Jump to content

Joana Nnazua Kolo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Joana Nnazua Kolo
Commissioner for Youth and Sports Development in Kwara State
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
October 2019
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Joana Nnazua Kolo

1993 (ọmọ ọdún 31–32)
AráàlúNigerian
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
EducationKwara State University
OccupationPolitician, Humanitarian

Joana Nnazua Kolo (tí wọn bí lọ́dún 1993) jẹ́ aṣenilááánú àti ọ̀dọ́ tó kéré jù lọ ní Nigeria, tó jẹ́ kọ̀míṣánnà fún ètò ọ̀dọ́ àti idagbasoke eré-ìdárayá ní Ìpínlẹ̀ Kwara. [1][2][3] A gbà wípé òun ni ọmọ Nigeria tó kéré jù lọ, lọ́mọdun mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n, tí wọ́n yàn sípò Kọ̀míṣánnà. Ó jẹ́ àkàwé gboyè nínú ìmọ̀ Library Science ti Kwara State University, ní Ìpínlẹ̀ Kwara State.[4][5][6]

Wọ́n yan Joana Nnazua lásìkò tí ó ṣì ń ṣe agùnbánirọ̀, National Youths Service Corps (NYSC) ní Ìpínlẹ̀ Jigawa níbi tí ó ti ń kọ́ àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ní ilé ẹ̀kọ́ Model Boarding Junior Secondary School Guri.[4][7]

Lọ́dún 2020, Ilé-iṣẹ́ ìwé - ìròyìn Guardian dárúkọ Joana lára àwọn gbajúmọ̀ obìnrin tó lágbára, làmìlaka julọ ní Nigeria nípa iṣẹ́ ìfifúnni àánú rẹ̀ tí ó ń ṣe àti ìpolongo fún ìṣèjọ̀ba tó dára, àti kọ̀míṣánnà tó kéré jù lọ listed as one of the "Top 100 Most Influential Women" by Guardian Newspaper, through her humanitarian, community development and advocacy for good governance as the youngest commissioner in Nigeria.[8]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "26 Years Old Others Tip as Commissioners in Kwara State". TheNationOnlineNG. Retrieved November 7, 2020. 
  2. "Abulrazaq and His 26 year old Commissioner". PMNewsNigeria. Retrieved November 7, 2020. 
  3. "26 year old Joana Nnazua Kolo Appointed as Commissioner in Kwara". TheCableNG. Retrieved November 7, 2020. 
  4. 4.0 4.1 "26 year old Joana Kolo Appointed as Kwara State Youth Sports Commissioner". PunchNG. Retrieved November 7, 2020. 
  5. "26 year old four other women make kwaras first cabinet". VanguardNGR. Retrieved November 7, 2020. 
  6. "Joana Nnazua Kolo: Who be di 26 year old NYSC member wey make Kwara Commissioner nominee list". BBC Pidgin. Retrieved November 7, 2020. 
  7. "26-year-old Joana Kolo appointed as Kwara youth commissioner". TodayNG. Retrieved November 7, 2020. 
  8. "100 Most Inspiring Women in Nigeria 2020". GuardianNG. Retrieved November 7, 2020.