Ìtanná: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 11: Ìlà 11:


Ninu [[electrical engineering|iseero onitanna]], itanna unje lilo fun:
Ninu [[electrical engineering|iseero onitanna]], itanna unje lilo fun:
* '''[[electric power|agbara itanna]]''' (eyi le tokasi bi [[electrical potential energy|okun iniagbara onitanna]] ba se posi tabi si [[power (physics)|energy per time|okun onitanna larin aiko kan]]) to wa fun lilo, latodo [[electrical power industry|ile-ise onitanna]]. Bakanna, "itanna" le je lilo bi oro fun "sisomo waya fun itanna" to tumosi [[electrical connection|isopomora]] isise mo [[power station|ibuso agbara ina]]. Iru isopomora bahun fun awon alo "itanna" ni aye si [[electric field|papa itanna]] to wa ninu [[electrical wiring|isopowaya itanna]], ati bi be si agbara itanna.
* '''[[electric power|agbara itanna]]''' (eyi le tokasi bi [[electrical potential energy|okun iniagbara onitanna]] ba se posi tabi si [[power (physics)|okun onitanna larin asiko kan]]) to wa fun lilo, latodo [[electrical power industry|ile-ise onitanna]]. Bakanna, "itanna" le je lilo bi oro fun "sisomo waya fun itanna" to tumosi [[electrical connection|isopomora]] isise mo [[power station|ibuso agbara ina]]. Iru isopomora bahun fun awon alo "itanna" ni aye si [[electric field|papa itanna]] to wa ninu [[electrical wiring|isopowaya itanna]], ati bi be si agbara itanna.
* '''[[electronics|isiseonina]]''' da lori awon [[electrical circuit|asoyipo onitanna]] ti won ni awon [[active component|ohun inu alagbese onitanna]] bi awon [[vacuum tube|igo adepa]], awon [[transistor|tiransisto]], awon [[diode|adojuona]] ati awon [[integrated circuit|asoyipo olodidi]], ati awon oroiseona to ba sepo.
* '''[[electronics|isiseonina]]''' da lori awon [[electrical circuit|asoyipo onitanna]] ti won ni awon [[active component|ohun inu alagbese onitanna]] bi awon [[vacuum tube|igo adepa]], awon [[transistor|tiransisto]], awon [[diode|adojuona]] ati awon [[integrated circuit|asoyipo olodidi]], ati awon oroiseona to ba sepo.


Electrical phenomena have been studied since antiquity, though advances in the science were not made until the seventeenth and eighteenth centuries. Practical applications for electricity however remained few, and it would not be until the late nineteenth century that [[Electrical engineering|engineers]] were able to put it to industrial and residential use. The rapid expansion in electrical technology at this time transformed industry and society. Electricity's extraordinary versatility as a means of providing energy means it can be put to an almost limitless set of applications which include [[motive power|transport]], [[HVAC|heating]], [[electric lighting|lighting]], [[Telecommunication|communications]], and [[computation]]. Electrical power is the backbone of modern industrial society, and is expected to remain so for the foreseeable future.<ref>
Awon isele onitanna ti je gbigbeka lati igba aye atijo, sibesibe ilosiwaju ninu sayensi re ko sele titi di orundun ketadinlogun ati kejidinlogun. Awon imulo alamuse fun itanna sibesibe si kere, yio si di opin orundun okandinlogun ki awon [[Electrical engineering|oniseero]] o to le lo ni ile-ise ati ibugbe. Igbale iyara ninu oroiseona onitanna ni asiko yi se awon ile-ise ati awujo di otun. Nitoripe itanna se lo lorisirisi ona lati pese okun gba laye mulo ninu opo imulo alainiye bi [[motive power|irinna]], [[HVAC|igbegbonna]], [[electric lighting|itanmole]], [[Telecommunication|ibanisoro]], ati [[computation|isirokomputa]]. Agbara onitanna ni igbaeyin ile-ise awujo odeoni, be si ni yio ri lojowaju.<ref>
{{Citation
{{Citation
| first = D.A. | last = Jones
| first = D.A. | last = Jones
Ìlà 25: Ìlà 25:
| year = 1991}}
| year = 1991}}
</ref>
</ref>

The word ''electricity'' is from the [[New Latin]] ''ēlectricus'', "amber-like"{{Ref label|A|a|none}}, coined in the year 1600 from the Greek ''ήλεκτρον'' (electron) meaning [[amber]], because electrical effects were produced classically by rubbing amber.





Àtúnyẹ̀wò ní 10:09, 13 Oṣù Kàrún 2012

Multiple lightning strikes on a city at night
Lightning is one of the most dramatic effects of electricity.

Ìtanná (Electricity) ni sayensi, iseero, oroiseona ati àwon isele eleda to je mo bi awon adijo ina se wa ati bi won se un sanlo. Itanna unfa orisirisi isele onitanna, bi monamona, ina ojukan, ifasara onigberingberin onina ati isanlo iwo onitanna ninu waya onitanna. Bakanna, itanna gba idasile ati igbasodo iranka onigberingberin onina bi awon iru radio laye.

Ninu itanna, awon adijo unse awon papa onigberingberin onina ti won unsise lori awon adijo miran. Itanna unsele nitori orisirisi awon iru isiseeda:

Ninu iseero onitanna, itanna unje lilo fun:

Awon isele onitanna ti je gbigbeka lati igba aye atijo, sibesibe ilosiwaju ninu sayensi re ko sele titi di orundun ketadinlogun ati kejidinlogun. Awon imulo alamuse fun itanna sibesibe si kere, yio si di opin orundun okandinlogun ki awon oniseero o to le lo ni ile-ise ati ibugbe. Igbale iyara ninu oroiseona onitanna ni asiko yi se awon ile-ise ati awujo di otun. Nitoripe itanna se lo lorisirisi ona lati pese okun gba laye mulo ninu opo imulo alainiye bi irinna, igbegbonna, itanmole, ibanisoro, ati isirokomputa. Agbara onitanna ni igbaeyin ile-ise awujo odeoni, be si ni yio ri lojowaju.[1]


Akiyesi

  1. Jones, D.A. (1991), "Electrical engineering: the backbone of society", Proceedings of the IEE: Science, Measurement and Technology, 138 (1): 1–10, doi:10.1049/ip-a-3.1991.0001 

Itokasi

Ajapo ode

Àdàkọ:Wiktionary

Àdàkọ:Link FA Àdàkọ:Link GA ak:Ɛlɛktrisiti