Ìṣèlú: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
k Bot Fífikún: frr:Politiik
EmausBot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot Fífikún: ba:Сәйәсәт
Ìlà 34: Ìlà 34:
[[ast:Política]]
[[ast:Política]]
[[az:Siyasət]]
[[az:Siyasət]]
[[ba:Сәйәсәт]]
[[bar:Politik]]
[[bar:Politik]]
[[bat-smg:Puolitėka]]
[[bat-smg:Puolitėka]]

Àtúnyẹ̀wò ní 21:03, 27 Oṣù Kẹjọ 2010

Ìṣèlú tabi òṣèlú ni igbese bi awon idipo eniyan kan se n sepinnu. Oro yi je mimulo si iwuwa ninu awon ìjọba abele.


ÌSÈLÚ NILE YORUBA

Ní àwùjo Yorùbá, á ní àwon ònà ìsèlú tiwa tí ó dá wa yàtò sí èyà tàbí ìran mìíràn. Kí àwon Òyìnbó tó dé ní àwa Yorùbá ti ni ètò ìsèlú tiwa tí ó fesèmúlè. Tí ó sì wà láàárin òpò àwon ènìyàn. Yàtò sí tí àwon èyà bí i ti ìgbò tí ó jé wí pé àjorò ni won n fi ìjoba tiwon se (acephalous) tàbí ti Hausa níbi tí àse pípa wà lówó enìkan (centralization).

Ètò òsèlú Yorùbá bèrè láti inú ilé. Eyi si fi ipá tí àwon òbí ń kò nínú ilé se ìpìlè ètò òsèlú wa. Yorùbá bò won ní, “ilé là á tí kó èsó ròdé”. Baba tí ó jé olórí ilé ni ó jé olùdarí àkókó nínú ètò ìsèlú wa. Gbogbo èkó tó ye fún omo láti inú ilé ni yóò ti bèrè sí kó won. Bí i àwon èkó omolúàbí. Tí èdèàiyèdè bá selè nínú ile, bàbá ni yóò kókó parí rè. tí kò bá rí i yanjú ni yóò tó gbé e lo sí òdò mógàjí agbo-ilé. Agbo-ilé ni ìdílé bíi mérin lo sókè tó wà papò ni ojú kan náà. Won kó ilé won papò ní ààrin kan náà. Tí mógàjí bá mò ón tì, ó di odo olóyè àdúgbò. Olóyè yìí ni ó wà lórí àdúgbò. Àdúgbò ni àwon agbo-ilé orísìírísìí tí ó wà papò ní ojúkan. A tún máa ń rí àwon Baálè ìletò pàápàá tí wón jé asojú fún oba ìlú ní agbègbè won. Àwon ni òpá ìsàkóso abúlé yìí wà ní owó won. Ejó tí won kò bá rí ojúùtú sí ni wón máa ń gbé lo sí odo oba ìlú. Oba ni ó lágbára ju nínú àkàsò ìsàkóso ilè Yorùbá. Àwon Yorùbá ka àwon Oba won sí òrìsa Ìdí nìyí tí won fí máa ń so pé:

  • Igba Irúmolè ojùkòtúu
  • Igba Irúmolè ojùkòsì

Òkan tí ó lé nínú rè tí ó fi jé òkànlénú tàbí òkàn-lé-ní-rinwó (401), àwon oba ni. Won a ní.

KÁBÌYÈSÍ ALÁSE. ÈKEJÌ ÒRÌSÀ

Oba yìí ní àwon ìjòyè tí won jo ń sèlú. Ejó tí oba bá dá ni òpin. Ààfin oba ni ilé ejó tó ga jù. Oba a máa dájó ikú. Oba si le è gbésè lé ìyàwó tàbí ohun ìní elòmíì. Wón a ní: Oba kì í mùjè Ìyì ni oba ń fi orí bíbé se.

A rí àwon olóyè bí ìwàrèfà, ní òyó ni a ti ń pè wón ní Òyó-mèsì. Ìjòyè méfà tàbí méje ni won. Àwon ni afobaje. A rí àwon ìjòyè àdúgbò tàbí abúlé pàápàá tí ó máa ń bá oba se àpérò tàbí láti jábò ìlosíwájú agbègbè won fún un.

A tún ń àwon èsó tí ó ń dáàbò bo oba àti ìlú. Àwon ni won ń kojú ogun. Àwon ni o n lo gba isakole fóba. A tún ní àwon onífá, Babaláwo àti béè béè lo.

Ètò òsèlú wa tí ó fesè múlè yìí ni ó mú kí ó sòro fún àwon òyìnbó láti gàba tààrà lórí wa (Indirect rule). Àwon oba àti ìjòyè wa náà ni won ń lò láti sèjoba lórí wa. Ó pè díè kí wón tó rí wa wo.