Angola: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 106: Ìlà 106:
'''Àngólà''', lóníbiṣẹ́ bíi '''Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àngólà''' ({{lang-pt|República de Angola}}, {{IPA-pt|ʁɨˈpublikɐ dɨ ɐ̃ˈɡɔla|pron}};<ref>This is the pronunciation in Portugal; in Angola it is pronounced as it is written</ref> [[Kikongo]], [[Kimbundu]], [[Umbundu]]: Repubilika ya Ngola), jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní apágúsù Áfríkà tó ní bodè mọ́ [[Namibia]] ní gúsù, [[Democratic Republic of the Congo|Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò]] ní àríwá, àti [[Zambia]] ní ilàòrùn; ìwọ̀òrùn rẹ̀ bọ́ sí etí Òkun Atlántíkì. [[Luanda]] ni olúìlú rẹ̀. Ìgbèríko [[Enclave and exclave|òde]] [[Cabinda Province|Kàbíndà]] ní bodè mọ́ [[Republic of the Congo|Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò]] àti [[Democratic Republic of the Congo|Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò]].
'''Àngólà''', lóníbiṣẹ́ bíi '''Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àngólà''' ({{lang-pt|República de Angola}}, {{IPA-pt|ʁɨˈpublikɐ dɨ ɐ̃ˈɡɔla|pron}};<ref>This is the pronunciation in Portugal; in Angola it is pronounced as it is written</ref> [[Kikongo]], [[Kimbundu]], [[Umbundu]]: Repubilika ya Ngola), jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní apágúsù Áfríkà tó ní bodè mọ́ [[Namibia]] ní gúsù, [[Democratic Republic of the Congo|Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò]] ní àríwá, àti [[Zambia]] ní ilàòrùn; ìwọ̀òrùn rẹ̀ bọ́ sí etí Òkun Atlántíkì. [[Luanda]] ni olúìlú rẹ̀. Ìgbèríko [[Enclave and exclave|òde]] [[Cabinda Province|Kàbíndà]] ní bodè mọ́ [[Republic of the Congo|Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò]] àti [[Democratic Republic of the Congo|Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò]].


The Portuguese were present in some—mostly coastal—points of the territory of what is now Angola, from the 16th to the 19th century, interacting in diverse ways with the peoples that lived there. In the 19th century they slowly and hesitantly began to establish themselves in the interior. Angola as a [[Portuguese West Africa|Portuguese colony]] encompassing the present territory was not established before the end of the 19th century, and "effective occupation", as required by the [[Berlin Conference (1884)]] was achieved only by the 1920s. Independence was achieved in 1975, after a protracted liberation war. After independence, Angola was the scene of an intense [[Angolan Civil War|civil war from 1975 to 2002]]. The country has vast mineral and petroleum reserves, and its economy has on average grown at a two-digit pace since the 1990s, especially since the end of the civil war. In spite of this, standards of living remain low for the majority of the population, and [[life expectancy]] and [[infant mortality|infant mortality rates]] in Angola are among the worst-ranked in the world.<ref>{{en icon}} [https://www.cia.gov/library/publications/the-world-factbook/rankorder/2102rank.html Life expectancy at birth] www.cia.gov (2009)</ref> At the same time, a minority has reached comfortable life standards, and the dominant stratum has succeeded in accumulating considerable wealth, so that social inequality in Angola is one of the highest in the world.
Angola di [[Portuguese West Africa|ileamusin Portugal]] ni 1884 leyin [[Berlin Conference (1884)|Ipade Berlin]]. O gba ilominira ni odun 1975 leyin ogun itusile. Ko pe leyin ilominira ni [[Angolan Civil War|ogun abele sele lati 1975 de 2002]]. Angola ni opo alumoni ati petroliomu, be sini okowo re ti ungbera soke pelu iwon eyoika meji lati odun 1990, agaga lateyin igba ti ogun abele wa sopin. Sibesibe opagun ijaye si kere gidigidi fun opo alabugbe, be sini [[life expectancy|ojo ori]] ati [[infant mortality|iye ọ̀fọ̀ ọmọwọ́]] ni Angola je awon eyi to buru julo lagbaye.<ref>{{en icon}} [https://www.cia.gov/library/publications/the-world-factbook/rankorder/2102rank.html Life expectancy at birth] www.cia.gov (2009)</ref>



{{ekunrere}}
{{ekunrere}}

Àtúnyẹ̀wò ní 08:27, 9 Oṣù Kẹfà 2012

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àngólà
Republic of Angola

República de Angola  (Portuguese)
Repubilika ya Ngola   (Kikongo, Kimbundu, Umbundu)
'Orin ìyìn: Angola Avante!  (Portuguese)
Rìnsó Àngólà

Forward Angola!
Location of Àngólà
OlùìlúLuanda
Ìlú tótóbijùlọolúìlú
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaPotogí
Lílò national languagesKikongo, Chokwe, Umbundu, Kimbundu, Ganguela, Kwanyama
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
(2000)
37% Ovimbundu
25% Ambundu
13% Bakongo
22% ará Áfríkà míràn
2% Mestiço
1% ará Europe
Orúkọ aráàlúará Àngólà
ÌjọbaOrílẹ̀-èdè olómìnira ìṣọ̀kan oníàrẹ
• Ààrẹ
José Eduardo dos Santos
Fernando da Piedade Dias dos Santos
AṣòfinIlé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin
Ìlómìnira
• látọwọ́ Pọ́rtúgàl
11 November 1975
Ìtóbi
• Total
1,246,700 km2 (481,400 sq mi) (23k)
• Omi (%)
negligible
Alábùgbé
• 2009 estimate
18,498,000[1][2]
• Census
(yíò wáyè ní 2013)
• Ìdìmọ́ra
14.8/km2 (38.3/sq mi) (199th)
GDP (PPP)2011 estimate
• Total
$115.679 billion[3] (64k)
• Per capita
$5,894[3] (107k)
GDP (nominal)2011 estimate
• Total
$100.948 billion[3] (61st)
• Per capita
$5,144[3] (91k)
Gini (2000)59[4]
Error: Invalid Gini value
HDI (2011)0.486
Error: Invalid HDI value · 148k
OwónínáKwanza (AOA)
Ibi àkókòUTC+1 (WAT)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+1 (kòsí)
Ojúọ̀nà ọkọ́ọ̀tún
Àmì tẹlifóònù+244
ISO 3166 codeAO
Internet TLD.ao

Àngólà, lóníbiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àngólà (Pọrtugí: República de Angola, pípè [ʁɨˈpublikɐ dɨ ɐ̃ˈɡɔla];[5] Kikongo, Kimbundu, Umbundu: Repubilika ya Ngola), jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní apágúsù Áfríkà tó ní bodè mọ́ Namibia ní gúsù, Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò ní àríwá, àti Zambia ní ilàòrùn; ìwọ̀òrùn rẹ̀ bọ́ sí etí Òkun Atlántíkì. Luanda ni olúìlú rẹ̀. Ìgbèríko òde Kàbíndà ní bodè mọ́ Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò àti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò.

Angola di ileamusin Portugal ni 1884 leyin Ipade Berlin. O gba ilominira ni odun 1975 leyin ogun itusile. Ko pe leyin ilominira ni ogun abele sele lati 1975 de 2002. Angola ni opo alumoni ati petroliomu, be sini okowo re ti ungbera soke pelu iwon eyoika meji lati odun 1990, agaga lateyin igba ti ogun abele wa sopin. Sibesibe opagun ijaye si kere gidigidi fun opo alabugbe, be sini ojo ori ati iye ọ̀fọ̀ ọmọwọ́ ni Angola je awon eyi to buru julo lagbaye.[6]


Itokasi

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named unpop
  2. Population Forecast to 2060 by International Futures hosted by Google Public Data Explorer
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 "Angola". International Monetary Fund. Retrieved 17 April 2012. 
  4. "Gini Index". World Bank. Retrieved 2 March 2011. 
  5. This is the pronunciation in Portugal; in Angola it is pronounced as it is written
  6. (Gẹ̀ẹ́sì) Life expectancy at birth www.cia.gov (2009)