Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ṣàngó"
Jump to navigation
Jump to search
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
k (Bot Fífikún: fr:Shangô) |
|||
'''Sàngó''' Olukoso, Oko Oya.
Ìhùwàsí búburú ati dídá wàhalá ati ìkolura pèlú ìjayé fàmílétè-kí-n-tutó pò lówó sàngó gégé bí Oba tó bẹ́ẹ̀ títí ó fi di òtéyímiká, èyí jásí wí pé tọmọdé tàgbà dìtè mó o. Wón fi ayé ni í lára. Ó sì fi ìlú Òyó sílè nígbèyìn-gbéyín. Ó pokùnso sí ìdí igi àyàn kan lébà ònà nítòsí Òyó nígbàtí Oya: Ìyàwó rẹ̀ kan tókù náà sì di odò.
|