Jump to content

Oúnjẹ Shiro

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Shiro
Shiro served upon injera is a staple food of Eritrean and Ethiopian cuisine
TypeStew
Course
Place of origin
Region or stateEast Africa
Main ingredients
VariationsShiro fit-fit
Food energy
(per 100 g serving)
353 kcal (1478 kJ)[1]
Nutritional value
(per 100 g serving)
Protein22.3 g
Fat4.8 g
Carbohydrate50 g
Àdàkọ:Wikibooks-inline 
Chickpeas being prepared for grinding into flour for shiro tsebhi

Shiro, èyí tí a tún mọ̀ sí shiro wat, tàbí tsebhi shiro, ó jẹ́ ọbẹ̀ tí wọ́n máa ń fi jẹ oúnjẹ ọ̀sán àti oúnjẹ alẹ́, èyí tí a le tọpa rẹ̀ Àríwá orílẹ̀-èdè Ethiopia àti gúúsù Eritrea. Ó jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára oúnjẹ orílẹ̀-èdè Eritrea àti orílẹ̀-èdè Ethiopia, ohun èlò rẹ̀ tó ṣe kókó ni chickpeas tàbí ẹ̀wà broad tí wọ́n sì máa ń sè é pẹ̀lú àlùbọ́sà, ata ilẹ̀, àti àwọn ohun èlò mìíràn. Wọ́n máa ń bu ọbẹ̀ Shiro sórí injera tàbí kitcha. Tegabino shiro jẹ́ ẹ̀yà shiro kan tí wọ́n se láti ara legume aláta rẹ́súrẹ́sú, chickpea, field pea, tàbí ẹ̀wà fava, òróró (tàbí bútà), àti omi. Wọ́n máa ń jẹ ẹ́ nínú ìsasùn kékeré pẹ̀lu sergegna injera.[2]

A le se Shiro lásán, bẹ́ẹ̀ ni a le sè é mọ́ injera or taita kí á sì jẹ́ pẹ̀lú ṣíbí; èyí ni wọ́n ń ẹ̀yà rẹ̀ ní shiro fit-fit.

Shiro jẹ́ ààyò oúnjẹ nígbà tí wọ́n bá ń ṣe àwọn ayẹyẹ kan bíi: Tsom (Lent), àwẹ̀ Ramadan àti àwọn àwẹ̀ mìíràn.

Bí a ṣe le sè é

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bí a bá fẹ́ ṣe shiro wat, ohun àkọ́kọ́ tí a máa ṣe ni láti se chickpeas tàbí lentils. Lẹ́yìn náà ni a máa yí i papọ̀ mọ́ àwọn àgbàdo kan tí a yan pẹ̀lú omi nínú abọ́ ìdáná ọ̀tọ̀ pẹ̀lú àlùbọ́sà, ata ilẹ̀, àti jíńjà.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Habesha Food | Miten Shiro | purchase online". 
  2. McCann, James C. (2009). Stirring the Pot: A History of African Cuisine. Ohio University Press. pp. 104. ISBN 9780896804647.