Joan Baez
Joan Chandos Baez ( /baɪz/,[lower-alpha 1] es; ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹsàn án oṣù kínní ọdún 1941[3] jẹ́ ònkọrin, akọrin, olórin ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn, ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà[4] Àwọn orin rẹ̀ ló ma ń dálé ìrúnilọ́kàn-sókè tí ó ń bèrè fún ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn láwùjọ.[5] Ó ti tó ọgọ́ta ọdún tí Baez ti ń ṣeré ìta gbangba bọ̀, tí ó sì ti ṣe àwo orin tí ó ti lé ní ọgbọ̀n.
Orin Folk ni Baez ma ń kọ ní tirẹ̀, àmọ́, orin rẹ̀ ti ya sí oríṣiriṣi ọ̀nà lati 1960 tí a sì ti ń gbóòórùn orin ''rock'', ''country'' àti '' gospel'' nínú orin rẹ̀. Ó bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣe àwo orin rẹ̀ jáde láti ọdún 1960 tí ó sì tibẹ̀ di ìlúmọ̀ọ́ká.
Àwoborin rẹ̀ mẹ́ta àkọ́kọ́ tí ó pè ní: "Diamond & Rust" àti covers Phil Ochs gbogbo rẹ̀ ló pegedé lórí ìgbéléwọ̀n here record ne" Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé the Band's "The Night They Drove Old Dixie Down". Ó tún ṣe àwọn àwo orin kan pẹ̀lú àwọn ònkọrin míràn "Farewell, Angelina", "Love Is Just a Four-Letter Word", "Forever Young", "Here's to You", "Joe Hill", "Sweet Sir Galahad" àti "We Shall Overcome". Baez kọ orin mẹ́rìnlélógún ní ọdún 1969 níbi Woodstock Festival ó sì ti ń fojú sí òṣèlú àti ọ̀rọ̀ àwùjọ fún ọnọ́ tó ti pẹ́.[6] Wọ́n gba Baez wọlé sí àwùjọ Rock and Roll Hall of Fame ní ọjọ́ keje oṣù keje ọdún 2017.[7]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]<ref> tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/> tag was found.
- ↑ Baez, Joan (2009), And A Voice to Sing With: A Memoir, New York City: Simon & Schuster, p. 61,
I gave Time a long-winded explanation of the pronunciation of my name which came out wrong, was printed wrong in Time magazine, and has been pronounced wrong ever since. It's not "Buy-ezz"; it's more like "Bize," but never mind.
- ↑ Wells, J. C. (2000). "Baez 'baɪez; baɪ'ez —but the singer Joan Baez prefers baɪz". Baez 'baɪez; baɪ'ez —but the singer Joan Baez prefers baɪz. Harlow, England: Pearson Education Ltd..
- ↑ "UPI Almanac for Thursday, Jan. 9, 2020". United Press International. January 9, 2020. https://www.upi.com/Top_News/2020/01/09/UPI-Almanac-for-Thursday-Jan-9-2020/6871578415895/. "...singer Joan Baez in 1941 (age 79)"
- ↑ Baez, Joan (2024). When you see my mother, ask her to dance: poems. Boston: Godine. ISBN 978-1-56792-801-3.
- ↑ Jackson, Ernie. "Folk Guitarists". The Everything Guitar Book Joelma. F+W Publications Inc., 2007. Àdàkọ:ISBN?Àdàkọ:Page?
- ↑ Brown, Mick (September 15, 2009). "Joan Baez interview". The Daily Telegraph (London). https://www.telegraph.co.uk/culture/music/worldfolkandjazz/6173753/Joan-Baez-interview.html.
- ↑ "Inductees: Joan Baez". Rock & Roll Hall of Fame. Archived from the original on December 21, 2016. Retrieved December 20, 2016. Unknown parameter
|url-status=ignored (help)