Mariam Eniola Bolaji
Ìrísí
Mariam Eniola Bolaji (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù Kẹsán ọdún 2005) je elere para-badminton omo Naijiria. Ó wà ní ipò kìíní ní àgbáyé nínú akọsílẹ̀ ẹ̀ka SL3 Para Badminton World Federation . Ó kópa nínú ìdíje Paralympics ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn ọdún 2024, níbi tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ idẹ nínú ìdíje SL3 àwọn obìnrin .
Ó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà àkọ́kọ́ tó gba àmì ẹ̀yẹ nínú eré ìdárayá náà ní Olympics/ Paralympics, ó gba Idẹ nínú ìdíje SL3 àwọn obìnrin nínu eré ìdárayá na ní Paris. Ìjáwé olúborí rẹ̀ ló jẹ́ àmì-ẹ̀yẹ àkọ́kọ́ fún Nàìjíríà ní Paris Paralympics.


Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Leaks, The Daily (2024-09-02). "Mariam Bolaji becomes first African to win badminton medal". The Daily Leaks (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-09-03.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]