Mark Strong
Appearance
Mark Strong | |
---|---|
Strong ní ọdún 2019 | |
Ọjọ́ìbí | Marco Giuseppe Salussolia 5 Oṣù Kẹjọ 1963 London, England |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 1989–present |
Olólùfẹ́ | Liza Marshall |
Àwọn ọmọ | 2 |
Mark Strong (orúkọ àbísọ rẹ̀ ni Marco Giuseppe Salussolia;tí a bí ní ọjọ́ Kàrún-ún oṣù kẹjọ ọdún 1963) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Britian tí ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Prince Septimus ní Stardust (2007), Archibald ní RocknRolla (2008), Lord Henry Blackwood nínú Sherlock Holmes (2009), Frank D'Amico nínú Kick-Ass (2010), Jim Prideaux nínú Tinker Tailor Soldier Spy (2011), Sinestro in Green Lantern (2011), George in Zero Dark Thirty (2012), Major General Stewart Menzies nínú The Imitation Game (2014), Merlin nínú Kingsman: The Secret Service (2014) àti Kingsman: The Golden Circle (2017), Dr. Thaddeus Sivana nínú Shazam! (2019) àti Shazam! Fury of the Gods (2023), àti gẹ́gẹ́ bi John nínú Cruella (2021).