Lilo Agbara Itansan Oorun (Photosynthesis)
Ìrísí

Lilo Agbara Itansan Oorun je nigba awon ohun ogbin lo agbara lati orun, omi, kárbónì ọlọ́ksíjínìméjì (carbon dioxide) tabi karboni ategun-meji lati da oksijin tabi ategun ati agbara ni irisi ti suga.[1]