Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Jamáíkà"

Jump to navigation Jump to search
99 bytes removed ,  15:57, 17 Oṣù Kàrún 2010
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
web|url=http://web.archive.org/web/20071016055722/http://www.uctp.org/VocesIndigena.html |title=
Taíno Dictionary |illistrator= The United Confederation of Taíno People |accessdate=2007-
10-18|language=Spanish}}</ref> Nigba kan bi ini [[Habsburg Spain|Spein]] ti won si pe ibe ni ''{{lang|es|Santiago}}'', ni 1655 o di ibiamusin Ilegeesi, ati leyin eyi o di ti Britani, toruko
re n je "Jamaica". Pelu awon eniyan ti won to egbegberun 2.8, o je orile-ede keta [[English-
 
speaking world|anglophone]] to ni awon eniyan pipojulo ni orile [[the Americas|Amerika]], leyin
ibiamusin Ilegeesi, ati leyin eyi o di ti Britani, toruko
awon orile-ede [[United States|Iparapo awon Ipinle]] ati [[Canada|Kanada]]. O wa ninu
 
[[Commonwealth realm|ile Ajoni]] pelu [[Queen Elizabeth II]] bi [[Head of State|Olori Orile-ede]].
re n je "Jamaica". Pelu awon eniyan ti won to
[[Kingston, Jamaica|Kingston]] ni ilu titobijulo ati oluilu re.
 
egbegberun 2.8, o je orile-ede keta [[English-
 
speaking world|anglophone]] to ni awon eniyan
 
pipojulo ni orile [[the Americas|Amerika]], leyin
 
awon orile-ede [[United States|Iparapo awon
 
Ipinle]] ati [[Canada|Kanada]]. O wa ninu
 
[[Commonwealth realm|ile Ajoni]] pelu [[Queen
 
Elizabeth II]] bi [[Head of State|Olori Orile-ede]].
 
[[Kingston, Jamaica|Kingston]] ni ilu titobijulo ati
 
oluilu re.
 
==Itan==
"Villa de la Vega". Spanish Town ni o ni
[[Cathedral|Ile isin]] to pejulo larin awon ibiamusin
 
Britani. Awon ara Ilegeesi fi tipatipa le awon ara
 
Spein kuro ni Ocho Rios ni St. Ann. Sugbon, o di
 
odun 1655, ni Tower Isle, ki awon ara Ilegeesi o to
 
gba ogba ologun awon ara Spein to gbeyin ni
 
Jamaica. Omo Spein to n je Don Cortez Arnoldo de
 
Yassi da abo bo Tower Hill (ibi ti Tower Isle wa)
 
lowo awon ara Ilegeesi fun odun marun, ki o to salo
 
si Kuba. Ibi to gba salo ni won n pe ni "Runaway
 
Bay", eyi na wa ni St. Ann. Oruko Montego Bay, to
 
je oluilu parish St. James, wa lati oruko lede Spein
 
''{{lang|es|manteca bahía}}'' (tabi Bay of Lard) fun
 
opo iye pupo [[boar]] ti won n lo fun lard-making
 
industry.<ref>{{cite
 
web|url=http://www.mobay.com/town4.htm
 
|title=Town of Montego Bay info
 
|publisher=Mobay.com |date=2007-05-07
 
|accessdate=2009-07-04}}</ref>
[[File:Morgan,Henry.jpg|thumb|160px|right|[[Henry
 
Morgan]] was a famous [[Piracy in the
 
Caribbean|Caribbean pirate]] and privateer who
 
had arrived in the West Indies as an indentured
 
servant, like many of the early settlers.<ref>
 
[http://www.historynet.com/henry-morgan-the-
 
pirate-who-invaded-panama-in-1671.htm Henry
 
Morgan: The Pirate Who Invaded Panama in 1671].
 
Historynet.com.</ref>]]
Ara Ilegeesi Admiral [[William Penn (admiral)|William
 
Penn]] (baba [[William Penn]] ti Pennsylvania) ati
 
Ogagun [[Robert Venables]] gba erekusu yi ni 1655.
 
Ni 1660, iye awon eniyan ni Jamaika je 4,500 awon
 
alawo funfun ati bi 1,500 melo awon alawo
 
dudu.<ref name="population">
 
[http://www.newadvent.org/cathen/08270a.htm
 
Donovan, J. (1910). Jamaica. In The Catholic
 
Encyclopedia. New York: Robert Appleton
 
Company].</ref> Lati bi awon odun 1670, awon
 
eniyan alawo dudu ni won je ogunlogo iye awon
 
eniyan nibe.<ref>
 
[http://findarticles.com/p/articles/mi_m2005/is_n1_v
 
28/ai_16106981/pg_2 A failed settler society:
 
marriage and demographic failure in early
 
Jamaica], ''Journal of Social History'', Fall, 1994, by
 
Trevor Burnard</ref>
 
Nigba ti awon ara Ilegeesi gba Jamaika ni 1655
 
olumusin ara Spein sa kuro nibe won si fi opolopo
 
awon omo eru won lati Afrika seyin. Ki awon ara
 
Ilegeesi o mo baa tun mu won leru, won salo si
 
agbegbe oke alapata ni ori erekusu yi, nibi ti won ti
 
darapo mo awon miran ti awon na ti sa kuro lowo
 
awon ara Spein tele lati lo gbe pelu awon [[Taínos]].
 
Awon eru ti won ti salo wonyi je mimo bi [[Jamaican
 
Maroons]], koja lu awon ara Britani ni orundun
 
18th. Awon iran won si n je oruko yi titi doni. Nigba
 
oko eru awon Maroon sedasile agbajo alominira
 
larin inu oke ile Jamaica niran deran.
 
Nigba awon odun 200 akoko ijoba Britani, Jamaika
 
di ikan ninu awon orile-ede to siwaju lagbaye to n
 
ta [[sugar|suga]] ati to n lo eru, nipa sise iye to ju
 
toonu 77,000 suga lo lododun larin 1820 ati 1824.
 
Leyin [[Slave Trade Act 1807|ipare owo eru]] (eyi
 
yato si oko eru gan ti won ko pare) ni 1807,<ref>
 
[http://countrystudies.us/caribbean-islands/8.htm
 
The Sugar Revolutions and Slavery], ''U.S. Library
 
of Congress''</ref> awon ara Britani mu awon ara
 
India ati ara Saina wa bi awon [[indentured
 
servant|oniwofa]] lati sise. Awon omo-omo awo
 
awon oniwofa lti Asia yi si wa ni Jamaika titi doni.
 
Nigba to fi di ibere orundun 19th, nitoripe Jamaica
 
gbokan le [[slavery|oko eru]] eyi ki awon eniyan
 
alawodudu (awon ara Afrika) o poju awon eniyan
 
alawofunfun (awon ara Europe) lo ni ipin 20 si 1.
 
Botilejepe awon Ilegeesi ti fi ofinde owo eru,
 
ifayawo won si awon ibiamusin si tun sele nigbana.
 
Ijoba Britani se ofin to lana ipare oko eru, sugbon
 
won tun lana lati se imudara igbe awon eru ibe.
 
Ninu awon ilanna yi ni ifofinde lilo egba ninu oko,
 
ifofinde nina awon obinrin, ikede pe awon eru
 
gbodo je gbigba laye lati gba ilana esin,
 
ipondandan pe awon eru gbodo ni ojo kan ninu
 
ose lati ta awon ogbin oko won, bakanna won si
 
tun fofinde awon oja ojo Aiku.
[[File:Jm-map.png|thumb|left|Map of Jamaica]]
Sugbon ni Jamaika, awon lana yi je lilodi di latowo
 
Ile-igbimo Asofin. Ileigbimo yi so pe awon eru
 
nitelorun ara won, won si lodi si itowobo Ileasofin
 
si oro to n lo ni erekusu ohun, botilejepe opo awon
 
to ni eru n beru pe ijidide awon eru le se.
 
 
{{ekunrere}}
 
== Itokasi ==
{{reflist}}

Ètò ìtọ́sọ́nà