Lovelyn Orji-Ben
| Òrọ̀ ẹni | |||||||||||||||||||||||
|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
| Orúkọ kíkúnrẹ́rẹ́ | Lovelyn Orji-Ben | ||||||||||||||||||||||
| Ọmọorílẹ̀-èdè | |||||||||||||||||||||||
| Ọjọ́ìbí | 3 Oṣù Kejìlá 1979 Nigeria | ||||||||||||||||||||||
| Sport | |||||||||||||||||||||||
| Erẹ́ìdárayá | Judo | ||||||||||||||||||||||
| Event(s) | 48 kg | ||||||||||||||||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
| |||||||||||||||||||||||
Lovelyn Orji-Ben (ojoibi je Ọjọ́ kẹta, oṣù Kejìlá ọdún 1979) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan tó dije nínú ìdíje 48 kg fún àwọn obìnrin. Ó gba ẹ̀bùn idẹ ní Pan African Games ti ọdún 1999 àti àmì ẹ̀yẹ idẹ méjì ní African Judo Championships ní ọdún 1997 àti 2000. [1]
Iṣẹ́ eré ìdárayá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ìdíje Judo ti ilẹ̀ Áfíríkà, Lovelyn ti gba àmì ẹ̀yẹ méjì lápapọ̀. Èkíní ni ìdíje Judo ti ilẹ̀ Áfíríkà ti ọdún 1997 tí a ṣe ní Casablanca, Morocco. Lovelyn kópa nínú ìdíje 48 kg níbi tí ó ti gba àmì ẹ̀yẹ idẹ. Èkejì ní ìdíje Judo ti ilẹ̀ Áfíríkà ti ọdún 2000 tí a ṣe ní Algiers, Algeria níbi tí ó ti gba àmì ẹ̀yẹ fàdákà pẹ̀lú nínú ìdíje 48 kg. [2] [3]
Ní ọdún 1999, tí wọ́n ṣe awọn eré gbogbo-Afíríkà ní Johannesburg, South Africa, ó gba àmì ẹ̀yẹ idẹ lẹ́yìn tó kópa nínú ìdíje méjídínláàdọ́ta kg. [4]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Lovelyn Orji-Ben, Judoka, JudoInside". www.judoinside.com. Retrieved 2020-11-20.
- ↑ "African Championships Casablanca, Event, JudoInside". judoinside.com. Retrieved 2020-11-20.
- ↑ "African Championships Algier, Event, JudoInside". judoinside.com. Retrieved 2020-11-20.
- ↑ "African Games Johannesburg, Event, JudoInside". www.judoinside.com. Retrieved 2020-11-20.