Ole
Ìrísí
Olè je ona kan ti a n gba lati ji ohun ini elomiran, lai gba iyanda lati se bee pely ero lati fi ohun ini re ohun dun un[1][2][3]. Ole pin si orisirisi ona bii : Idigunjale, iwa ajebanu, ilonilowo-gba, bnilakimaeeli ati gbigba eru ole sakata eni. [2] Ni ile Yoruba, orisirisi oruko ni won ma n pe ole, lara re ni: ''gbewiri'', ''jaguda'', ''alo kolohun-kigbe'', ''firi'ndi-oke'', ''ofan''.
Àwon ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Theft". Merriam-Webster. Merriam-Webster, Inc. Retrieved 8 November 2021.
- ↑ 2.0 2.1 Lehman, Jeffrey; Phelps, Shirelle (2005). West's Encyclopedia of American Law Vol. 10 (2 ed.). Detroit: Thomson/Gale.
- ↑ Green, Stuart P.; Kugler, Matthew B. (22 July 2010). "Community Perceptions of Theft Seriousness: A Challenge to Model Penal Code and English Theft Act Consolidation: Community Perceptions of Theft Seriousness". Journal of Empirical Legal Studies 7 (3): 511–537. doi:10.1111/j.1740-1461.2010.01187.x.