Kwara State Polytechnic

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Kwara State Polytechnic
Established1973 (1973)
TypePublic
RectorMas'ud Elelu[1]
LocationIlorin, Kwara State, Nigeria
CampusUrban
Websitekwarastatepolytechnic.edu.ng
Fáìlì:Kwara State Polytechnic (logo).jpg

Kwara State Polytechnic jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo-nìṣe ilẹ̀ Nàìjíríà  tí olórí ìjọba ológun ìpínlẹ̀ Kwara tẹ́lẹ̀ Ọ̀gágun  Col. David Bámigbóyè dá sílẹ̀ ní ọdún 1973 ní wọ́n kéde rẹ̀ lẹ́yìn tí wọ́n ti pinu láti dá ilé-ẹ̀kọ́ náà sílẹ̀ sí ìpínlẹ́̀ Kwara lọ́dún 1971.[2] Ilé-ẹ̀kọ́ náà ló wà ní Ìlọrin tí ọ́ jẹ́ olú ìlù ìpínlẹ̀ náà. Ilé-ẹ̀kọ́ náà kọ́kọ́ gba àwón ọgọ́rùún ó lé mẹ́wàá akẹ́kọ̀ọ́ wọlé nígbà àkọ́kọ́ fún sáà ètò ẹ̀kọ́ ọdún náà nígbà tí wọ́n ń pèsè ètò ẹ̀kọ́ National Diploma àti Higher National Diploma fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọn gbogbo.[3]

Ẹ tún lè wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • List of polytechnics in Nigeria

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Akinpelu, Kehinde (September 1, 2015). "Kwara Poly to showcase own products". Daily Times Nigeria (Ilorin). http://dailytimes.com.ng/kwara-poly-showcase-products/. Retrieved 12 September 2015. 
  2. Empty citation (help) 
  3. "Kwara Poly disowns suspected cultists". The Guardian. August 18, 2015. http://www.ngrguardiannews.com/2015/08/kwara-poly-disowns-suspected-cultists/. Retrieved 12 September 2015.