Gíríìsì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
k r2.6.2) (Bot Títúnṣe: xmf:საბერძნეთი
Xqbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k r2.7.2) (Bot Títúnṣe: nap:Grecia
Ìlà 266: Ìlà 266:
[[na:Grit]]
[[na:Grit]]
[[nah:Grecia]]
[[nah:Grecia]]
[[nap:Gracia]]
[[nap:Grecia]]
[[nds:Grekenland]]
[[nds:Grekenland]]
[[nds-nl:Griekenlaand]]
[[nds-nl:Griekenlaand]]

Àtúnyẹ̀wò ní 23:36, 6 Oṣù Kẹ̀sán 2011

Hẹ́llẹ́nìkì Olómìnira
Hellenic Republic

Ελληνική Δημοκρατία
Ellīnikī́ Dīmokratía
Motto: Eleftheria i Thanatos, (Greek: "Ελευθερία ή Θάνατος", "Freedom or Death") (traditional)
Orin ìyìn: Ὕμνος εἰς τὴν Ἐλευθερίαν
Ýmnos eis tīn Eleftherían
Hymn to Liberty1
Ibùdó ilẹ̀  Gíríìsì  (green) – on the European continent  (light green & grey) – in the European Union  (light green)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Gíríìsì  (green)

– on the European continent  (light green & grey)
– in the European Union  (light green)  —  [Legend]

Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Athens
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaGreek
Orúkọ aráàlúGreek
ÌjọbaParliamentary republic
• Ààrẹ
Karolos Papoulias
George Papandreou
AṣòfinParliament
Modern statehood
25 March 1821
• Recognized
3 February 1830, in the London Protocol
7 May 1832, in the Convention of London
11 June 1975,
Third Hellenic Republic
Ìtóbi
• Total
131,990 km2 (50,960 sq mi) (96th)
• Omi (%)
0.8669
Alábùgbé
• 2009 estimate
11,260,402[1] (74th)
• 2001 census
10,964,020[2]
• Ìdìmọ́ra
85.3/km2 (220.9/sq mi) (88th)
GDP (PPP)2008 estimate
• Total
$341.688 billion[3] (33rd)
• Per capita
$30,681[3] (26th)
GDP (nominal)2008 estimate
• Total
$357.548 billion[3] (27th)
• Per capita
$32,105[3] (27th)
Gini (2005)332
Error: Invalid Gini value · 36th
HDI (2007) 0.942[4]
Error: Invalid HDI value · 25th
OwónínáEuro ()3 (EUR)
Ibi àkókòUTC+2 (EET)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+3 (EEST)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù30
Internet TLD.gr4
  1. Also the national anthem of Cyprus.
  2. CIA World Factbook.
  3. Before 2001, the Greek drachma.
  4. The .eu domain is also used, as it is shared with other European Union member states.

Gríìsì (English: /ˈɡriːs/  ( listen); Gíríkì: Ελλάδα, Elláda, IPA: [eˈlaða]  ( listen); Èdè Grííkì Ayéijọ́unἙλλάς, Hellás, IPA: [helːás]), bakanna gege bi Hellas ati fun ibise bi Helleniki Olominira (Ελληνική Δημοκρατία, Ellīnikī́ Dīmokratía, IPA: [eliniˈci ðimokraˈtia]),[5] je orile-ede kan ni guusuapailaorun Europe, o budo si apaguusu opin Balkan Peninsula. Griisi ni ile bode mo Albania, Olominira ile Makedonia ati Bulgaria si ariwa, ati Turki si ilaorun. Okun Aegeani dubule si ilaorun re, the Okun Ioniani si iwoorun, ati Okun Mediterraneani si guusu. Griisi ni o ni etiodo kewa togunjulo ni agbaye toje 14,880 km (9,246.00 mi) ni gigun, ti o ni opolopo iye awon erekusu (bi 1400, 227 ni ibi ti aon eniyan ngbe), ninu won ni Crete, Dodecanese, Cyclades, ati awon Erekusu Ioniani. Bi ogorin ninu ogorun ile Griisi ni o je ti awon oke, ninu ibi ti Oke Olympus ni o gajulo to je 2,917 m (9,570.21 ft).

Griisi oni fa gbongbo de asa-olaju Griisi ayeijoun, nibi ti gbogbo eniyan gba bi ibusun asa-olaju Apaiwoorun. Nitori eyi o je ibi ibere oseluaralu,[6] imoye Apaiwoorun,[7] Awon Idije Olympiki, litireso Apaiwoorun ati itankiko, sayensi oloselu, awon ipile sayensi ati mathematiki pataki, ati drama,[8] ati trajedi ati awada. Asesile yi han gedegbe ninu awon Ibi Oso Agbaye UNESCO 17 ti won wa ni Griisi.

Griisi je orile-ede adagbasoke to ni Human Development Index giga,[9][10][11][12] Griisi ti je omo egbe Isokan Europe lati 1981 ati Isokan Okowo ati Owonina Europe lati 2001,[13] NATO lati 1952,[14] ati Ile-ise Ofurufu Europe lati 2005.[15] Bakanna o tun je omo egbe latibere Isodokan awon Orile-ede, OECD,[16] ati Agbajo Ifowosowopo Okowo ni Okun Dudu. Atensi ni oluilu re; awon ilu pataki miran nibe tun ni Thessaloniki, Patras, Heraklion ati Larissa.


Awon Periferi ati ibile

Fun amojuto, Griisi ni periferi metala ti won je pipin si ibile mokaleladota ([nomoi] error: {{lang}}: text has italic markup (help), singular Gíríkì: nomos). Bakanna ni agbegbe idawa kan wa to n je Oke Athos (Gíríkì: Agio Oros, "Oke Mimo"), to ni bode mo periferi Central Macedonia.

Map Number Periphery Capital Area (km²) Area (sq mi) Population
1 Attica Athens 3,808 1,470 3,761,810
2 Central Greece Lamia 15,549 6,004 605,329
3 Central Macedonia Thessaloniki 18,811 7,263 1,871,952
4 Crete Heraklion 8,259 3,189 601,131
5 East Macedonia and Thrace Komotini 14,157 5,466 611,067
6 Epirus Ioannina 9,203 3,553 353,820
7 Ionian Islands Corfu 2,307 891 212,984
8 North Aegean Mytilene 3,836 1,481 206,121
9 Peloponnese Kalamata 15,490 5,981 638,942
10 South Aegean Ermoupoli 5,286 2,041 302,686
11 Thessaly Larissa 14,037 5,420 753,888
12 West Greece Patras 11,350 4,382 740,506
13 West Macedonia Kozani 9,451 3,649 301,522
- Mount Athos (Autonomous) Karyes 390 151 2,262




Itoka

  1. "Total population". Eurostat. 2009-01-01. Retrieved 2009-08-02. 
  2. National Statistical Service of Greece: Population census of 18 March 2001: Πίνακας 1. Πληθυσμός κατά φύλο και ηλικία
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 "Greece". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01. 
  4. Human Development Report 2009. The United Nations. Retrieved 12 October 2009.
  5. "World Factbook - Greece: Government". CIA. www.cia.gov. 2007-03-15. Retrieved 2007-04-07. 
  6. Finley, M. I. Democracy Ancient and Modern. 2d ed., 1985. London: Hogarth.
  7. History of Philosophy, Volume 1 by Frederick Copleston
  8. Brockett, Oscar G. History of the Theatre. sixth ed., 1991. Boston; London: Allyn and Bacon.
  9. "World Economic Outlook Database October 2009—WEO Groups and Aggregates Information". International Monetary Fund. Retrieved 19 January 2010. 
  10. "Data - Country Groups - High-income OECD members". World Bank. Retrieved 19 January 2010. 
  11. "Appendix B :: International Organizations and Groups". The World Factbook. Central Intelligence Agency. Retrieved 19 January 2010. 
  12. "Human Development Report 2009 - HDI rankings". United Nations Development Programme. Retrieved 19 January 2010. 
  13. "Member States of the EU: Greece". European Union. europa.eu. Retrieved 2007-04-07. 
  14. On the 14 August 1974 Greek forces withdrew from the integrated military structure of NATO in protest at the Turkish occupation of northern Cyprus. Greece rejoined NATO in 1980.
  15. "Greece becomes 16th ESA Member State". European Space Agency. www.esa.int. 2005-03-22. Retrieved 2007-04-07. 
  16. "Convention on the OECD". Organisation for Economic Co-operation and Development. www.oecd.org. Retrieved 2007-04-07. 

Àdàkọ:Link FA