Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Amẹ́ríkà Látìnì"

Jump to navigation Jump to search
280 bytes removed ,  13:12, 13 Oṣù Kẹ̀sán 2017
k
replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
k (Bot: Migrating 109 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q12585 (translate me))
k (replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents)
 
== Ìfáàrà ==
 
“E“Ẹ tókótọ́kọ́ máa wa ìjobaìjọba òsèlú ná
 
Èyí tókù a ó sì fi fún yin
 
ÀpilèkoÀpilẹ̀kọ yìí seṣe àgbéyèwòàgbéyẹ̀wò ìbásepòìbásepọ̀ láàrin Afíríkà (Yorùbá) àti ètò ìsèjobaìsèjọba ni Latin America, àti ní pàtàkì jùlojùlọ bi wonwọn se igbógun tí àwonàwọn ènìyàn Afíríkà nípa kíkópa nínú ìsèjòbaìsèjọ̀ba Latin AmerikaAmẹrika. Nígbà tí Brazil yóò dúró gégégẹ́gẹ́ bii burè fún síse àlàyé ní òrínọ̀rín kinníwín Afro-Brazilian ni a o máa fiwé àwonàwọn ohun tí ó selesẹlẹ ni orílèorílẹ̀-èdè Afro-Latin America nípa ètò ìsèjobaìsèjọba àti ìgbési aye wonwọn ni ayé àtijóàtijọ́ àti ayé òde òní.
 
IséIṣẹ́ yìí yóò yiri bi àwonàwọn ènìyàn ilèilẹ̀ Afíríka tí se àmúlùmálà àsààṣà òlàjúọ̀làjú àti òsèlú ibi ti wonwọn ba ara wonwọn. Ìbéèrè ni pé nǹ jéjẹ́ ìgbé ayé àwonàwọn ènìyàn ilèilẹ̀ AdúláwòAdúláwọ̀ ni orílèorílẹ̀ èdè Latin America dábòbò àsààṣà àti ìse wonwọn láti èyìnẹ̀yìn wà bí? Tàbí ó mú ki àyípadà o de bá àjosepòàjọsepọ̀ wonwọn?
 
Nígbà tí a bá sòròsọ̀rọ̀ nípa Afíríkà ni àsìkò òwò erúẹrú, Yorùbá jéjẹ́ èyàẹ̀yà kan pàtàkì tí àsààṣà àti ìse wonwọn borí to si gbajúmògbajúmọ̀ jú láàrin àwonàwọn èyàẹ̀yà ilèilẹ̀ Afíríká yòókú. Fún àpeereàpẹẹrẹ gbogbo àsààṣà àti ìse Yorùbá bíi èsìnẹ̀sìn, ìbòrisàìbọ̀risà àti ìgbàgbóìgbàgbọ́ wonwọn ni wonwọn mu ni òkúnkúndùnọ̀kúnkúndùn ní òkè òkun níbi tí wónwọ́nwonwọn lolọ gégégẹ́gẹ́ bíi erúẹrú. Èyí kìí se àsodùnàsọdùn rárá pé kàkà ki kìnníùn seṣe akápò EkùnẸkùn, oníkálukú yóò seṣe odeọdẹ tirètirẹ̀ lótòòtòlọ́tọ̀ọ̀tọ̀. Nítorí náà a rí àwonàwọn erúẹrúwónwọ́n gbà pé àwonàwọn yóò maa se àsààṣà àti èsìnẹ̀sìn wonwọn bi àwonàwọn ti nń se nígbà tí wónwọ́n wà ni Afíríkà, àwonàwọn erúẹrú ti wonwọn gbà pé wonwọn kò ní se àsààṣà àti èsìnẹ̀sìn ìlú aláwòaláwọ̀ funfun ni wonwọn pàgópàgọ́ (cadomble) tí Yorùbá si jejẹ asaájú fún àwonàwọn yòókù.
 
Ohun tí a nń sosọ ni pe kàkà ti Yorùbá yóò fi faramófaramọ́ àsààṣà, èsìnẹ̀sìn àti ìse ibi ti wonwọn ba ara wonwọn, èsìnẹ̀sìn àti àsààṣà ti wonwọn ni wonwọn gbe lárugelárugẹ tí ó si gbilègbilẹ̀ débi pe àwonàwọn èyàẹ̀yà Afíríkà mìíràn darapòdarapọ̀ momọ wonwọn ti wonwọn si jojọ nń bobọ àwonàwọn òrìsàòrìṣà bíi ÈlàẸ̀là, Ògún, Sàngó, ObàtáláỌbàtálá, sanponnasanpọnna, ObalufonỌbalufọn àti àwonàwọn irúnmolèirúnmọlẹ̀ yòókù ni òkè okun. Lára àwonàwọn ìlú tí àwonàwọn ènìyàn wa ni: Lati America, Bahia, Guayana, Brazil, Haiti, Alagre, Cuba, Columbia, Trinidad abbl.
Nínú iséiṣẹ́ yìí a o lolọ Afíríkà tàbí àwonàwọn ènìyàn ilèilẹ̀ AdúláwòAdúláwọ̀ dípò Yorùbá fún ìtumòìtumọ̀ lékùnrérélẹ́kùnrẹ́rẹ́ nípa ìgbésí ayé wonwọnorílèorílẹ̀-èdè AmerikaAmẹrika.
 
Afro-American ni àwonàwọn ènìyàn tí wonwọn kó ni erúẹrú ní Afíríkà lolọorílèorílẹ̀-èdè AmerikaAmẹrika (New world) àwonàwọn ni wonwọn n sisesisẹwónwọ́n si nń gbé àárín AmerikaAmẹrika. Afro-Latin America ni àwonàwọn erúẹrú láti ilèilẹ̀ Afíríkà ti wonwọnwonwọn gba Amerika lolọ si Gúsù Amerika (south American) ní àwonàwọn ìlú bíi. Agentina, Mexico, Haiti, Cuba, Brazil abbl.
 
ÌyàtòÌyàtọ̀ tí ó wa láàrin Afro-America àti Afro-Latin America ni pé wonwọn kò gbà àwonàwọn Dúdú (Afíríkà) láàyè láti ni ìbásepò pèlúpẹ̀lú àwonàwọn aláwòaláwọ̀ funfun (oyinbo) ni Afro-America, sùgbónṣùgbọ́n kò sí eléyàẹlẹ́yà-mèyàmẹ̀yà ní Afro-Latin America.
 
Ìsòro mìíràn tí ó tún kojú àwonàwọn ènìyàn Afíríkà ni èdè, ni Afro-America, èdè ìsèjobaìsèjọba wonwọn ni èdè GèésìGẹ̀ẹ́sì (English) sùgbónṣùgbọ́n èyí kò ri béèbẹ́ẹ̀ ní Afro-Latin America, èdè ìsèjobaìsèjọba ni èdè Faransé, Potogi àti Spanish (French, Prtuguese and Spanish). Èyí mú kí ó sòro fún àwonàwọn ènìyàn láti ní ìbásepòìbásepọ̀ tàbí ìfikùnlukùn àyàfi ki wonwọn o ri ògbufòògbufọ̀. Títí di odúnọdún 1970 si 1972 ni Brazil ó jéjẹ́ ìsòro fún àwonàwọn ènìyàn ti o nń seṣe akòròyìnakọ̀ròyìn láti kokọ nnkannǹkan nípa Afíríkà.
 
ÀwonÀwọn ìsòro mìíràn tí ó tún kojú àwonàwọn ènìyàn Afíríka ni Àríwá AmerikaAmẹrika n títa kò àti ìkórira àwonàwọn Dúdú gbogbo ohun ti ko ba ti dara wonwọn gbà pé owoọwọ Afíríkà lo ti wa. WonWọn kò gbà ki àwonàwọn Afíríkà ni asojú nínú ètò òsèlú àti ìjobaìjọba, bákan náà ni wonwọn ko ni ètò òsèlú àti ìjobaìjọba, bákan náà ni wonwọn ko ni ètóẹ̀tọ́ láti dìbò tàbí díje fún ipò kankan. Òfin kò fi ààyè sílèsílẹ̀ fún ànfààníàǹfààní béèbẹ́ẹ̀. Bí ìgbógun tí àwonàwọn AdúláwòAdúláwọ̀ àti ìwà eleyameyaẹlẹyamẹya se níponnípọn tó. SíbèSíbẹ̀, àwonàwọn ènìyàn Afíríkà si ri ara wonwọn gégégẹ́gẹ́èyàẹ̀yà kanna, ibi yòówù ki wonwọn o wa, ìsòro yòówù ki wonwọn o maa la kojakọja.
 
Bi gbogbo ìsòro tí ó n kojú àwonàwọn Afíríkà se pòpọ̀ tó yìí, ipa ti àwonàwọn ti ó wà ni ìpàgóìpàgọ́ kò se fi owóọwọ́ rórọ́ séyìnsẹ́yìn, ni osùoṣù kinni odúnọdún 1976 àwonàwọn egbéẹgbẹ́ tí ó wà ni ìpàgóìpàgọ́ ni Bahia kò gba ìwé àseàsẹ láti òdòọ̀dọ̀ àwonàwọn olópàáọlọ́pàáwonwọn tó se ìpàdé tàbí ìwódeìwọ́de.
 
Bákan náà ni Colombia, ni agbègbè Caribbean (àwonàwọn eruẹru ti wonwọn sa) ni wonwọn pàgópàgọ́ síbèsíbẹ̀, àwonàwọn Palenquenos kò tijú láti fi ara wonwọn hàn gégégẹ́gẹ́ bí Afíríkà nípa ìgbé ayé wonwọn títí di òní.
 
Bákan náà ni a kò le sai menumẹnu ba ipa ribiribi ti Manuel Zapeta Ollivella ti se onísègùn, òpìtàn àti ònkòwéòǹkọ̀wé omoọmọ Afro – Colombian kó, láti ìgbà tí o ti wa ni akékòóakẹ́kọ̀ọ́ ni o ti fi ìféìfẹ́ hàn si ìjàgbara àwonàwọn ènìyàn ilèilẹ̀ Afíríkà lówólọ́wọ́ àwonàwọn amúnisìn. Ní odúnọdún 1950 o kópa nínú ìwódeìwọ́de ìta gbangba tí àwonàwọn akékòóakẹ́kọ̀ọ́ Afro-Colombian University se láti tako ìwà amúnìsìn. OmoỌmọ rèrẹ̀ obìnrin tí ó jéjẹ́ odoọdọ Edeluma náà kokọ ewì lórí àwonàwọn adúláwòadúláwọ̀. Nicomedes Santa Cruz ti o jejẹ omoọmọ Peru ni eniẹni àkókóàkọ́kọ́ ti o kokọ nnkannǹkan nípa ìsòro tí ó nń kojú àwonàwọn ènìyàn adúláwòadúláwọ̀ tí o pe akoleakọ̣le rerẹ ni “congo Libre” tí o fi sorisọri Patrice Lummba. Nínú ìwé tí o kokọ ni o se àfihàn ìbásepòìbásepọ̀ to wà láàrin Afíríkà àti Peru. Ó sosọ nínú ìwé rerẹ ogbónọgbọ́nàwonàwọn alawoalawọ funfun n da láti mu àdínkù ba àwonàwọn Afíríkà àti bi wonwọn ó se. din agbára wonwọn kù, o fi ìwé rerẹ náà tako ìwà eléyàmèyàẹlẹ́yàmẹ̀yà.
 
A o ni kógo jà bí a bá kùnà láti ménubàmẹ́nubà Abdias do Nascimento ti òun náà kokọ ìwé lórí Afro-Latin America, iséiṣẹ́ ònkòwéòǹkọ̀wé yìí ni o gbegba orókè láàrin àwonàwọn ònkòwéòǹkọ̀wé Afro-Brazilian.
 
== ÌgúnlèÌgúnlẹ̀ ==
 
Ni ibèrèibẹ̀rẹ̀ pepepẹpẹ ìbásepòìbásepọ̀ láàrin adúláwòadúláwọ̀ àti funfun dàbí omoọmọ odoọdọ si ogaọga rerẹ (olówó rerẹ) sùgbónṣùgbọ́npépẹ́ kò jìnnà, ìfarakínra nípa ìgbéyàwò , èsìnẹ̀sìn bèrèbẹ̀rẹ̀ sí ní da àwonàwọn méjèèjì papòpapọ̀.
 
ÀsèyìnwáÀsẹ̀yìnwá, àsèyìnbòàsẹ̀yìnbọ̀ ikoluraikọlura àti ifagagbaga àsààṣà bèrèbẹ̀rẹ̀ si ni kò ara wonwọn jojọ wonwọn n dá egbéẹgbẹ́ sílèsílẹ̀ tí a mòmọ̀egbeẹgbẹ ajìjagbara lówólọ́wọ́ amúnisìn. ÀwonÀwọn dudu bèrèbẹ̀rẹ̀ si ni ri ara wonwọn gégégẹ́gẹ́òkanọ̀kan láìwo eyaẹya tàbí ìlú tàbí gbe òsùnwònòsùnwọ̀n le bi iya ti nń jejẹ wonwọn si.
 
Bí ó ti lelẹ jejẹ pé ìjàgbara láti kópa nínú ìsèjobaìsèjọba wáyé, sùgbónṣùgbọ́n kò so èso rere. Ní odúnọdún 1920 àwonàwọn aláwòdúdúaláwọ̀dúdúegbéẹgbẹ́ òsèlú ti wonwọn sílèsílẹ̀ ni orílèorílẹ̀ èdè Brazil urugay àti Cuba. Ní orílèorílẹ̀ èdè Brazil ni a ti dá egbéẹgbẹ́ tí a pè ní Frente Negra Brasilaira (Brazil Front) wonwọn forúkoforúkọ egbéẹgbẹ́ náà sílèsílẹ̀ lódòlọ́dọ̀ àwonàwọn elétò ìdìbò gégégẹ́gẹ́egbéẹgbẹ́ òsèlú, sùgbónṣùgbọ́n ìjákulèìjákulẹ̀ dé báa ìgbésèìgbésẹ̀ yìí látàrí ìfipá gba ìjobaìjọba ológun lówólọ́wọ́ ìjobaìjọba lágbádá tó wáyé. Ní odúnọdún 1937 tí o si fi òfin de egbéẹgbẹ́ òsèlú síse. LéyìnLẹ́yìn èyí egbéẹgbẹ́ náà tún bèrèbẹ̀rẹ̀ ìpàdé wonwọn sùgbónṣùgbọ́n ojú àpá kò jojọ ojú ara nítorí pé ìpàdé yìí kò lówólọ́wọ́ òsèlú nínú bíi ti télètẹ́lẹ̀.
 
Láàrin odúnọdún 1973 – 5 ni àwonàwọn àyípadà díèdíẹ̀ bèrèbẹ̀rẹ̀ sí ní dé bá àwonàwọn adúláwòadúláwọ̀ tí ó wà lábélábẹ́ ìjobaìjọba Brazil. Gbigba ominira orílèorílẹ̀-èdè guinea-Bissau Mozambique àti Angol kò sàì lówólọ́wọ́ ipa ti orílèorílẹ̀ - èdè Brazil kó nínú. Bákan náà ni ipa ti Brazil ko nípa èdè àti àsààṣà Afíríkà kìí se kèrémí. ÒpòỌ̀pọ̀ àwonàwọn èèyàn Angola ni wonwọn nń seṣe àtìpó ní Brazil.
== ÌWÉ ÌTÓKASÍÌTỌ́KASÍ ==
 
Anani Dzidizienyo (African Yoruba) Culture and the Political Kingdom in Latin America. Afro-American Studies Brown University Providence, Rhodeisland
309

edits

Ètò ìtọ́sọ́nà