Kubrat Owolabi
| Òrọ̀ ẹni | |
|---|---|
| Ọmọorílẹ̀-èdè | |
| Ọjọ́ìbí | 21 Oṣù Kínní 1967 |
Kubrat Owolabi (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kìíní ọdún 1967) jẹ́ obìnrin tí ó ti ń gbá bọ́ọ̀lù tẹ́nìsì orí tábìlì ní àgbáyé láti Nàìjíríà àti England tẹ́lẹ̀ . [1]
Iṣẹ́ Gégébí Agbábóólù Tẹ́nísì orí tábìlì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó ṣojú fún England ní 2000 World Team Table Tennis Championships (ìṣẹ̀lẹ̀ ẹgbẹ́ àwọn obìnrin Corbillon Cup) pẹ̀lú Helen Lower àti Linda Radford.[2] Ó jẹ́ àṣàṣorí ẹnìkọ̀ọ̀kan tẹ́lẹ̀ ti African Table Tennis Championships ọdún 1988, olùṣẹ́gun méjì-méjì ní ìgbà méjì nígbà tí ó ń dúró fún Nigeria àti olùgba wúrà nínú méjì-méjì adàlú nígbà tí ó ń dúró fún Nigeria at the 1987 All-Africa Games.[citation needed]
Ó jáwé olú borí ni igba èmejì ni orílẹ̀-èdè England ní ìgbà méjì pẹ̀lú Andrea Holt àti Nicola Deaton ní English National Table Tennis Championships. Ó tún díje nínú ìṣẹ̀lẹ̀ ẹnìkọ̀ọ̀kan àwọn obìnrin ní 1988 Summer Olympics.[3]
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Friday Photos 79". Table Tennis England. Archived from the original on 4 December 2020. Retrieved 6 September 2018. Unknown parameter
|url-status=ignored (help) - ↑ "Table Tennis: Eckersley in open triumph". The Argus. 7 December 2000.
- ↑ "Kuburat Owolabi". Olympedia. Retrieved 14 July 2020.