Magalan Ugochukwu
Ìrísí
Page Module:Infobox/styles.css has no content.
| Magalan Ugochukwu Awala.jpg Magalan playing for Chittagong Abahani in 2019 | |||
| Personal information | |||
|---|---|---|---|
| Orúkọ | Magalan Ugochukwu Awala | ||
| Ọjọ́ ìbí | 20 Oṣù Kẹfà 1990 | ||
| Ibi ọjọ́ibí | Kaduna, Nigeria | ||
| Ọjọ́ aláìsí | 26 June 2024 (ọmọ ọdún 34)[1] | ||
| Ibi ọjọ́aláìsí | Satkhira, Bangladesh | ||
| Ìga | 1.80 m | ||
| Playing position | Striker | ||
| Youth career | |||
| 2006–2008 | Moderate Stars Academy | ||
| 2008–2009 | Hapoel Rishon LeZion | ||
| Senior career* | |||
| Years | Team | Apps† | (Gls)† |
| 2009–2010 | Hapoel Rishon LeZion | 30 | (6) |
| 2010–2011 | Hapoel Herzliya | 20 | (6) |
| 2011–2012 | Maccabi Ironi Bat Yam | 14 | (4) |
| 2012–2013 | Sektzia Ness Ziona | 32 | (6) |
| 2013 | Hapoel Rishon LeZion | 6 | (0) |
| 2014–2015 | Beitar Tel Aviv Ramla[2] | 1 | (0) |
| 2017–2018 | Muktijoddha Sangsad | 10 | (6) |
| 2018–2019 | Chittagong Abahani | 12 | (3) |
| 2021–2023 | Brothers Union | 12 | (2) |
| * Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 22 July 2023. † Appearances (Goals). | |||
Magalan Ugochukwu Awala tí wọn bí ní ọjọ́ ogún oṣù Okudu odun 1990 ó sì kú ní ọjọ́ keridinlogbon oṣù Okudu ọdún 2024) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ẹni tó gbá bọ́ọ̀lù kẹ́yìn fún Brothers Union ní Bangladesh Premier League.
Iṣẹ́ ọwọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awala bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú Ilé-ẹ̀kọ́ awọn Ìràwọ̀ Dídára, ó sì dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ kan ní Ísírẹ́lì ní ọdún 2008. Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó dára jùlọ nínú àwọn agbábọ́ọ̀lù tó dára jùlọ ní Israel league ní oṣù Keje ọdún 2010 pẹ̀lú Hapoel Ironi Rishon LeZion.[3]Lẹ́yìn ọdún méjì pẹ̀lú Hapoel Ironi Rishon LeZion, ó dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ Liga Leumit Hapoel Herzliya.[4]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "সাতক্ষীরায় ম্যাচে হৃদরোগে আক্রান্ত, পরে মৃত্যু নাইজেরিয়ান ফুটবলারের". channelionline.com (in Bengali). 26 June 2024. Retrieved 26 June 2024.
- ↑ Player profile Archived 2017-01-10 at the Wayback Machine. at IFA website
- ↑ כובש בראשל"צ, חולם על ארסנל on myynet.co.il
- ↑ "The Official Website of Segra Football - SegraFootball.com - Our Players". www.segrafootball.com. Retrieved 6 February 2018.