Overland Airways

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán ọkọ̀-òfururú kan ní Overland Airways

Overland Airways ó jẹ́ ilé iṣẹ́ pápákọ̀ òfurufú tí ó fìsí kalẹ̀ sí ìlú an airline based in Ìkẹjà, Ìpínlẹ̀ Èkó. Olú ilé iṣẹ́ wọn wà ní pápákọ̀ Òfurufú Murtala Muhammed International Airport, ní Ìkẹjà, tí wọ́n si ní ẹ̀ka sí pápákọ̀ Òfurufú Nnamdi Azikiwe International Airport, ní ìlú Àbújá.[1]

Ìtàn rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ilé iṣẹ́ bààlúù yí bẹ̀rbẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ọdún 2002, pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ tí wọ́n tó 194 níye. Ní ọdún 2007 ni ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún gbgbogbo ilé iṣẹ́ bàlúù àpérò ní gbèdéke di Ọgbọ̀njọ́ oṣù Kẹ́rin ọdún 2007 , kí wọ́n ṣàlékún ìgbáyé-gbádùngbádùn èrò tí wọ́n jẹ́ oníbàárà wọn nípa lílo bíbíọ̀ ọkọ̀ Òfurufú layeọ̀ àti aláfíà, bí bẹ́ẹ̀kọ́, kí wọ́n kógbá wọlé. Ilé iṣẹ́ yí bọ̀wọ̀ fún Òfin ìjọba tí ó ń rí sí ìgbòkègbodò ìrìnà afẹ́fẹ́ lábẹ́ àjọ Nigerian Civil Aviation Authority (NCAA)gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti pàá kalẹ̀ , ìjọba sì fòntẹ̀ lùú gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára ilé iṣẹ́ pápákọ̀ Òfurufú tí yóò ma ṣiṣẹ́ nílẹ̀ Nàìjíríà.

Àwọn Ibùdó tí ó ń ná[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ibùdó rẹ̀ lábẹ́lé tí ó ń ná ni ns:

Àkójọ Ọkọ̀ Òfurufú wọn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

The Overland Airways fleet includes the following aircraft:

Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàmbá rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́nnsọ wípé Ọkọ̀ Overland Airways ATR 72-202 ni ó gbiná ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹwàá ọdún 2018, látàrí ìná tí ó ṣẹ́yọ lásìkò tí wọ́n ṣàtúnṣe sí Ọkọ̀ náà ní pápákọ̀ Òfurufú Murtala Muhammed International Airport[2]. Ohun tí ó ṣokùnfà iná náà kò yé ẹnikẹ́ni. Àmọ́, qọ́n ṣì ń ṣè wádí lọ́wọ́ lóríbrẹ̀. Ẹ̀wẹ̀, ẹnikẹ́ni kò fara pa nínú ìjàmbá iná náà. [3].

Àwọn Ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

External links[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Commonscat inline