Ìtanná: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
Addbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 112 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q12725 (translate me)
k Removing Link GA template (handled by wikidata)
Ìlà 115: Ìlà 115:


{{Link FA|ar}}
{{Link FA|ar}}
{{Link GA|ja}}

Àtúnyẹ̀wò ní 11:26, 25 Oṣù Kàrún 2015

Multiple lightning strikes on a city at night
Monamona je ikan ninu ipa itanna afojuri.

Ìtanná (Electricity) ni sayensi, iseero, oroiseona ati àwon isele eleda to je mo bi awon adijo ina se wa ati bi won se un sanlo. Itanna unfa orisirisi isele onitanna, bi monamona, ina ojukan, ifasara onigberingberin onina ati isanlo iwo onitanna ninu waya onitanna. Bakanna, itanna gba idasile ati igbasodo iranka onigberingberin onina bi awon iru radio laye.

Ninu itanna, awon adijo unse awon papa onigberingberin onina ti won unsise lori awon adijo miran. Itanna unsele nitori orisirisi awon iru isiseeda:

Ninu iseero onitanna, itanna unje lilo fun:

Awon isele onitanna ti je gbigbeka lati igba aye atijo, sibesibe ilosiwaju ninu sayensi re ko sele titi di orundun ketadinlogun ati kejidinlogun. Awon imulo alamuse fun itanna sibesibe si kere, yio si di opin orundun okandinlogun ki awon oniseero o to le lo ni ile-ise ati ibugbe. Igbale iyara ninu oroiseona onitanna ni asiko yi se awon ile-ise ati awujo di otun. Nitoripe itanna se lo lorisirisi ona lati pese okun gba laye mulo ninu opo imulo alainiye bi irinna, igbegbonna, itanmole, ibanisoro, ati isirokomputa. Agbara onitanna ni igbaeyin ile-ise awujo odeoni, be si ni yio ri lojowaju.[1]


Akiyesi

  1. Jones, D.A. (1991), "Electrical engineering: the backbone of society", Proceedings of the IEE: Science, Measurement and Technology, 138 (1): 1–10, doi:10.1049/ip-a-3.1991.0001 

Itokasi

Ajapo ode

Àdàkọ:Wiktionary

Àdàkọ:Link FA