọn ọ̀dọ́ ń rà àwọn aṣọ ìgbàlódé bi athleisure láti àwọn àwọn ilé iṣẹ́ ìpèsè aso bí Nike àti Lululemon dípò àwọn aṣọ denim classics láti àwọn ilé iṣẹ́ ìpèsè aṣọ bí Abercrombie & Fitch.[61] Activewear ní ọdún 2014 àkọsílẹ̀ rírà aṣọ àwọn ọ̀dọ́ wá ní nkan ni 28%, lèyí tí ó jẹ́ ìdàgbàsókè sì títí 6% ni Ọdún 2008. Ní ọdún 2014, Nike, Lululemon, Under Armour, àti Adidas jẹ́ ara àwọn ilé iṣẹ́ ìpèsè aso tí wón gbájugbajà larin awon ọ̀dọ́. Àwọn alágbàtà aṣọ tí bèrè sí mú àdínku de ba iye tí wọ́n tá ọjà wọn. Bloomberg filéde pé ilé iṣẹ́ ìpèsè aso Levi's dúró ṣinṣin pẹ̀lú aṣọ tí wọ́n mo wọn mó (denim) dípò kí ó tẹ̀lé ojú òpó tuntun ti àwọn oníbàrá aṣọ sún sì. Látàrí èyí, ọwọ́ ọjà tí ń wọlé fún Levi's já wálẹ̀ láti bíllíónù méje Dollar (US$7 billion) sì bíllíónù Mẹ́rìn Bélénjá tondó méjọ (US$4.8 billion) ní ọdún 2015.[62]

Ní oṣù kejì ọdún 2021, wọn ṣe àfihàn pé ìtẹ̀síwájú dé bá ọwọ́ tí athleisure pa wọlé pẹ̀lú ìlẹ̀kùn bi 84% láti ǹkan bi oṣù kẹèta ọdún 2020 látàrí àtìmọ́lé ìdáàbòbò lọ́wọ́ ààrùn COVID-19.[63]

Àwọn àtúnṣe nípa ìrísí ṣòkòtò jìínsì

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Cigarette: Tí wón se lọ́nà tí yíò je ki o fún sugbon ko fún gádí-gádí mo itan àti gìgìtísè[64]
  • Cropped: Sòkòtò tí wọ́n gé ni ẹsẹ̀ tí kò gùn ju orí Kókó-ẹsẹ̀ lọ.[64]
  • Relaxed[64]
  • Skinny: Sòkòtò tí wọ́n rán tí ó fún mo ara gádí-gádí[64]
  • Wide-leg; or with cropped variant: sòkòtò èyí je eyi ti o má ń dúró ní orí ìlà ìgégérù ìdí, tí ó sì má ń tobi níwònba soro láti orunkun de kókó ẹsẹ̀.[64]
  • Mom/Mum: Sòkòtò jìínsì tí òun má dúró ní orí òkè ìgégérù ìdí ti o si tobi ni ọwọ́ itan pẹ̀lú ẹnu ti o fún pò díẹ̀ ni ọwọ́ ìsàlẹ̀.[65]
  • Straight-leg: Awon ṣòkòtò jìínsì irú èyí má ń wálẹ̀ sooro láti òkè de ìsàlẹ̀.[66]
  • Boyfriend: Àwọn ṣòkòtò jìínsì eleyi má ń dúró ní orí ìka ìgégérù ìdí ti o si má ń tobi díẹ̀.[65]
  • Flared, tàbí bell-bottomed: Ní òpò ìgbà, ṣòkòtò jìínsì irú èyí ma ń fún ní owó itan sugbon yio fe ni ọwọ́ ìsàlẹ̀ ẹsẹ̀ bèrè láti orókún.[67]
  • High-waisted jeans Àwọn ṣòkòtò tí wọ́n ma ń dúró ní orí idodo di gbajúmọ̀ ni àwọn àkókò ìgbà ọdún 1970s, ṣùgbọ́n tí wọ́n tún ṣẹ̀ṣẹ̀ bèrè sí mo di gbajúmọ̀ ni òde òní. Àwọn ṣòkòtò tí wọ́n ma ń dúró ní orí idodo òní won ṣe dámọ̀ pẹ̀lú bi won ṣe má ń dúró lórí idodo. Won lè fún mo ara, kí wọ́n tobi, tí wọ́n sì má ń wá ní oríṣiríṣi àwò àti ìrírí.[68]

Jìnnsì tí ó má ń jòkọ́ sì òkè ìbàdí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ọníròyìn filéde ni ọdun 2017 wipe ni awuyewuye ọ̀tún lórí àwọn jìínsì tí wọ́n ń jòkọ́ ni ìsàlẹ̀ ìbàdí ' low-rise jeans', tí ó jẹ́ gbajúmọ̀ ni àwọn nkan bí ọdún 1990s àti 2000s, òun ni ó tún ti ń padà gba òde látàrí ìfẹ́ tí wọ́n ní sì àṣà aṣọ wíwò ọ̀tun kan tí ń jẹ Y2K.

Ní àwọn ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2000s, ṣòkòtò jìínsì tí ó dúró ní ìsàlẹ̀ ìbàdí òun ni wón sábà má ń rí ní àwọn ibi ayẹyẹ àjọ̀dún àwọn gbajúmọ̀ olórin bí Britney Spears, Jennifer Lopez, Paris Hilton, Gwen Stefani àti Christina Aguilera,tí wọ́n ní afijo pẹ̀lú àṣà ìwoso Y2K. No Odún 2021, iwadi ni ori èrò ayélujára fi hàn wípé ni àṣà ìwoso 'y2k fashion' òun ni ó tún ní ìdàgbàsókè 193%,[69] lèyí tí ó fi hàn wípé ni àṣà ìwoso tí ń padà wá, tí aṣọ jìínsì tí òun dúró ní ìsàlẹ̀ ìbàdí sì ti ń di nkan iyì ni àárín àwọn ọ̀dọ́langba.[70][71][72]

Àwọn ṣòkòtò jìínsì tí òun má ń dúró ní ìsàlẹ̀ ìbàdí ni ó má ń wá pẹ̀lú ìwọ̀n 2–3 inches (5–8 cm) tàbí jùbélo wálẹ̀ ni ìsàlẹ̀ idodo.[73] àwọn ṣòkòtò jìínsì tí ó má ń dúró ní ìsàlẹ̀ ìbàdí tí wọ́n bá ṣe láti ilé iṣẹ́ aṣọ ni jíjìnnà ìlà ìbàdí sì abé ṣòkòtò sábà má ń kéré. Ìrísí àwọn ṣòkòtò yí òun ni wón je kó rí bè látàrí bí wọn ṣe ṣe lèyí tí ó má ń jẹ ki o dabi ẹni wípé ṣòkòtò òun Ṣáàgì tabi wá sí ilé ni ìdí ju bí ótiyẹ lo. Eleyi kí ṣe irú Ṣáàgì ' sagging' , tí àwọn olórin ọkùnrin tàkasúfe sódì gbajúmọ̀ ni àwọn nkan ọdún 1990s o.

Bí wọn ṣe ń ṣe ṣòkòtò jìínsì láti ilé iṣẹ́

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó tún lè yẹ àwọn eléyi náà wò

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. ↑ Bottom weight Ó jẹ́ Ìrépé aso kan tí ó dára fún rírán ṣòkòtò àti síkéètì pants (a.k.a. bottoms). Kí ṣe wípé ni aṣọ òun ó nípọn tàrà be na ṣùgbọ́n ó wúwo jù òun ti wọn lé fi rán àwọn ask bí bùláùsì tàbí èwù.
  1. ↑ "A Nevada Stylist: Your Denim Jeans Are a Nevada Invention". Nevada State Museum Newsletter 36 (3): 4. 2006. Archived from the original on April 29, 2013. https://web.archive.org/web/20130429105158/http://museums.nevadaculture.org/dmdocuments/mus-let37.pdf. Retrieved January 29, 2015.
  2. ↑ Empty citation (help)
  3. ↑ "Textiles in the Slave Trade" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2026-02-10.
  4. ↑ Kobayashi, Kazuo (2013-06-27). "Indian cotton textiles in the eighteenth-century Atlantic economy - Africa at LSE". Africa at LSE - LSE’s engagement with Africa. Retrieved 2026-02-09.
  5. ↑ "The synthesis of indigo". Ingenious.org.uk. Archived from the original on March 4, 2016. Retrieved October 28, 2015. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. ↑ "Jean - Etymology, Origin & Meaning of the Name". etymonline (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2026-05-07.
  7. ↑ Transnationalism and Society: An Introduction. McFarland. 2011. ISBN 978-0-78648625-0. https://books.google.com/books?id=Qy4YtuIHsQcC&pg=PA235. Retrieved August 14, 2017.
  8. ↑ "Jeans". facweb.cs.depaul.edu. Archived from the original on June 19, 2017. Retrieved August 14, 2017. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. 1 2 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named "Gruber_2010".
  10. ↑ National Archives (February 18, 1576). "Import and Export books for the Port of Barnstaple". E 190/930/5.
  11. ↑ Shopping in the Renaissance: Consumer Cultures in Italy 1400–1600. New Haven: Yale University Press. 2005. p. 44. https://archive.org/details/shoppinginrenais0000welc.
  12. ↑ Saris, John; Satow, Ernest Mason (1900). The voyage of Captain John Saris to Japan, 1613. University of California Libraries. London : Printed for the Hakluyt Society. http://archive.org/details/voyageofcaptainj00saririch.
  13. 1 2 William, Carrie (September 3, 2017). "Origin and History of Dungaree Fabric". Historyofjeans.com. Archived from the original on November 25, 2015. Retrieved October 28, 2015. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  14. 1 2 3 Jeans: A Cultural History of an American Icon. London: Gotham Books. August 17, 2006. ISBN 978-1-59240-214-4. OCLC 62697070. https://archive.org/details/jeansculturalhis00sull.
  15. 1 2 Downey, Lynn (2007). "A Short History of Denim" (PDF). official Levi Strauss & Co. historian. Archived from the original (PDF) on August 9, 2014. Retrieved June 2, 2014. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  16. ↑ Wagman-Gellar, Marlene (2010). Eureka!: The Surprising Stories Behind the Ideas That Shaped the World, Eureka #3 (1871) (unpaginated). Penguin Group (USA), Inc. Retrieved October 2, 2011.
  17. ↑ Àdàkọ:US patent
  18. ↑ "To die for? The health and safety of fast fashion" (in en). Occupational Medicine 63 (5): 317–319. July 1, 2013. doi:10.1093/occmed/kqt079. ISSN 0962-7480. PMID 23837074.
  19. ↑ "A History Of Blue Jeans: From Miners' Wear to American Classic" (in en). Mother Earth News. http://www.motherearthnews.com/nature-and-environment/history-of-blue-jeans-zmaz90jazshe.
  20. ↑ "Style: August 2015" (in en-US). New Orleans Living Magazine. Archived from the original on March 17, 2017. https://web.archive.org/web/20170317144125/http://www.livingneworleans.com/?p=11550.
  21. ↑ "Small pocket on your pants and jeans: Here's what it's for – Insider". Insider.com. Archived from the original on October 26, 2023. Retrieved April 30, 2020. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  22. ↑ "Pockets Full of History – Levi Strauss & Co". January 12, 2017. Archived from the original on June 19, 2020. Retrieved April 30, 2020. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  23. ↑ Schellinger, A. (2016). Aircraft Nose Art: American, French and British Imagery and Its Influences from World War I through the Vietnam War. McFarland, Incorporated, Publishers. p. 82. ISBN 978-1-4766-1932-3. https://books.google.com/books?id=oV7TCwAAQBAJ&pg=PA82. Retrieved January 29, 2024.
  24. ↑ "James Dean: an enduring influence on modern fashion | Fashion". The Guardian. https://www.theguardian.com/fashion/fashion-blog/2014/apr/18/james-dean-an-enduring-influence-on-modern-fashion.
  25. ↑ Schober, Anna (2001). Blue Jeans. Vom Leben in Stoffen und Bildern. Frankfurt/ New York: Campus.
  26. ↑ The Classic Ten: poella grande y gruesa The True Story of the Little Black Dress and Nine Other Fashion Favorites. Penguin. 2003. p. 42. ISBN 978-0-14-200356-5. https://books.google.com/books?id=hCap5dsIJiAC&pg=PT42. Retrieved January 13, 2011.
  27. ↑ "女生七嘴八舌嚷「解放」 老教授硬是不准入課堂" (in zh). The Kung Sheung Daily News. May 27, 1977. https://mmis.hkpl.gov.hk/coverpage/-/coverpage/view?_coverpage_WAR_mmisportalportlet_hsf=%E7%89%9B%E4%BB%94%E8%A4%B2&_coverpage_WAR_mmisportalportlet_actual_q=%28%20verbatim_dc.collection%3A%28%22Old%5C%20HK%5C%20Newspapers%22%29%20%29%20AND+%28%20%28%20allTermsMandatory%3A%28true%29%20OR+all_dc.title%3A%28%E7%89%9B%E4%BB%94%E8%A4%B2%29%20OR+all_dc.creator%3A%28%E7%89%9B%E4%BB%94%E8%A4%B2%29%20OR+all_dc.contributor%3A%28%E7%89%9B%E4%BB%94%E8%A4%B2%29%20OR+all_dc.subject%3A%28%E7%89%9B%E4%BB%94%E8%A4%B2%29%20OR+fulltext%3A%28%E7%89%9B%E4%BB%94%E8%A4%B2%29%20OR+all_dc.description%3A%28%E7%89%9B%E4%BB%94%E8%A4%B2%29%20%29%20%29&_coverpage_WAR_mmisportalportlet_sort_field=score&p_r_p_-1078056564_c=QF757YsWv5%2BaFKLr9PBvgILoEa3mihLU&_coverpage_WAR_mmisportalportlet_o=11&_coverpage_WAR_mmisportalportlet_sort_order=desc.
  28. ↑ "大阪大学講師 過去にジーンズ姿の女子大生の受講を拒否" (in ja). NEWSポストセブン. April 9, 2011. https://www.news-postseven.com/archives/20110409_17067.html.
  29. ↑ "De Nimes". vice.com. March 11, 2013. Archived from the original on October 26, 2023. Retrieved May 30, 2017. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  30. ↑ "Levi's By the Numbers (Men's)". Worldflow Knowledge. Archived from the original on May 8, 2009. Retrieved December 31, 2010. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  31. ↑ Foreman, Katya (April 1, 2015). "Jean genie: The denim evolution". Archived from the original on April 25, 2016. Retrieved May 29, 2016. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  32. ↑ Keers, Paul (1987). A Gentleman's Wardrobe: Classic Clothes and the Modern Man. London: Weidenfeld & Nicolson. pp. 56–57. ISBN 9780297791911. https://archive.org/details/gentlemanswardro0000keer.
  33. 1 2 Malone, Scott (February 19, 2004). "Chuck Roaste's New 'Guru'". WWD 187 (35): 9. https://wwd.com/fashion-news/fashion-features/denim-dish-chuck-roaste-s-new-guru-galey-still-in-red-valley-connects-the-dot-696964/.
  34. ↑ Peres, Daniel, ed (2007). "Jeans". Details Men's Style Manual. New York: Gotham Books. pp. 132–139. ISBN 9781592403288.
  35. ↑ "Indigo and Indigo Colorants". Ullmann's Encyclopedia of Industrial Chemistry. Weinheim, Germany: Wiley-VCH. 2004. doi:10.1002/14356007.a14_149.pub2. ISBN 3527306730.
  36. ↑ "Levi Strauss & Co. Timeline" (PDF). Archived from the original (PDF) on October 9, 2012. Retrieved November 23, 2012. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  37. ↑ Der Preis der Bluejeans documentary by Studio Hamburg 2012
  38. ↑ "Am I too old for ... ripped jeans?". The Times: p. 11. March 8, 2014. http://www.thetimes.co.uk/tto/magazine/article4021673.ece.
  39. 1 2 Shapira, J.A. (December 14, 2016). "The Denim Jeans Guide — Gentleman's Gazette". www.gentlemansgazette.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on October 26, 2023. Retrieved November 23, 2018. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  40. 1 2 Jensen, Ingrid (24 July 2019). "”Ripped Jeans: From Kate Hepburn to Iggy Pop”". Please Kill Me. Retrieved 15 April 2026.
  41. ↑ Woodward, Daisy (16 November 2016). "”Ten of Iggy Pop's Stylish Moments”". DAZED. Retrieved 15 April 2026.
  42. ↑ "Distressed denim: a history". September 15, 2023. Archived from the original on May 22, 2017. Retrieved May 22, 2017. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  43. ↑ Pickering, Ethan (18 April 2022). "” The History of Ripped Jeans through the Decades”". MTSU Sidelines. Retrieved 15 April 2026.
  44. ↑ "Changes in the Air - Stone-Washed Blue Jeans (Minus the Washed)". The New York Times (San Francisco, California, US). November 1, 2011. https://www.nytimes.com/2011/11/02/science/earth/levi-strauss-tries-to-minimize-water-use.html.
  45. ↑ "Droptima - Abwasserfreie Wasch-Technologie". IKU Newsroom (in Èdè Jámánì). Karlruhe, Germany: Fraunhofer-Institut für System- und Innovationsforschung ISI. 2022. Archived from the original on July 9, 2022. Retrieved July 10, 2022. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  46. ↑ "Klink Textile Pflege-Dienste: Kooperation mit Entwicklungs- und Schwellenländern bei technischen oder sozialen Innovationen für Umwelt- und Klimaschutz – Preisträger 2022". Innovationspreis für Klima und Umwelt (IKU) (in Èdè Jámánì). Karlsruhe, Germany: Fraunhofer-Institut für System- und Innovationsforschung ISI. 2022. Archived from the original on July 10, 2022. Retrieved July 9, 2022. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  47. ↑ Dontscheff, Alexander (May 30, 2022). "Unternehmen aus Salzgitter will zig Millionen Kubikmeter Wasser retten - Für eine Neuerung der Jeans-Produktion gab es den Innovationspreis für Klima und Umwelt des Bundesministeriums für Wirtschaft und Umwelt.". Salzgitter. regionalHeute.de (in Èdè Jámánì). Wolfenbüttel, Germany: Medien für die Region GmbH. Archived from the original on July 10, 2022. Retrieved July 10, 2022. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  48. ↑ "Sandblasted jeans: Should we give up distressed denim?". BBC News (BBC World Service). October 1, 2011. https://www.bbc.co.uk/news/magazine-15017790.
  49. ↑ "Wash My Jeans? Hardly.". LS&CO. UNZIPPED. July 30, 2012. Archived from the original on September 11, 2010. https://web.archive.org/web/20100911121229/http://www.levistrauss.com/blogs/wash-my-jeans-hardly.
  50. ↑ "History, Travel, Arts, Science, People, Places | Smithsonian". Blogs.smithsonianmag.com. Archived from the original on November 11, 2020. Retrieved October 28, 2015. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  51. 1 2 "Rape, Blue Jeans, and Judicial Developments in Italy". Columbia Journal of European Law. 2009. http://www.cjel.net/online/16_1-faedi/. Retrieved April 26, 2011. "Rape, Blue Jeans, and Judicial Developments in Italy". GGU Law Digital Commons 104: 1–4. 2009. Archived from the original on March 8, 2022. https://web.archive.org/web/20220308123342/https://digitalcommons.law.ggu.edu/pubs/104/. Retrieved October 17, 2021.
  52. ↑ Owen, Richard (July 23, 2008). "Italian court reverses 'tight jeans' rape ruling". Irish Independent (Dublin). https://www.independent.ie/world-news/europe/italian-court-reverses-tight-jeans-rape-ruling-26464014.html.
  53. ↑ "World Denim Market – A Report on Capacities, Market Size, Forecasts etc". Denimsandjeans.com. October 13, 2009. Archived from the original on September 23, 2015. Retrieved October 28, 2015. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  54. ↑ "How Can Jeans Cost $300?". The Wall Street Journal. July 7, 2011. https://www.wsj.com/articles/SB10001424052702303365804576429730284498872.
  55. ↑ Menzel, Rebecca (2004) (in de). Jeans in der DDR: vom tieferen Sinn einer Freizeithose. Ch. Links Verlag. ISBN 978-3-86153-335-1. https://books.google.com/books?id=ZUCVNbVrYyEC.
  56. 1 2 Rudevich, Alexei. Worth going to prison for: Getting hold of jeans in the USSR Archived September 27, 2014, at the Wayback Machine.. Russia Beyond the Headlines, September 16, 2014. Accessed on November 16, 2014.
  57. ↑ Lupandin, K. K., ed (1961). English-Russian Textile Dictionary (Second Edition, Revised and Englarged ed.). Central Editorial Board, Foreign-Language Scientific and Technical Dictionaries, Fizmatgiz. p. 247.
  58. ↑ "Soviet Denim Smuggling—Jeans Behind the Iron Curtain" (in en-US). Heddels. May 9, 2018. https://www.heddels.com/2014/09/soviet-denim-smuggling-history-jeans-behind-iron-curtain/.
  59. ↑ "Exploring the USSR's underground obsession with Levi's 501s" (in en). Dazed. August 19, 2016. http://www.dazeddigital.com/fashion/article/32495/1/exploring-the-ussr-s-underground-obsession-with-levi-s-501s.
  60. ↑ "How Teens Are Spending Money". Business Insider. April 9, 2014. Archived from the original on November 8, 2015. Retrieved October 28, 2015. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  61. ↑ Lutz, Ashley (October 11, 2015). "A longtime American wardrobe staple is in danger of extinction". AOL. Archived from the original on October 30, 2015. Retrieved October 28, 2015. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  62. ↑ Bottomley, Tom (February 17, 2021). "Athleisure orders rise by 84% since start of pandemic". TheIndustry.fashion (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on October 20, 2022. Retrieved October 20, 2022. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  63. 1 2 3 4 5 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named "Adhav_2020".
  64. 1 2 Charlie Bell (January 24, 2022). "Boyfriend jeans vs mom jeans: what's the difference, and which is best for your style?". Woman and Home Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on October 20, 2022. Retrieved October 20, 2022. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  65. ↑ Johnson, Paul. "What Are Straight Leg Jeans? (Explained)". Work Wear Command (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on October 20, 2022. Retrieved October 20, 2022. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  66. ↑ "The Difference Between Bootcut, Straight, Skinny, and Flare-Legged Jeans". Outfit Ideas HQ (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). July 23, 2014. Archived from the original on October 20, 2022. Retrieved October 20, 2022. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  67. ↑ "high-rise", The Fairchild Books Dictionary of Fashion, Fairchild Books, 2022, p. 75, ISBN 978-1-5013-6669-7, doi:10.5040/9781501365287.1334, archived from the original on October 26, 2023, retrieved June 24, 2023 Unknown parameter |url-status= ignored (help); Unknown parameter |chapter-url-access= ignored (help)
  68. ↑ "The Anatomy of a Trend: Y2K". blog.trendalytics.co (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). August 23, 2021. Archived from the original on October 20, 2022. Retrieved October 20, 2022. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  69. ↑ Jennings, Rebecca (April 6, 2021). "Low-rise jeans are back. Try not to scream.". Vox (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on October 20, 2022. Retrieved October 20, 2022. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  70. ↑ "Low rise jeans are back – and the lower the better". The Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). January 15, 2022. Archived from the original on October 20, 2022. Retrieved October 20, 2022. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  71. ↑ "How Low Can These Low-Rise Jeans Go?". Vogue (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). September 30, 2021. Archived from the original on October 20, 2022. Retrieved October 20, 2022. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  72. ↑ "10 Types Of Jeans Every Woman Should Have In Her Wardrobe". The Singapore Women's Weekly. 26 Oct 2021. Retrieved 7 April 2026.