Jump to content

Kọlọkọlọ

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kolokolo ni èérún yinyin

Kọlọkọlọ (kọ́lọ́kọ́lọ́) je ẹranko pèlú ogbon. Won kere ati won ni ẹsẹ mẹta, won je ọdẹ dara gidigan. Àwọn kọlọkọlọ, won le sáré kiakia ati won le ri dada nigba ẹranko gbékuro, sùgbón, ti o ba ẹranko won ma duro, ati won ko gbékuro, nigbamiiran, àwon kolokolo, won ko ma ri won àwon òǹkòwé ti ri be. Àwọn kolokolo, won le sise ni ale ati ni osan. Àwon okere, won je afoju ni ale, sùgbón won le sise ni osan. Àwon kolokolo, won ni ebun, nitori won le sise ati gbékuró, ni gbogbo àsikò. O je àwon iyipada ti àwon kolokolo ni, àwon kolokolo ni aarin ti iris ti ojú won, o je ge ni inaro súgbón, fun àwọn ẹranko miiran ni aarin ti iris ti ojú won o je roboto dabi rogodo. Nitori naa, àwọn kọlọkọlọ, won ni anfani ti o poju àwọn ẹranko miiran. Nitori naa, nitori ojú ti kolokolo je dabi bee, won le ni akoso lori iye ti imolè ti o ma wolè ninu ojù won. Nitori naa, won le dẹ ni orisirisi ipo ti imolè.[1]

Àwọn kọlọkọlọ le sáré kiakia, won le sáré pèlú iyara ti meji-le-aadorin kilomita ni wakati ọkan, (72km/w).[2]

àwọn kọlọkọlọ ni èérún yinyin
Kọlọkọlọ
Kọlọkọlọ, o ni ogbon ti o tobi gan
  1. https://www.wildlifeonline.me.uk/animals/article/red-fox-senses
  2. https://www.livescience.com/27168-foxes.html