Joy Udo-Gabriel
Ìrísí
| Òrọ̀ ẹni | |
|---|---|
| Ọjọ́ìbí | 2 Oṣù Kẹfà 1999 Abia State, Nigeria[1] |
| Ẹ̀kọ́ | University of Lagos |
| Height | 1.60 m[2] |
| Weight | 63 kg |
| Sport | |
| Erẹ́ìdárayá | Athletics |
| Event(s) | 100 metres, 200 metres |
| Club | Unattached |
| Coached by | Feyi Shayo Daramola Udoh (2021–) |
Joy Udo-Gabriel (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejì oṣù kẹfà ọdún 1999) jẹ́ Eléré ìje asáré orí páápá ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. [3] Ó gba àmì-ẹ̀yẹ idẹ nínú ìdíje oní 100 mítà ní African Championships ti ọdún 2018, àmì-ẹ̀yẹ idẹ kan níbi ìdíje tí 4 × 100 mítà relay ní Commonwealth Games ti ọdún 2018 àti àmì-ẹ̀yẹ wúrà kan nínú 4 x 100 mítà relay ní African Games ti ọdún 2019. [4]
Akọsílẹ̀ àwọn eré ìje
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]| Gégébí Asoju fún | |||||
|---|---|---|---|---|---|
| 2018 | Commonwealth Games | Gold Coast, Australia | 9th (sf) | 100 m | 11.53 |
| 3rd | 4 × 100 m relay | 42.75 | |||
| African Championships | Asaba, Nigeria | 3rd | 100 m | 11.58 | |
| 1st | 4 × 100 m relay | 43.77 | |||
| 2019 | World Relays | Yokohama, Japan | 17th (h) | 4 × 100 m relay | 45.07 |
| African Games | Rabat, Morocco | 4th | 100 m | 11.44 | |
| 1st | 4 × 100 m relay | 44.16 | |||
| World Championships | Doha, Qatar | 10th (h) | 4 × 100 m relay | 43.05 | |
| 2022 | World Championships | Eugene, United States | 4th | 4 × 100 m relay | 42.22 |
Akọsílẹ̀ Àwọn àkókò eré ìje rẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- 100 metres – 11.34(+0.3 m/s, yaba tech MOC Grand Prix 2021)
- 200 metres – 23.92 (-0.8 m/s, yabatech MOC Grand Prix 2021)
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Making of Champs profile". Retrieved 12 September 2018.
- ↑ "2018 CWG bio". Retrieved 1 May 2018.
- ↑ IAAF profile for Joy Udo-Gabriel
- ↑ "2019 African Games – Athletics – Results Book" (PDF). Archived from the original (PDF) on 1 September 2019. Retrieved 7 September 2019. Unknown parameter
|url-status=ignored (help)