Mọ́sà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Mọ́sà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn omi lẹgbẹ óńjẹ ìbílẹ̀ ní ilẹ̀ Nàìjíríà. [1]

Ìwúlò Mọ́sà gẹ́gẹ́ bí ọ́ńjẹ ìbílẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní pàtó, jíjẹ ni mọ́sà wà fún. Àmọ́,àwọn ènìyàn ma ń lòó fún sàráà ṣíṣe fún àwọn Òkú ọ̀run, nípa fífún àwọn atẹ́wọ́ gbọrẹ. Wọ́n tún ma ń lo òun àti Àkàrà láti fi ṣọdún Egúngún. [2][3]

Bí wọ́n ṣe ń jẹ Mọ́sà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n ma ń jẹ mọ́sà pẹ̀lú Ṣúgà, Ẹ̀wà àti onírúurú ohun mímu gbogbo tí ó bá wuni.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Recipe of the week – Plantain Mosa". Lagosmums. 2018-03-23. Retrieved 2019-12-28. 
  2. "Plantain Mosa (Plantain Puffs)". All Nigerian Recipes. 2019-03-25. Retrieved 2019-12-28. 
  3. "Mosa (Ghanian Tatale) and Lemony Palm oil vegetable sauce". Dooney's Kitchen – Promoting and Redefining New Nigerian Food. 2019-10-11. Archived from the original on 2019-12-28. Retrieved 2019-12-28.