Mary McLeod Bethune

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Mary Jane McLeod Bethune
Bethune42h.jpg
Mary Jane McLeod Bethune, je yiya ni foto latowo Carl Van Vechten, April 6, 1949
Born Oṣù Keje 10, 1875(1875-07-10)
Mayesville, South Carolina, United States
Died Oṣù Kàrún 18, 1955 (ọmọ ọdún 79)
Daytona Beach, Florida, United States
Occupation Oluko, Oluda, Olori Isakitiyan Eto Araalu awon omo Afrika Amerika
Spouse(s) Albertus Bethune, alaisi ni 1918

Mary Jane McLeod Bethune (July 10, 1875 – May 18, 1955) je oluko ati alakitiyan eto araalu ara Amerika to gbajumo fun didasile ile-eko fun awon omo Afrika Amerika ni Daytona Beach, Florida, to pada di Bethune-Cookman University ati fun jije oludamoran si Aare Franklin D. Roosevelt.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]