Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè"

Jump to navigation Jump to search
k
replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining characters (accents)
k (replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining characters (accents))
k (replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining characters (accents))
Èyí ni orin tí orílẹ̀-ède kan máa nń kọ nígbà tí wọ́n bá nń ṣe ayẹyẹ. Wọ́n máa nń kọ ọ́ tí olórí orílẹ̀-èdè mìíràn bá wá bẹ̀ wọ́n wò. Wọ́n máa nń kọ ọ́ níbi tí àwọn ènìyàn bá pé jọ sí tàbí ibi òṣèlú tó bá ṣe pàtàkì. Ẹnìkan lè dá a kọ fún gbogbo ènìyàn tàbí kí gbogbo ènìyàn kópa níní kíkọ rẹ̀.
Ọ̀rọ̀ inú orin yìí máa nń yin orílẹ̀-èdè àti àwọn ènìyàn tí ó wà nínú rẹ̀. Orin yìí máa n sábàá sọ àwọn ohun ribiribi tí ilẹ̀ kan ti gbé ṣe. [[Bouget de I’Isle]] ni ó kọ orin ti ilẹ̀ Faranse ní àsìkò ogun ní 1792. [[Francis Scott Key]] ni o kọ ti ilẹ̀ Àmẹ́rìkà ní 1814. A kò mọ ẹni tí ó kọ ‘God save the Queen’ ti ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ṣùgbọ́n 1745 ni wọ́n kọ́kọ́ kọ ọ́. ‘[[Arise, O Compatriots]]’ ni ó bẹ̀rẹ̀ orin orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]] tí a nń lò lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí.
 
 
309

edits

Ètò ìtọ́sọ́nà