Orílẹ̀
Appearance
Orílẹ̀ jẹ́ àkójọ àwọn Orílẹ̀-èdè àti agbègbè ńlá. Àwọn orílẹ̀ tó wà lágbáyé ni Asia, Africa, North America, South America, Antarctica, Europe, àti Australia.[1]
Agbegbe ati piposi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Orile | Agbegbe (km²) | Logorun apapo isupo ile |
Piposi 2008 |
Logorun apapo piposi |
Kikisi Enia ni km² |
---|---|---|---|---|---|
Asia | 43,820,000 | 29.5% | 3,879,000,000 | 60% | 86.70 |
Africa | 30,370,000 | 20.4% | 922,011,000 | 14% | 29.30 |
North America | 24,490,000 | 16.5% | 528,720,588 | 8% | 21.0 |
South America | 17,840,000 | 12.0% | 382,000,000 | 6% | 20.8 |
Antarctica | 13,720,000 | 9.2% | 1,000 | 0.00002% | 0.00007 |
Europe | 10,180,000 | 6.8% | 731,000,000 | 11% | 69.7 |
Australia | 9,008,500 | 5.9% | 32,000,000 | 0.5% | 3.6 |
Àkójọ ilẹ̀ àwọn orílẹ̀ ni 148,647,000 km², tàbí 29.1% ilẹ̀ ayé (510,065,600 km2).
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Continents: What is a Continent?". National Geographic. 20 September 2011. Archived from the original on 16 July 2019. Retrieved 9 March 2023. "Most people recognize seven continents—Asia, Africa, North America, South America, Antarctica, Europe, and Australia, from largest to smallest—although sometimes Asia and Europe are considered a single continent, Eurasia."