Jump to content

Lawrencia Mallam

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lawrencia Laraba-Mallam
Minister of Environment
In office
5 March 2014 – 29 May 2015
ÀàrẹGoodluck Jonathan
Arọ́pòAmina Mohammed
National president, Catholic Women Organization (CWO)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíNigeria
AráàlúNigeria
(Àwọn) olólùfẹ́Pius Mallam

Lawrencia Laraba-Mallam jẹ́ Mínísítà  fún Àyíká tàbí agbègbè níleNàìjíríà láti  ọdún 2014 si 2025. Ó wà lára àwọn Mínísítà mọ́kànlá tí Ààrẹ Goodluck Jonathan gbà sénu isẹ́ ní oṣù Kẹta ọdún 2014.[1][2][3][4][5][6][7] Lẹ́yìn tí ó kúrò nípò ni Amina Muhammed rọ́pò rẹ.[8] Kí wọ́n tó yàn án sí pò, ó fi ìgbà kàn jẹ́ Ààrẹ Hgboogbò fún Ẹgbẹ́ Àwọn Obìnrin Catholic (CWO) .[9]

Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Mínísítà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

NÍgbà ìṣè ìjọ̀ba rẹ̀, Wọ́n fi òǹtẹ̀ lu National Great Green Wall (GGW) láti pese legal architecture fún àwọn ìṣè àkànṣe tí ó jẹ́ mọ́ àwọn àgbègbè àti ohun tí ó jọ mọ́ ìṣòro àyíká wa. Èyí ló mú kí Ààrẹ fi owó iyebíye Bílíọ́nù mẹ́rìndínlógún láti lè ṣe iṣẹ́ náà. [10]

O sọ̀rọ̀ lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n fi Gas Flare Tracker Website tí Ẹ̀ka kan ni ilu United Kingdom Department for International Development, sọ bí gáàsí ṣe fọ́ká sí Ìpínlẹ̀ Niger Delta ni Oṣù Kejìlá ní ọdún 2014, Mallam je kí ó yé wa pé, tí a bá lọ sí àwọn àperò lókè òkun ni àwọn ìlú ibòmíràn, Wọ́n a má sọ fún wa nípa bí àwọn gáàsí ṣe fọ́ká sínú afẹ́fẹ́, ṣùgbọ́n a kò mọ. Ṣùgbọ́n láti òní lọ, a kò ní sàìmọ̀ gbogbo èyí kọ, a ó má sọ iye gáàsí tí ó wà ní afẹ́fẹ́ pẹ̀lú tracker náà. [11]

Ìjínigbé àti Ìdásílẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọjọ́ kẹta Oṣù Kejìlá, ọdún 2016, Wọ́n jí Lawrencia àti Ọkọ rẹ̀ tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́taléàádọ́rin tí orúkọ ń jẹ́ Pius Mallam, ní agbègbè Jere ni òpópónà Kaduna sì Abuja. [12] Àmọ́, Àwọn tí wọ́n jí wọn gbé padà fi won sílè lẹ́yìn ọjọ́ méjì tí wọ́n gbé wọn.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Gusau, Obanikoro to run Nigeria's defence ministry". PM News. March 5, 2014. https://pmnewsnigeria.com/2014/03/05/gusau-obanikoro-to-run-nigerias-defence-ministry/. 
  2. Andrews, Jaiyeola (March 5, 2014). "Nigeria: Jonathan Drops Bolaji Abdullahi, Swears in 11 New Ministers". All Africa. Lagos: This Day. Retrieved September 23, 2024. 
  3. Chima, Amechi B. (March 5, 2014). "Breaking News:President Jonathan Sacks Sports Minister". Modern Ghana. https://www.modernghana.com/amp/nollywood/27182/breaking-newspresident-jonathan-sacks-sports-minister.html. 
  4. Adesulu, Dayo (October 9, 2014). "Dons brainstorm on alternative energy as minister flags off Enville seminar". Vanguard Nigeria. https://www.vanguardngr.com/2014/10/dons-brainstorm-alternative-energy-minister-flags-enville-seminar/. 
  5. "Jonathan names Gasau, Obanikoro, Boni Haruna as ministers". The Nigerian Voice. January 22, 2014. https://www.thenigerianvoice.com/news/135346/jonathan-names-gasau-obanikoro-boni-haruna-as-ministers.html. 
  6. Mustapha, Olusegun (March 6, 2014). "Aliyu Gusau ne Ministan Tsaro" (in ha). Aminiya. https://aminiya.ng/aliyu-gusau-ne-ministan-tsaro/. 
  7. Heath-Brown, Nick, ed (February 7, 2017) (in en) (ebook). The Statesman's Yearbook 2016. Palgrave Macmillan UK. p. 918. ISBN 9781349578238. https://books.google.com/books?id=lDkUDgAAQBAJ&dq=lawrencia+laraba+mallam&pg=PA918. Retrieved September 23, 2024. 
  8. "Ex-minister, husband released after 48 hours in captivity". TheCable. October 5, 2016. https://www.thecable.ng/ex-minister-husband-released-48-hours-captivity/amp/. 
  9. "What becomes of Jonathan's women?". TheNation. April 5, 2015. https://thenationonlineng.net/what-becomes-of-jonathans-women/. 
  10. "Council Approves Draft Bills To Boost Transportation". Channels Television. February 11, 2015. https://www.channelstv.com/2015/02/11/council-approves-draft-bills-boost-transportation/amp/. 
  11. Stein, Chris (November 27, 2014). "Satellite Tracker Throws Light on Gas Flaring in Nigeria". VOA. https://www.voanews.com/a/satellite-tracker-throws-light-on-gas-flaring-in-nigeria/2536982.html. 
  12. "Gunmen kidnap ex-minister, husband". TheCable. October 4, 2016. https://www.thecable.ng/breaking-gunmen-kidnap-former-environment-minister-husband/amp/.