Oúnjẹ
Appearance
(Àtúnjúwe láti Ounjẹ)
Óúnje jẹ ohun ti a le je tabi mu lati fun ara ni okun, Ounjẹ máa ń sáábà ní àmúaradàgbà, carbohydrate, ọ̀rá àti àwọn ohun aṣara lóore mìíràn ti ó ṣe pàtàkì fún ìtọ́jú ara àti agbára tí ó yẹ. A ma un saba ri ounje ni ara ewéko, ẹranko tàbí elu(fungi), ó sì ma ń lilo yíyí padà láti so di nkan tí o sé je. Óúnjẹ kìí ṣe fún ènìyàn nìkan, ẹranko àti ewéko náà ń jeun. Àwọn ewéko ń rí óúnjẹ wọn nípasẹ̀ agbara Oòrùn ( Co2 àti omi). A nílò oúnje láti wà láàyè, bí ó ti lẹ̀ jé wípé ènìyàn lè wà láàyè fún oṣù kan sí mejì láì jeun[1]
Apẹrẹ óúnjẹ ni Ìresì, Isu, èwà, iyán àti béè béè lọ
Otún Le Ka Èyí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwon Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Barrell, Amanda (2020-03-17). "How long can you go without food? Survival, effects, and more". Medical and health information. Retrieved 2022-02-20.