John Ene Okon
Ìrísí
| Personal information | |||
|---|---|---|---|
| Ọjọ́ ìbí | 15 Oṣù Kẹta 1969[1] | ||
| Ọjọ́ aláìsí | 15 March 2016 (ọmọ ọdún 47) | ||
| Ibi ọjọ́aláìsí | Calabar, Nigeria | ||
| Playing position | Midfielder | ||
| Senior career* | |||
| Years | Team | Apps† | (Gls)† |
| Acada United F.C. | |||
| Calabar Rovers | |||
| BCC Lions | |||
| Akwa United | |||
| National team | |||
| 1987 | Nigeria U-20 | ||
| 1992 | Nigeria | ||
| Teams managed | |||
| –2016 | Calabar Rovers | ||
| * Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). | |||
John Ene Effe Okon (Ọjọ́ karùndínlógún oṣù kẹta ọdún 1969 sí ọjọ́ karùndínlógún oṣù kẹta ọdún 2016) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Iṣẹ́ kárí ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó jẹ́ ara ẹgbẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Nàìjíríà nínú ìdíje Ayẹyẹ FIFA Àgbáyé fún Àwọn Ọ̀dọ́ ti ọdún 1987 àti Ife awọn Orílẹ̀-èdè Áfíríkà tí ó parí ní ipò kẹta ní ọdún 1992 Ife awọn Orílẹ̀-èdè Áfíríkà .
Ìgbésí ayé ara ẹni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ikú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Okon kú lẹ́yìn àìsàn kúkúrú kan ní oṣù kẹta ọdún 2016. Ó jẹ́ olùkọ́ni Calabar Rovers nígbà náà.
Títí di ìgbà ikú rẹ̀, ó tún jẹ́ olùkọ́ni Ẹgbẹ́ ere-idaraya Eastside, ẹgbẹ́ àwùjọ àti àwọn tí kìí ṣe ti iṣẹ́ ajé tí ó wà ní Calabar tí wọ́n ń gbìyànjú láti dá àjọṣepọ̀ sílẹ̀ láàrín àwọn ọ̀dọ́mọdé láti onírúurú ẹ̀ka ìgbésí ayé nípasẹ̀ eré ìdárayá.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Page Àdàkọ:Reflist/styles.css has no content.
- ↑ John Ene Okon - FIFA competition record