Muyiwa Ademola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Muyiwa Ademola (a bi ni ojo kerindinlogbon, osu kinni odun 1971) jé ogbontarigi osere ati oludari sinima agbelewo omo Yoruba lorílé èdè Nàìjíríà. Ni odun 2008, a yan fun ami eye Africa Movie Academy fun osere to dayato ninu awon osere abinibi.[1]

Ibere Aye[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bi Muyiwa Ademola ni 26 January 1971 ni ilu Abeokuta, ti ise olu ilu Ogun State ni Guusu Nàìjíríà.[2]. O si lọ si St. David's High School ni Molete ni Ibadan ibi ti o ti gba West Africa Secondary School Certificate.[3]. O tesiwaju si University of Ibadan ibi ti o ti gba Bachelor of Education degree ni Eko agba[4]

Itan Ise[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

O darapo mo ajo egbe oni fiimu ni Nàìjíríà nipasẹ Charles Olumo, ti opolopo mo si Agbako ni ilu, Abeokuta.[5]. O pade oludari fiimu ti a mo si S.I Ola ti o kọ ọ didari ere fiimu ni gbóògì.[6]. O bẹrẹ ere sise ni kikun ni 1995 nigbati o gbe fiimu re akoko jade ti akole re nje Àṣìṣe. Ise yi jade lati ile ise Dibel ti o owo Generating set. Lati 1995, o ti gbe opolopo fiimu Yorùbá jade.[7] Ni January 2013, iroyin jade wipe o ní buburu ijamba to fere yorisi iku re.[8]

Àwon fiimu tí ó ti kópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Asise (1995)
  • Ile
  • Ori
  • Ami Ayo
  • Fimidara Ire[9]
  • IranseAje
  • "J J

E tun wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • 4th Africa Movie Academy Awards

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]