Jump to content

Makonde

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Makonde Èdè Bàntú ni wón ń so, wón sì wà ní Tanzania àti Mozambique. Àwon Mwera, Makua àti Mabia ni àwon alámùúlégbé won. Isé won sì ni àgbè, ode àti igbá fínfín. Abúlé kòòkan ni ó sì ní baálè tirè, àwon alálè ni wón sì máa ń bo bíi Olórun ti won.