James Weldon Johnson

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
James Weldon Johnson
Jamesweldonjohnson.jpg
photographed by Carl Van Vechten, 1932
Iṣẹ́ educator, lawyer, diplomat, songwriter, writer, anthropologist, poet, activist
Ọmọ orílẹ̀-èdè American
Literary movement Harlem Renaissance
Notable works Lift Ev'ry Voice and Sing”, “The Autobiography of an Ex-Colored Man

James Weldon Johnson (June 17, 1871 – June 26, 1938) je ara Amerika to je olukowe, oloselu, diplomat, olugbewo, oniroyin, akoewi, onimoeda-eniyan, oluko, agbejoro, ako-orin, ati alakitiyan awon eto araalu. Johnson je riranti daada fun ikowe re to je iwe itan-aeoko, ewi, ikojopo awon itan ibile. Oun ni omo African-American ojogbon akoko ni New York University. Leyin re o tun di ojogbon ninu ida litireso ati ikowe ni Fisk University.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]