Ṣàngó: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
No edit summary
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
Ìlà 1: Ìlà 1:
'''Ṣàngó''' Olukoso, Oko Oya.
'''Ṣàngó''' Olukoso, Oko Oya.

Ṣàngó Je Okan lara Awon Orisa ti awon yorùbá n bò wọ́a ni àjànàkú kojá a morí nnkan fìrí, bí a bá rí erin, káwípe a rí erin ní òrò Ṣàngó jé láàárin àwon òrìsà ilee Yorùbá. Ṣàngó jé òrìsà takuntakun kan gbòógì láàárín àwon òrìsà tókù ní ilèe Yorùbá. Ó jé orisà tí ìran rè kún fún ìbèrù. Ìrísí, ìṣe àti ìsọ̀rọ̀ rẹ̀ pàápàá kún fún ìbèrù nígbàtí ó wà laaye nítorípé ènìyàn la gbọ́ pé Ṣàngó jẹ́ télè kí ó tó di òrìṣà àrá. Ìtàn so wí pé omo Òrányàn ni sàngó i ṣe àti pé Oya, Òṣun ati Obà jẹ́ ìyàwó rẹ̀.
Ṣàngó Je Okan lara Awon Orisa ti awon yorùbá n bọ̀ wọ́a ni àjànàkú kọjá a morí nǹkan fìrí, bí a bá rí erin, káwípe a rí erin ní òrọ̀ Ṣàngó jẹ́ láàárin àwon òrìsà ileẹ Yorùbá. Ṣàngó jẹ́ òrìsà takuntakun kan gbòógì láàárín àwon òrìsà tókù ní ilèe Yorùbá. Ó jẹ́ orisà tí ìran rẹ̀ kún fún ìbẹ̀rù. Ìrísí, ìṣe àti ìsọ̀rọ̀ rẹ̀ pàápàá kún fún ìbẹ̀rù nígbàtí ó wà laaye nítorípé ènìyàn la gbọ́ pé Ṣàngó jẹ́ tẹ́lẹ̀ kí ó tó di òrìṣà àrá. Ìtàn sọ wí pé ọmọ Ọ̀rányàn ni ṣàngó i ṣe àti pé Ọya, Ọ̀ṣun ati Ọbà jẹ́ ìyàwó rẹ̀.

Ìhùwàsí búburú ati dídá wàhalá ati ìkolura pèlú ìjayé fàmílétè-kí-n-tutó pò lówó sàngó gégéOba tó bẹ́ẹ̀ títí ó fi di òtéyímiká, èyí jásí wí pé tọmọdé tàgbà dìtè mó o. Wón fi ayé ni í lára. Ó sì fi ìlú Òyó sílè nígbèyìn-gbéyín. Ó pokùnso sí ìdí igi àyàn kan lébà ònà nítòsí Òyó nígbàtí Oya: Ìyàwó rẹ̀ kan tókù náà sì di odò.
Ìhùwàsí búburú ati dídá wàhalá ati ìkọlura pẹ̀lú ìjayé fàmílétè-kí-n-tutọ́ pọ̀ lọ́wọ́ ṣàngó g̣ẹ́gẹ́Ọba tó bẹ́ẹ̀ títí ó fi di ọ̀tẹ́yímiká, èyí jásí wí pé tọmọdé tàgbà dìtẹ̀ mọ́ . Wọ́n fi ayé ni í lára. Ó sì fi ìlú Ọ̀yọ́ sílẹ̀ nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín. Ó pokùnso sí ìdí igi àyàn kan lẹ́bà ọ̀nà nítòsí Ọ̀yọ́ nígbàtí Ọya: Ìyàwó rẹ̀ kan tókù náà sì di odò.

Ogbónàwon ènìyàn sàngó tókù dá láti fi bá àwon òtá rè jà nípa títi iná bolé won àti béèbéè lo ni ó so sàngó di òrìṣà tí wọ́n ń bo títí dòní tí wón sì ńfi enu won túúbá wí pé sàngó kò so: Oba koso.
Ọgbọ́nàwọn ènìyàn ṣàngó tókù dá láti fi bá àwọn ọ̀tá rẹ̀ jà nípa títi iná bọlé wọn àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ ni ó sọ ṣàngó di òrìṣà tí wọ́n ń bọ títí dòní tí wọ́n sì ńfi ẹnu wọn túúbá wí pé ṣàngó kò so: Ọba koso.

ÀWON ORÚKOSÀNGÓ Ń JÉ
ÀWỌN ORÚKỌṢÀNGÓ Ń JẸ́

Oríṣiríṣi orúko ni a mọ sàngó sí nínú èyí tí gbogbo won sì ní ìtumò tàbí ìdí kan pàtó ti a fi ńpè wọ́n béè. Àwon orúko bíi ìwònyìí:
Oríṣiríṣi orúkọ ni a mọ ṣàngó sí nínú èyí tí gbogbo wọn sì ní ìtumọ̀ tàbí ìdí kan pàtó ti a fi ńpè wọ́n bẹ́ẹ̀. Àwọn orúkọ bíi ìwọ̀nyìí:

1. Olúkòso: Ẹnití a mò mọ́ kòso tàbí oba tí ó wolè sí kòso.
1. Olúkòso: Ẹnití a mọ̀ mọ́ kòso tàbí ọba tí ó wọlẹ̀ sí kòso.

2. Arèkújayé:
2. Arẹ̀kújayé:

3. Àjàlájí:
3. Àjàlájí:

4. Ayílègbe Òrun:
4. Ayílègbe Ọ̀run:

5. Olójú Orógbó: nítorípé orógbó ni obì tirè, òun ni ó sì máa ń ṣàféérí nígbà ayé rè. Orógbó náà sì ni a máa ń lo ní ojúbo sàngó títí di òní.
5. Olójú Orógbó: nítorípé orógbó ni obì tirẹ̀, òun ni ó sì máa ń ṣàfẹ́ẹ́rí nígbà ayé rẹ̀. Orógbó náà sì ni a máa ń lo ní ojúbọ ṣàngó títí di òní.

6. Èbìtì-àlàpà-peku-tiyètiyè: Òrìṣà tí ó máa ń fi ìbínú gbígbóná pa ènìyàn ni àpalàyà tàbí àpafòn.
6. Èbìtì-àlàpà-peku-tiyẹ̀tiyẹ̀: Òrìṣà tí ó máa ń fi ìbínú gbígbóná pa ènìyàn ni àpalàyà tàbí àpafòn.

7. Onibon òrun: gégéòrìsà ó ń mú kí àrá sán wá láti ojú òrun pèlú ìrókèkè tó lágbára.
7. Onibon ọ̀run: gẹ́gẹ́òrìṣà ó ń mú kí àrá sán wá láti ojú ọ̀run pẹ̀lú ìrọ́kẹ̀kẹ̀ tó lágbára.

8. Jàkúta: gégé bí òrìṣà tí ń fi òkúta jà (edùn àrá). Irúfẹ́ òkúta kékeré kan tí ó máa sekúpa ènìyàn nípasẹ̀ sàngó
8. Jàkúta: gẹ́gẹ́ bí òrìṣà tí ń fi òkúta jà (ẹdùn àrá). Irúfẹ́ òkúta kékẹrẹ́ kan tí ó máa sekúpa ènìyàn nípasẹ̀ ṣàngó

9. Abotumo-bí-owú: Òrìsà léè wolé pa ènìyàn bi enierù ń lá ni ó wólu irú eni bẹ́ẹ̀.
9. Abọtumọ-bí-owú: Òrìsà léè wọlé pa ènìyàn bi ẹniẹrù ń lá ni ó wólu irú ẹni bẹ́ẹ̀.

10. Èbìtì-káwó-pònyìn-soro: Irúfẹ́ Òrìṣà tí ó jẹ́ wí pé ìṣowó-sekúpa asebi rẹ̀ máa ńya ènìyàn lénu gidigidi.
10. Èbìtì-káwó-pònyìn-soro: Irúfẹ́ Òrìṣà tí ó jẹ́ wí pé ìṣọwọ́-sekúpa asebi rẹ̀ máa ńya ènìyàn lẹ́nu gidigidi.

11. Alágbára-inú-aféfé: Òrìsà tí ó jé wípé owọ́jà a re, máa ńwá láti inú aféfé tàbí òfurufú ni.
11. Alágbára-inú-afẹ́fẹ́: Òrìsà tí ó jẹ́ wípé ọwọ́jà a rẹ, máa ńwá láti inú afẹ́fẹ́ tàbí òfurufú ni.

12. Abánjà-májẹ̀bi: òrìṣà tíí jà láì ṣègbè léyìn aṣebi tàbí ṣe àṣìmú elòmíràn fún oníṣé ibi.
12. Abánjà-májẹ̀bi: òrìṣà tíí jà láì ṣègbè lẹ́yìn aṣebi tàbí ṣe àṣìmú elòmíràn fún oníṣẹ́ ibi.

13. Lánníkú-oko-oya: Òrìsà tí o ni èrù iku níkàwó.
13. Lánníkú-ọkọ-ọya: Òrìsà tí o ni ẹ̀rù iku níkàwọ́.

14. Òkokonkò èbìtì: Òrìsà tí ó le subú lu ènìyàn bii ìgànnán tí ó ti denukọlè.
14. Òkokoǹkò ẹ̀bìtì: Òrìsà tí ó le subú lu ènìyàn bii ìgànnán tí ó ti dẹnukọlẹ̀.

15. Eléèmò: Òrìsà tí ó ni èèmò.
15. Eléèmọ̀: Òrìsà tí ó ni èèmọ̀.

AWON IWE ITOKASI
AWON IWE ITỌKASI

1. Daramola Olu [1967] Awon Asa ati Orisa Ile Yoruba. Lati owo Olu Daramola ati
1. Daramola Olu [1967] Awọn Asa ati Orisa Ilẹ Yoruba. Lati ọwọ Olu Daramola ati
jẹjẹ Adebayọ
jeje Adebayo

2. Adeoye C. L. [1985] Igbagbo ati Esin Yorùbá. Ibadan. Evans Brother. Press
2. Adeoye C. L. [1985] Igbagbọ ati Ẹsin Yorùbá. Ibadan. Evans Brother. Press

Àtúnyẹ̀wò ní 13:55, 13 Oṣù Kẹ̀sán 2017

Ṣàngó Olukoso, Oko Oya.

Ṣàngó Je Okan lara Awon Orisa ti awon yorùbá n bọ̀ wọ́a ni àjànàkú kọjá a morí nǹkan fìrí, bí a bá rí erin, káwípe a rí erin ní òrọ̀ Ṣàngó jẹ́ láàárin àwon òrìsà ileẹ Yorùbá. Ṣàngó jẹ́ òrìsà takuntakun kan gbòógì láàárín àwon òrìsà tókù ní ilèe Yorùbá. Ó jẹ́ orisà tí ìran rẹ̀ kún fún ìbẹ̀rù. Ìrísí, ìṣe àti ìsọ̀rọ̀ rẹ̀ pàápàá kún fún ìbẹ̀rù nígbàtí ó wà laaye nítorípé ènìyàn la gbọ́ pé Ṣàngó jẹ́ tẹ́lẹ̀ kí ó tó di òrìṣà àrá. Ìtàn sọ wí pé ọmọ Ọ̀rányàn ni ṣàngó i ṣe àti pé Ọya, Ọ̀ṣun ati Ọbà jẹ́ ìyàwó rẹ̀.

Ìhùwàsí búburú ati dídá wàhalá ati ìkọlura pẹ̀lú ìjayé fàmílétè-kí-n-tutọ́ pọ̀ lọ́wọ́ ṣàngó g̣ẹ́gẹ́ bí Ọba tó bẹ́ẹ̀ títí ó fi di ọ̀tẹ́yímiká, èyí jásí wí pé tọmọdé tàgbà dìtẹ̀ mọ́ ọ. Wọ́n fi ayé ni í lára. Ó sì fi ìlú Ọ̀yọ́ sílẹ̀ nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín. Ó pokùnso sí ìdí igi àyàn kan lẹ́bà ọ̀nà nítòsí Ọ̀yọ́ nígbàtí Ọya: Ìyàwó rẹ̀ kan tókù náà sì di odò.

Ọgbọ́n tí àwọn ènìyàn ṣàngó tókù dá láti fi bá àwọn ọ̀tá rẹ̀ jà nípa títi iná bọlé wọn àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ ni ó sọ ṣàngó di òrìṣà tí wọ́n ń bọ títí dòní tí wọ́n sì ńfi ẹnu wọn túúbá wí pé ṣàngó kò so: Ọba koso.

ÀWỌN ORÚKỌ TÍ ṢÀNGÓ Ń JẸ́

Oríṣiríṣi orúkọ ni a mọ ṣàngó sí nínú èyí tí gbogbo wọn sì ní ìtumọ̀ tàbí ìdí kan pàtó ti a fi ńpè wọ́n bẹ́ẹ̀. Àwọn orúkọ bíi ìwọ̀nyìí:

1. Olúkòso: Ẹnití a mọ̀ mọ́ kòso tàbí ọba tí ó wọlẹ̀ sí kòso.

2. Arẹ̀kújayé:

3. Àjàlájí:

4. Ayílègbe Ọ̀run:

5. Olójú Orógbó: nítorípé orógbó ni obì tirẹ̀, òun ni ó sì máa ń ṣàfẹ́ẹ́rí nígbà ayé rẹ̀. Orógbó náà sì ni a máa ń lo ní ojúbọ ṣàngó títí di òní.

6. Èbìtì-àlàpà-peku-tiyẹ̀tiyẹ̀: Òrìṣà tí ó máa ń fi ìbínú gbígbóná pa ènìyàn ni àpalàyà tàbí àpafòn.

7. Onibon ọ̀run: gẹ́gẹ́ bí òrìṣà ó ń mú kí àrá sán wá láti ojú ọ̀run pẹ̀lú ìrọ́kẹ̀kẹ̀ tó lágbára.

8. Jàkúta: gẹ́gẹ́ bí òrìṣà tí ń fi òkúta jà (ẹdùn àrá). Irúfẹ́ òkúta kékẹrẹ́ kan tí ó máa sekúpa ènìyàn nípasẹ̀ ṣàngó

9. Abọtumọ-bí-owú: Òrìsà léè wọlé pa ènìyàn bi ẹni pé ẹrù ń lá ni ó wólu irú ẹni bẹ́ẹ̀.

10. Èbìtì-káwó-pònyìn-soro: Irúfẹ́ Òrìṣà tí ó jẹ́ wí pé ìṣọwọ́-sekúpa asebi rẹ̀ máa ńya ènìyàn lẹ́nu gidigidi.

11. Alágbára-inú-afẹ́fẹ́: Òrìsà tí ó jẹ́ wípé ọwọ́jà a rẹ, máa ńwá láti inú afẹ́fẹ́ tàbí òfurufú ni.

12. Abánjà-májẹ̀bi: òrìṣà tíí jà láì ṣègbè lẹ́yìn aṣebi tàbí ṣe àṣìmú elòmíràn fún oníṣẹ́ ibi.

13. Lánníkú-ọkọ-ọya: Òrìsà tí o ni ẹ̀rù iku níkàwọ́.

14. Òkokoǹkò ẹ̀bìtì: Òrìsà tí ó le subú lu ènìyàn bii ìgànnán tí ó ti dẹnukọlẹ̀.

15. Eléèmọ̀: Òrìsà tí ó ni èèmọ̀.

AWON IWE ITỌKASI

1. Daramola Olu [1967] Awọn Asa ati Orisa Ilẹ Yoruba. Lati ọwọ Olu Daramola ati jẹjẹ Adebayọ

2. Adeoye C. L. [1985] Igbagbọ ati Ẹsin Yorùbá. Ibadan. Evans Brother. Press