Kiniun ti òkè ati eranko Cougar je eranko kanna, won je dabi akunrin re kiniun, sugbon o n gbé ni tabi lori òkè. Kiniun ti òkè ko ni gọgọ ati ko le bu ramuramu tabi pariwo dabi kiniun.[1]