Ìṣeìjọánglíkánì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
No edit summary
k Bot: Migrating 1 interwiki links, now provided by Wikidata on d:Q6423963
Ìlà 11: Ìlà 11:
{{DEFAULTSORT:Anglikani}}
{{DEFAULTSORT:Anglikani}}
[[Ẹ̀ka:Ẹ̀sìn Krístì]]
[[Ẹ̀ka:Ẹ̀sìn Krístì]]

[[en:Anglicanism]]

Àtúnyẹ̀wò ní 09:24, 18 Oṣù Kẹrin 2013

Ìṣeìjọánglíkánì (Anglicanism) je asa kan ninu Esin Kristi to ni awon ijo ti won ni ibasepo ojoun po mo Ijo ile Ilegeesi tabi iru igbagbo, isin ati ito ijo kanna.[1] Anglikani bi oro wa lati inu ecclesia anglicana, oro ede Latin igba ailaju ni bi odun 1246 to tumosi Ijo Ilegeesi (the English Church). Awon onigbagbo Iseijoanglikani ni won unje Awon Anglikani. Opo awon Anglikani ni won je omo egbe awon ijo ti won je ara Idarapo awon Anglikani kariaye.[2]




Itokasi

  1. "What it means to be an Anglican". Retrieved 2009-03-16.  Text " Church of England " ignored (help)
  2. "The Anglican Communion official website - homepage". Retrieved 2009-03-16.