Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ẹ̀sìn Krístì"

Jump to navigation Jump to search
53 bytes added ,  04:04, 4 Oṣù Kẹfà 2014
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
k (Bot: Migrating 1 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q5043 (translate me))
<font face="Tahoma">'''Ẹ̀sìn Kristi''' tàbí Ìsìn Kristi tàbí Ẹ̀sìn onígbàgbọ́ (tí àwon míràn máa ń pè ni Ẹ̀sìn Kiriyò) jẹ́ [[ẹ̀sìn Ọlọ́runkan]] tọ́ dá l'órí ìgbésíayé àti àwọn ẹ̀kọ́ [[Jesu Kristi|Jesu ti Nasareti]] gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe kọsílẹ̀ nínú [[Májẹ̀mú Tuntun]] ti [[Bíbélì]].
 
Ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ ló fẹ́rẹ̀ tan kálẹ̀ jù ní gbogbo àgbáyé. Ní bíi nkàn an ọdún bíi mewa séyìn ìye àwon Tí ó n sẹ ẹ̀sìn ìgbàgbọ ní àgbáye fẹ́rẹ̀ tó bílìònù méjì ènìyàn Bíì àwọn ẹ̀sìn míràn èsìn ìgbàgbọ́ ní àwọn òpó igbagbọ àti àsà tì ó dìrò mó. Fún àwọn tó bá jẹ onígbàgbó nìkan ló lè ní òye ìtumọ̀ àwọn òpó igbagbo tí ẹ̀sìn yí dìró mọ́ dáradára. Sùgbọ́n síbẹ̀síbẹ̀ a sì lè sàlàyé fún aláìgbàgbọ́ nínú ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ ohun tí èsìn ìgbàgbọ́ jẹ.
Anonymous user

Ètò ìtọ́sọ́nà