Jump to content

Mao Zedong

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mao Zedong
毛泽东
1st Chairman of the Communist Party of China
In office
1943–1976
DeputyLiu Shaoqi
Lin Biao
Zhou Enlai
Hua Guofeng
AsíwájúZhang Wentian
(As General Secretary)
Arọ́pòHua Guofeng
1st Chairman of the People's Republic of China
In office
September 27, 1954 – April 1959
PremierZhou Enlai
DeputyZhu De
AsíwájúPosition Created
Arọ́pòLiu Shaoqi
1st Chairman of the CPC Central Military Commission
In office
1954–1976
AsíwájúPosition Created
Arọ́pòHua Guofeng
1st Chairman of the CPPCC
In office
October 1, 1949 – December 25, 1954
AsíwájúPosition Created
Arọ́pòZhou Enlai
In office
December 25, 1954 – September 9, 1976 (honorary)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1893-12-26)26 Oṣù Kejìlá 1893
Shaoshan, Xiangtan, Hunan, Qing Dynasty
Aláìsí9 September 1976(1976-09-09) (ọmọ ọdún 82)
Beijing, People's Republic of China
Ọmọorílẹ̀-èdèChinese
Ẹgbẹ́ olóṣèlúCommunist Party of China
(Àwọn) olólùfẹ́Luo Yixiu (1907–1910)
Yang Kaihui (1920–1930)
He Zizhen (1930–1937)
Jiang Qing (1939–1976)
Mao Zedong
Simplified Chinese 毛泽东
Traditional Chinese 毛澤東
Hanyu Pinyin Máo Zédōng
Chairman Mao
Chinese 毛主席

Mao Zedong, o tun se e ko bi Mao Tse-tung Zh-Mao_Zedong.ogg pipe (December 26, 1893 – September 9, 1976), je ara Saina Han to je olujidide, asero oloselu ati olori egbe kommunisti leader. O siwaju Orile-ede Olominira Awon Ara Saina (PRC) lati igba idasile re ni 1949 titi di ojo iku re ni 1976. Awon ero re lori Isemarksi-Iselenin, ona ijagun ologun ati awon iru eto Kommunisti re lapapo la mo si Isemao.