Mọsko

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Mọsko
Red Square
Mọsko is located in Russia
Mọsko
Àwọn ajọfọ̀nàkò: 55°45′08″N 37°35′56″E / 55.75222°N 37.59889°E / 55.75222; 37.59889
Ìjọba
 - Mayor
Ààlà
 - Iye àpapọ̀ 1,081 km2 (417.4 sq mi)
Olùgbé
 - Iye àpapọ̀ 12,382,754

Mọsko ni olú-ìlú Rọ́síà. Ìlú nlá ni. Orí odò Moskva ni ó wà. Odún 1918 ni ó di olú-ìlú USSR nígbà tí wón gbé olú-ìlú yìí kúrò ní Leningrad. Moscow ni ìlú tí ó tóbi jù ní Rósíà. Oun ni ó wà ní ipò kefà tí a bá ní kí á ka àwon ìlú tí ó tóbi ní ilé-ayé. Ìlú tí ó léwà ni Moscow. Uspenki Cathedral tí ó wà ní ibè ni wón ti máa n dé àwon tsar (àwon olùdarí Rósíà) lade láyé àtijó. Ibè náà ni Arkhangelski tí wón ti n sin wón wà. Ilé-isé àti Ilé-èko pò ní ibè Lára àwon ilé-èkó ibè ni. Lomonosov University tí ó jé University ìjoba wa ni ibe. Orí òkè Lenin ni wón kó o sí òun sì ni University tí ó tóbi jù ní Rósíà. Ibè náà ni USSR Academy of Sciences wa. Mùsíómù, ilé-ìkàwé àti tíátà wà níbè. Àwon Bolshoi Theatre and Ballet, the State Symphony Ochestra àti the State Folk Dance Company tí ó wà ni Moscow gbayì gan-an ni.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]