Janet Omorogbe
Ìrísí
| Òrọ̀ ẹni | |
|---|---|
| Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
| Ọjọ́ìbí | 22 Oṣù Kọkànlá 1942 |
| Sport | |
| Erẹ́ìdárayá | Sprinting |
| Event(s) | 4 × 100 metres relay |
Janet Omorogbe (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kọkànlá ọdún 1942) jẹ́ Asáré orí páápá eléré ìje ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó kópa nínú dije ere ije mita 4 × 100 ti awọn obinrin ni Olimpiiki Igba Ooru ti ọdun 1968.[1]