Jump to content

Maureen Gwacham

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Maureen Chinwe Gwacham
Member, House of Representatives from Anambra State
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
2023
ConstituencyOyi/Ayamelum
Àwọn àlàyé onítòhún
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Grand Alliance
OccupationPolitician, businesswoman

Maureen Chinwe Gwacham jẹ́ obìnrin oníṣòwò àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n yàn sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin orílẹ̀-èdè kẹwàá láti sójú Oyi/Ayamelum ni ilé ìgbìmò aṣòfin àgbà ti ìpínlẹ̀ Anambra lábé ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Grand Alliance (APGA). [1] [2] [3] Gwacham ni ìbò 15,299 lati ṣẹgun oludije ti Young Progressive Party (YPP), Charles Uchenna Okafor, ti o gba ibo 13,332. Oludije People's Democratic Party (PDP) ati ọmọ ile igbimọ aṣofin tẹlẹ gba ibo 6,912 nìkan. [4] Ìdìbò ti Gwacham ni awọn oludije ẹgbẹ YPP, PDP ati Labour Party takò ní ile ẹjọ kò tẹ mi lọrun. [5]

Gwacham jẹ ọkan nínú awọn obìnrin 17 nìkan ti a yan si Apejọ Orilẹ-ede awọn aṣòfin kẹwàá ti awọn ọmọ aṣòfin kékeré àti àgbà (senato) fun orílè-èdè Nàìjíríà jẹ 469. [6] [7]

  1. https://von.gov.ng/apga-candidate-gwacham-wins-house-of-rep-oyi-ayamelum-constituency/
  2. https://pmexpressng.com/2023-lady-gwacham-indicates-desire-to-represent-oyi-ayamelum-federal-constituency/
  3. https://www.thexpressng.com/2023-anambra-hotelier-lady-maureen-declares-to-contest-oyi-ayamelum-federal-constituency-election/
  4. https://www.blueprint.ng/apga-defeats-pdp-wins-2-reps-seats-in-anambra/
  5. https://www.thisdaylive.com/index.php/2023/04/09/anambra-tribunal-receives-31-nassembly-election-petitions/
  6. https://www.thecable.ng/did-you-know-women-got-only-3-5-of-national-assembly-seats-declared-so-far
  7. https://www.tori.ng/news/229788/meet-the-17-women-who-made-it-to-10th-national-ass.html